YO/Prabhupada 0436 - Cheerful in all Cases and Interested Simply in Krishna Consciousness



Lecture on BG 2.8-12 -- Los Angeles, November 27, 1968

Olufokansin: ese iwe 11, Olorun to dara sowipe: On soro bi alakowe sugbon on sukun fun nkan tio ye ko sukun fun. awon to logbon o kin sukun fun awon eyan to wa laaye tab awon ton ti ku (BG 2.11)." Ijabo: Olorun si d'Oluko osi kilo fun akeko re, pe ode loje. Olorun sowipe, " On soro bi alakowe, sugbon iwo o m'eyan toje alakowe, eni tomo nkan t'ara at'emi yi je, ko kin sukun fun ounkoun toba sele s'ara yi, boya to wa laaye tabi toti ku. Base salaaye ninu awon apa iwe to koja seyin, itumo imoye ni iyato laarin ohun aye yi at'emi, ati oloru awon mejeji. Arjuna si jiyan pe awon ofin esin gbodo ni idari lori eto iselu ati eto awujo eda, sugbon ko monipa imoye oun aye yi, emi ati Olorun pe won se pataki ju gbogbo awon ofin esin. ati nitoripe ko monipa imoye yi, koye se bewipe alakowe loje. Nitoripe kofibe mo nkan, osin sukun fun nkan tio ye ko sukun. Ara wa ti ni ibimo sugbon o le paari leni tab'ola. Nitorina emi wa se pataki ju ara yi lo. Eni to mo nipa eto yi loje alakowe to daju. Fun iru eyan bayi kosejo pe on sukun fun ounkoun nipa ara eda."

Prabhupada: Krsna sowipe, " Ara eda yi, boya o wa laye tabi toti ku awa o gbodo sukun fun." Kasowipe ara eda na ti ku, ko wulo mo. Kiniiwulo pe an sunkun? Ele sukun fun aimoye odun, kole ni iyi kankan mo. Beena kosejo awa n'sukn lori ara eda. nipa awon emi, won wa fun tayeraye. Toba tir jewipe won ti ku, tabi o ku pel'ara na, kole ku. Beena kilode teyin sen sunkun "Oh, baba mi ti ku, eyan bayi bayi toje ebi mi ti ku," ten sukun? Kio yti ku. Imoye toye ka ni leleyi. Lehin na inu re ma dun nigbogbo igba asi f'okan si imoye Krsna. Kosi nkan toye ka sukn fun ninu aye yi. Krsna ti salaaye ninu ese iwe yi. Tesiwaju.

Olufokansi: " Kosigbati emi, tabi iwo ati awon oba wanyi, t'awa o si laaye kode nisi igba t'awa o ni wa laaye mo (BG 2.12)". Iye: Ninu awon Veda, ninu Katha Upanusad, gege bi Svetasvatara Upanisad, wan sowipe...."

Prabhupada: ( satunse si bon se daruko) Svetasvatara. Awon Upanisads po gan, won pe wan ni Veda. Upanisad je àkọlé awon Veda. gege bi àkọlé se wa lori apa iwe, beena awon Upanisads wanyi daabi àkọlé Veda. orisirisi Upanisads tope 108, lowa, nipataki. ninu gbogbo won mesan lose pataki ju. Ninu awon Upaniṣads mesan wanyi, Śvetāśvatara Upaniṣad, Taittireya Upaniṣad, Aitareya Upaniṣad, Īśopaniṣad, Īśa Upaniṣad, Muṇḍaka Upaniṣad, Māṇḍūkya Upaniṣad, Kaṭhopaniṣad, Awon Upanisad wanyi lose pataki ju. Ti idamu kankan bawa lori eto kan, Eyan gbodo fi awon Upanisads fi jerisi