YO/Prabhupada 0415 - Within Six Months You'll Become God - Very Foolish Conclusion



Lecture & Initiation -- Seattle, October 20, 1968

iye odun wa ninu aye yi ko lasiko. L'eyikeyi asiko ale ku. Sugbon fun nkan gidi laye yi wa fun. Kino yen je? Lati se waadi to daju si awon isoro aye wa. fun igba t'awa ba wa ninu ara eda yi, agbodo tun ara imi gba, nkan sikeji. Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi (BG 13.9). Ibimo ati iku kan sikeji. T'ayeraye l'emi wa, sugbon ara eda orisirisi lon wo, gege bi aso. Sugbon awon eyan o foju si isoro tani yi, sugbon isoro loje fun wa. Lati wa ona abayo s isoro aye yi ni igbese aye yi wa fun, sugbon awon eyan o logbon , won a sife mu eto na ni pataki. Teyin ba ni igbese aye to gun, aye wa pe e le ba enikan, enikan pelu iwa to daa, lati lejeke wa ona abayo si awon isoro aye yi. sugbon kose se mo, nitoripe igbese aye wa o gun to. Prāyeṇa alpāyuṣaḥ sabhya kalāv asmin yuge janāḥ mandāḥ (SB 1.1.10). awa o si fe lo igbese aye kekere tanni dada. Awa sin gbe aye wa bi awon eranko, ka jeun, ka sun, ka se imo ako ati abo, ka gbeja ara wa. Otan. Lasiko tawa yi, teyan ba le jeun ki inu re kun, a rowipe, " Ise mi ti tan leni." Teyan ba le toju iyawo re pel'ommo meji tabi meta, eyan pataki loje si awon eyan. On toju ebi re. nitoripe opolop awon eyan l'ebi, kosi ise pataki kankan ton se. Awon aami asiko tawa yi leleyi. beena botilejepe igbese aye wa o gun, sugbon awa o fe mu aye yi ni pataki. Mandāḥ, k'ama lo diedie. beena nibi, awa tin se iwaasu nipa egbe imoye Krsna yi. Koseni tofe ko nipa egbe wa yi. Awon eyan ton fe, won fe kon yan wa je. awonn fe nkan ti o wan, tabi nkan to rorun fun eto imora-eni. Wonn lowo sugbon won fe fun eni, toma sofun wa wipe " Ma fun yin ni mantra tema lo fun iseju meedogun, lehin osu mefa ele d'Olorun na," iru nkan bayi lon fe. Mandhah manda-matayo. Ipari iranu nitumo Manda-matayo. Koye won bawo lesele fe ri " Ona abayo si awon isoro aye yi, teba san dollar marundinlogoji?" Won ti ya didirin. Nitoripe t'awa ba sowipe teyin bafe ni ona abayo si awon isoro aye yi egbodo tele awon ofn wanyi, "Oh, o ti le ju. E je kin san dollar marundinlogogji, ke tunse, e wa ona abayo>" Se ri bayi? Wanfe ki awon eyan yan wa je. Nitorina lon se pe won ni manda-matayo. awon omo-odaran asi wa lati tanwan je. Mandāḥ sumanda-matayo manda-bhāgyā (SB 1.1.10). itumo Manda-bhāgyā niwipe alaisorire ni won. Olorun fun ara re gan wa lati sewaasu funwa, " E dakun a wa simi, sugbon ko da won loju. Se ri bayi. Nkan alaisorire loje. Teyan ba wa fun yin ni dollar millionu, teyin ba sowipe, " Mio fe," se oriburuku koni yen je? Beena Caitanya Mahāprabhu sowipe

harer nāma harer nāma harer nāma eva kevalam
kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva gatir anyathā
(CC Adi 17.21)

"Fun imora eni e korin Hare Krsna eyin na ma ri ibajade to wa nibe." Rara. Won o ni gba. Alaini orirre ni wan. Teyin ban se waasu fun ona to rorunn bayi, sugbon awon eyan yi o fe, wan fe kon tan wan je... Se ri? Mandāḥ sumanda-matayo manda-bhāgyā hy upadrutāḥ (SB 1.1.10). Wan si feran isoro lati orisirisi nkan - ere tete, ati awon nkan orisirisi. Ipo aye won niyen. Igbese aye to kere, aiyara, won o si ni imoye, ton ba sife ni oye, wan fe kon tan wan je, alailorirre ni won, ipo t'aye isin leleyi. Kosiyato pe won be yin si orile-ede America tabi India, ipo gbogbo wa niyenn.