YO/Prabhupada 0434 - Don't Hear the Cheaters and Don't Try to Cheat Others



Morning Walk -- May 10, 1975, Perth

Prabhupada: Awon didinrin at'ode nitumo aye isin. Awa ogbodo tele awon ode ati didinrin wanyi. E gbodo tele eni toje pipe, Krsna.

Paramahamsa: Isoro towa niwipe gbogbo awon lon fe yan won je. Gbogbo eyan nisin lon salaaye nipa impye to ni....

Prabhupada: Nitorina lase gba Krsna tio le tan wa je. O feran lati tan awon eyan je nitorina losen fetisi awon oniro wanyi. Awa o kin tan awon eyan je, asi fe awon eyan tio ni tan enikeni je. Iyato laarin emi ati'wo niyen.

Ganesa: Sugbon gbogbo nibi lan tan awon eyan je ka'to pade re, Srila Prabhupada. Gbogbo wa lan tan awon eyan je, beena bawo loseje wipe eni tagba kole tan wa je? Bawo lose jewipe awon taje oniro, bawo lase gba imoye yi lowo yin?

Prabhupada: Beeni, nitoripe awa n'salaaye on ti Krsna ti so. Onitanje kole je. Olorun loje. Imoye temi ko nimon salaaye fun yin. Nkan ti Krsna so nimo n'salaaye fun yin. Otan. Nitorina mio kin se eni tole tan yin je. Mole je eni tole tanyin je, sugbon latigba timo bere sini salaaye nipa Krsna, mio kin se iru eyan bayi mo. (Isinmi to gun) Krsna sowipe, vedaham samatitani (BG 7.26), " Mo mo nipa oun ti tele, tisin ati t'ojowaju." Nitorina ko kin se eni tole tan wa je. Sugobn awa o mo nkan to sele tele tabi nkan to ma sele lojowaju. Awa o tie mo nkna ton sele nisin gan dada. taba si soro, lati tan awon eyan je nikan. Itanje leleyi. (Isinmi to gun) Ninu egbe imoye Krsna wa yi awa o kin feti si awon eyan bayi awa ode ni tan awo eyan je. E sooto ke gbo lati awon olori. Krsna niyen. (Isinmi to gun)

Amogha: Srila Prabhupada? Kilode toje pe awon eyan kan, tonba gbo nipa imoye Krsna wansi gba, sugon awon imi o nife gba. ati na, awon ton si gba, imi ninu won ma wa, imi ninu won ma kuro?

Prahupada: Awon ton sorire ati awon alailorire. Gege bi awon ton ri ohun baba won gba lehin igbato ku. Owo repete, sugbon lehin igba die o di talaka nitoripe oti lo owo na nilokulo. bayi loseje. Alaisorire loje. O ri owo gba, sugobn kole lo dada.

jayadharma: Se oreofe Krsna nitumo ojowaju?

Prabhupada: Oreofe Krsna wa nigbogbo gba. Ilokulo aaye teni loje. Wanti fun yin laaye - orire towa niyen. Sugbon eyin o fe gba ola yi. Alaisorire tiyin niyen. Wanti salaaye ninu Caitanya-caritamrta. Oluwa Caitanya sowipe, ei rupe brahmanda bhramite kona bhagyavan jiva (CC Madhya 19.151). Kono - awon eyan ton sorire lee gba. Nitoripe alaisorire lopolopo ninu won je. Seri ninu gbogbo Europu ati America awa seto ise yi. Awon akeko melo lonti wa? Iwonba kekere, sugbon wanti wa na. Won sorire gan.