YO/Prabhupada 0441 - Krishna is the Supreme, and We Are Fragmental Parts



Lecture on BG 2.8-12 -- Los Angeles, November 27, 1968

Olufokansi: " Eledumare, eyan loje, ati Arjun na, awon alabasepo t'Olorun ati awon oba ton wa nibe eyan ototo lonje. konsepe awon eyan yi o si laaye teletele, konsepe wan o ni si laaye tayeraye. Bosej'eyan teletele beena lonse ma wa lojoowaju. Nitorina kosejo fun ibanuje fu eni kankan. Awon Mayavadia tabi imoye awon eyna ton sowipe leyin igba t'emi wa ba pada s'odo metalokan, pe ama wole sinu ara Brahman lai ni isasoto kankan..."

Prabhupada: Nisin, Awon Mayavadi sowipe maya ni isasoto yi. Beena wan rowipe ikan soso ni gbogbo emi aye yi je. Imoye ton ni niwipe ghaṭākāśa poṭākāśa. Ghaṭākāśa poṭākāśa itumo re niwpe... gege bi sanma. Ofurufu ni sanma je. Ninu koko kekere, ton pade... Nisin, ninu koko na, sanma kekere kan wa. lesekese teba fo koko na, sanma nla to wa nita, ati sanma kekere to a ninu ma paapo. Imoye Mayavada leleyi. Sugbon awa o le lo iru ogbon bayi. Ogbon wanyi ko dogba. Ofin ogbon ori leleyi. Kosi basele fi sanma fi we... Awa o le fi sanma kekere to wa ninu koko fiwe awon eda laye yi. Nkan lasan ni sanma yi je, emi ni awon eda yi. Bawo lesele so be? Gege bi kokoro , emi pel'aye na loje. Osi wa fun ara re. Sugbon, okuta nla, tabi ori-oke tabi'ipata, kole jeyan. Awon nkan lasan o kin seyan. Sugbon awon eda pel'emi wonle jeyan. Beena ti awon eto wanyi yato si ara won, kosi besele fi we ara won. Ofin ogbonn ori leleyi. Beena kosi besele lo nkan aye pelu nkan to l'emi. Nitorina ni ogbon yi o se daju. Ghaṭākāśa poṭākāśa. Ijerisi imi tun wa ninu Bhagavad-gita. Krsna sowipe mamaivāṁśo jīva-bhūta (BG 15.7). " Awon eda ototo wanyi, nkankan lonje pelu mi." Jīva-loke sanātanaḥ. wan si wa tayeraye. Itumo re niwipe won wa pelu re tayeraye. lehin na.. Bawo lesefe jerisi imoye awon Mayavadi wanyi pe nitori maya, nitoripe maya ti bo won, nitorina lonse huwa bi awon eda to yato , sugbon ti idaabo maya yi ban tan leyin na won ma paapo gege bi sanma kekere ati sanma nla? Beena ironu yi o dogba teba f'ogbon wo daada, teba si fi awon iwe mimo Veda fi wo. Eda otooto lonje. Awon ijerisi to po gan si wa lati Bhagavad-gita. Bhagavad-gita sowipe kosi basele pin emi awon eda wanyi si kekere. Beena teyin ba sowipe nitoripe awon emi yi ni idaabo, nitorina lon se wa ni wewe, kolese se. Kosi besele ge. fun apeere teba ge iwe si wewe, nkan telese niyen nitoripe, nkan lasan niyen. Tayeraye awon eda wanyi wa lotooto, Eledumare na si wa fun ara re. Krsna ni Eledumare na, apa wewe ni gbo gbo wa si je. Wanti salaaye awon kan wanyi ninu Bhagavad-gita dada. Ibeere mi si gbogbo yin nipe e toju iwe Bhagavad-gita kan , gbogbo yin, kesi ka dada. Asi ma se idanwo losu kè̩sán . Beena.. kon se dandan, teba fe naani. Sugbon mosi fe ke mura fun idanwo yi na losu kesan. Eni keni toba se aseyori ma gba oruko Bhakti-sastri. See ti pin... Beeni. tesiwaju.

Olufokansi: " Beena ironu pe eda ototo laje nitoripe aw aninu aye yi ko si daju na. Krsna ti slaaye wipe lojowaju gbogbo awon eda pelu Olorun fun ara re ma wa bon se wa..."

Prabhupada: Krsna o sowippe lehin igba ti awon eda wanyi ba nigbala gbogbo won lonma paapo pel'Olorun. Krsna o osobe ninu Bhagavad-gita.