YO/Prabhupada 0428 - The Special Prerogative of the Human Being is to Understand - What I Am



Lecture on BG 2.11 -- Edinburgh, July 16, 1972

Oye ke gbiyanju lati ri bi awa se je awon alaimokan. Gbogbo wa la ni aimokan yi. Eto ekoo yi se pataki nitoripe awon eyan o mo nkankan won sin ja pelu ara won. Orile-ede kan gbogun ti imi, esin kan gbogun ti'keji. Sugbon nitori aimokan ni gbogbo e sen sele. Ara mi ko nimo je. Nitorina sastra sowipe, yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke (SB 10.84.13). Ātma-buddhiḥ kuṇape, apo egungun ati era leleyi je, lati awon dhatus meta lon ti wa. Awon oun elo aye yi nitumon Dhatu. gege bi awon ilana Āyur-veda se so: kapha, pitta, vāyu. Awon nkan aye yi. Beena nitorina emi nimo je. Nkankana nimo je pelu Olorun. Ahaṁ brahmāsmi. Ikeeko Veda leleyi je. Egbiyanju lati mo wipe eyin o ni kankan se pelu ile aye yi. Odo metalokan loye ke wa. Nkankana leje pelu Olorun. Mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7). Ninu Bhagavad-gītā, Olorun sowipe " Gbogbo awon eda je nkankana pelu mi." Manaḥ ṣaṣṭhānīndriyāṇi prakṛti-sthāni karṣati (BG 15.7). Awon eda sin gbiyanju latile gbe ninu aye yi, pelu ironu wipe ara re loje, Sugbon iru ironu bayi je ironu awon eranko. Nitoripe awon eranko sin jeun, won sun, won se imo ako ati abo, won sin gbeja ara won. Beena ti awa na bi eda eyan , se gbogbo awon ise wanyi, jijeun, sisun, imo ako ati abo, ati igbeja ara wa, awa o da ju awon ernako wanyi lo. Nkan tose pataki nipa eda eyan niwipe o le ni oye nipa " tani mo je? Se ara mi nimoje tabi nkan imi? Niotooro, ara mi ko nimo je. Moti fun yin ni apeere to po. Emi nimi. Sugbon lasiko tawayi gbogbo wa lan sise lati mo wipe ara mi nimoje. Koseni ton sise lati mowipe emi mimo nimi. Nitorina egbiyanju lati ni oye nipa egbe imoye Krsna yi. Afe ko gbogbo awon eda eyan laise isasoto kankan. nitoripe awa o gbokan le ara awon eda. Ara eda na leje ara Hindu, tabi Musluman, tabi Olugbe Eurupu, tabi olugbe America, tabi ara na le yato si tawa. gege bi eyin se wo aso to yato. Nisin, nitoripe mo wo aso pupa ati wipe eyin wo aso dudu, se iyen wa sowipe oye ke ja. Kilode? Eyin le wo aso to yato, mole wo aso to yato. Kinidi fun ija na? Oye tafe ki awon eyan ni nisin leleyi. Bibeko, eyin o daju awujo awon eranko. Gege bi aginju awon eranko wan'be. Awon ologbo, aja, owawa, ekun, gbogbo won lon ja. Nitorina t'awa bafe santi - Alafia nitumo santi - beena agbodo gbiyanju alti mo " Tani mi." Egbe imoye Krsna wa leleyi. Afe ko awon eyan lati mo eni ton je. Sugbon ipo onikaluku.. ipo gbogbo wa, temi nikan ko. Ti gbogbo eyan. Awon eranko na, Emi na ni gbogbo won. Kṛṣṇa salaaye wipe,

sarva-yoniṣu kaunteya
mūrtayaḥ sambhavanti yāḥ
tāsāṁ brahma mahad yonir
ahaṁ bīja-pradaḥ pitā
(BG 14.4)

Krsna p'ase wipe " Emi ni baba gbogbo awon eda." Niotooro, koko oro leleyi. tabafe mo nipa orisun iseda, wanti salaaye gbogbo e ninu Bhagavada-gita. gege bi baba omo lon fi orugbin ninu oyn iya, orugbin na asi dagba si ara to ye, Beena, eda ni gbogbo, nkankana pelu Olorun, beena Olorun lo fun iseda yi l'oyn pelu gbogbo awon eda ninu e, ati jade ninu iseda na pelu orisirisi ara to yato. Awon ara pe 8,400,000. Jalajā nava-lakṣāṇi sthāvarā lakṣa-viṁśati. Atojo gbogbo awon eda na wa. Gbogbo e lowa.