YO/Prabhupada 0430 - Caitanya Mahaprabhu Says That Each and Every Name of God is as Powerful as God



Lecture on BG 2.11 -- Edinburgh, July 16, 1972

nāmnām akāri bahudhā nija-sarva-śaktis
tatrārpitā niyamitaḥ smaraṇe na kālaḥ
etādṛśī tava kṛpā bhagavan mamāpi
durdaivam īdṛśam ihājani nānurāgaḥ
(CC Antya 20.16)

Caitanya Mahāprabhu sowipe awon oruko Olorun ni agbara kanna pel'Olorun. Nitoripe Olorun je pipe, kosi'yato kankan laarin oruko re, ara re, awon akoko idaraya re. Kosin nkan to yato s'Olorun. Imoye to gaju leleyi. Advaya-jñāna. Beena teba korin oruko Olorun, itume re niwipe eyin wa pel'Olorun niyen Nitoripe oruko Olorun o yato si. Egbiyanju lati ni oye na. Beena, teba fowokan ina, o ma jo yin. Teba mo tabi teyin o ba ko, iru ina toje, asi jo yin lowo. Teba fowokan ina a jo yin lowo. Beena, teba korin oruko Olorun a sise. Apeere to wa niwipe , teba fi irin sinu ina, abere sini gbona die die, lehin igba die a gbona gan. pelu asepo toni pelu ina, irin na ma daabi ina. Sugbon ina ko ni irin yi je. Sugbon nitori asepo to ni pelu ina, oun na ti'dina, beena toba ti gbona gan, teba fowokan, irin na ma jo yin lowo. Beena, teba ni asepo pel'Olorun, diedie eyin na ma ni awon iwa mimo. Eyin o le d'Olorun,, sugbon ema ni awon iwa bi tie. lesekese teyin ba yasi mimo, gbogbo awon iwa mimo yi ma jade. Sayensi leleyi. E gbiyanju lati mo. Nkankana laje pel'Olorun, gbogbo awon eda. Ele sewaadi nipa Olorun, tal'Olorun je, teba sewaadi fun ara yin. Nitoripe moje nkankana pelu , fun apeere teba mu apo iresi te yo iresi die kuro, ele ri, ele mo nipa iru iresi wo lowa ninu apo na. beena, alagbara l'Olorun je, o daa be. Subon tawa ba sewaadi si eni taje, ale monipa eni t'Olorun je. Gege bi iwonba omi kekere lati omi okun. Teyin ba mo iru awon kemika wo lon wa ninu e, ele mo nipa awon kemika towa ninu omi okun. Nkan tonpe ni sasaro niyen, lati mo nipa ara eni, " Tani mi?" Teyan ba sewaadi lati mo eni toje, lehin na lole mo eni t'Olorun je. Nisin fun apeere, " Tani mi?" Teyin ba sasaro lori ara yin, ele mo nipa eni teyin je pe eyan leje fun ara yin. Eyan funa ra yin, itumo re niwipe eyin ni okan tiyin. Ele ronu fun ara yin. Nitorina igbami ale ni awon idamu die. Nitoripe eda funa ra wa laje. nitoripe awa je awon eda, toje nkankan pel'olorun, eda fun ara re l'Olorun. Iwaadi to wa niyen. Gege bi mosej'eyan, eyan na l'Olorun je. Kosi b'Olorun o le ma seyan. tawa ba mu Olorun bi baba wa talakoko... Awon onigbagbo nigbagbo na. Gbogo awon esin iyoku na ni gbagbo, awa na ni gbagbo, Bhagavad-gita. Nitoripe Krsna sowipe, ahaṁ bīja-pradaḥ pitā (BG 14.4), " Emi ni baba t'alakoko gbogbo eda." Beena t'Olorun ba je baba gbogbo awon eda, ati wipe gbogbo awon eda si je eda ototo si ara won, bawo lose jewipe Olorun o kin seyan? Eyan l'Olorun je. Nkan tonpe ni imoye niyen. Ogbon.

Nisin, nibi, ninu aye yi, ati jerisi pe awa fe nife fun eni ta feran Enikeni. Beena pelu awon erank, kiniun na feran awon omo re. Ife na wan'be. Prema, nkan ton pe ni prema niyen. Beena nitorina eto ife yi wa pel'Olorun. Taba si ni asepo pel'Olorun gbogbo nkan taba se ma wa lori ife. Mo nife Krsna tabi Olorun, ati Krsna na si nife mi. Safiropo ife wa leleyi. Beena ele ni oye eto yi lai ka awon iwe Veda - sugbon teyin ba sewaadu nipa eni t'Olorun je, ele ni oye nipa Olorun. Nitoripe apeere Olorun nimi, nkankan pelu re. Gege bi wure kekere. Omi die lat'omi okun na ni iyo. Omi okun na ni iyo, soye yin bayi. Beena, taba sewaadi lori eni taje, ale mo nipa eni t'Olorun je. Apa kan leleyi. Nibi Olorun ti farare han, Krsna. O sowipe "Yadā yadā hi dharmas... (Isinmi) ...lati pa awon esu, Nitorina lo sen farahan." Sugobn ranti pe, pipe l'Orlorun je. Pipa awon esu tabi ibukun fun awon olufokansi, nkankanna loje. Nitoripe lati awon iwe mimo Veda wanti salaaye wipe awon esu t'Olorun ba fiku pa, gbogbo won lonma ni'gbala. Nitoripe Olorun fu ara re lo pa won, Olorun ti fowokan. beena sayensi pataki loje. Konse nkan afori ro. Lori imoye Veda loti jade. Beena ibeere wa niwipe ke mu egbe yi ni pataki inu yin a si dun.