YO/Prabhupada 0419 - Initiation Means the Third Stage of Krishna Consciousness



Lecture & Initiation -- Seattle, October 20, 1968

Beena ipo keta nitumo itebomi mimo yi ninu imoye Krsna. Awon ton ti gba itebomi mimo yi won gbodo ranti pe wan ni lati teleawon ofin wa. gege b'eyan to bafe ki aisan re tan, ogbodo tele awon aimase ti ologun ba sofun, pelu iranlowo yi ole jaded kuro ninu aisan na kiakia. Beena won gbodo tele awon ofin merin wanyi, kon korin fun igba merin dinlogun lojojumo, diedie loma gunke ninu igbagbo toni, asi ni ifarasi ati itowo fun, lehin na ife fun Krsna ma jade lesekese.. O wa ninu okan gbogbo wa. Ife fun Krsna, kon se nkan ajeji lawa fe daale. Rara. O wa nibikibi, ninu gbogbo eda. Bibeko kilode ti awon omo okurin at'obirin America tgba sokan tio ba si ninu won? O wa nibe. Mo kan ran won lowo. gege bi isana: Ina wa, tawa ba ranlowo tafi pa ara apo isana, otan. Ina ma jade. Teyin ba fi igi maeji lasan fi pa ara won , ina o ni jade, tio ba si kemika to wa lori igi isana. Beena imoye Krsna wa ninu okan gbogbo eyan; Agbodo jisoke pelu asepo yi, asepo pelu imoye Krsna. Beena ko lee, kon se nkan teyin o le se, koni ibanuje kankan. Gbogbo nkan si da. Beena ibeere wa ni wipe kon gba ebun Oluwa Caitanya yi, Egbe imoye Krsna yi, ati orin kiko Hare Krsna, inu yin ma dun si. Ise wa niyen.

Ese pupo.