YO/Prabhupada 0442 - In Christian Theology, one Prays to God, 'Give us our Daily Bread'



Lecture on BG 2.8-12 -- Los Angeles, November 27, 1968

Olufokansi: " Krsna ti salaaye wipe lojowaju gbogbo wa ma laaye, gege bi awon Upanisads se jerisi, ama wa tayeraye. Ase ni awon oro Krsna wanyi."

Prabhupada: Beeni, Upanisada sowipe nityo nityanam. Nisin, itumo nitya ni tayeraye, Olorun si wa tayeraye, gbogbo awon eda na, awa tayeraye. Oun ni olori wa. Eko bahunam... Bawo lose jep oun ni olori wa? Eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Oun leni kan soso ton peese fun gbogbo awon oun ini gbogbo wa. Awon nkan wanyi on ti salaaye ninu Veeda. Awa na ti jerisi. Gege bi awon onigbagbo ton losi ile-adura lati s'aadura s'Olorun, " E funwa l'ounje wa lojojumo." Kilode ton sen bere lowo Olorun? Sugbon nisin awon alainigbagbo tin sofun, " Nibo l'ounje na wa? Eyin losi ile adura wanyi. E wa s'odo wa; ama fun yin l'ounje." Beena ironu Veda si wa nbe. Aown Veda sowipe, eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Olorun gbogbo agbaye yi lon peese gbogbo awon eda. Bibeli na ti salaaye pe " E beere fun onje yin lowo Olorun." Beena afi t'Olorun baje oluso wa ati eni ton peese funwa, kilode t'oro yi se wa n'be? Nitoripe oun loje olori ibe. Oun ni oluso wa. Awon Veda ti salaaye ipo Olorun yi. Oun lo gaju. T'oro yo ba yewa ama ni alafiaa. Imoye Veda niyen. Tesiwaju.

Olufokansin: " Oro Krsna yi daju nitoripe kosi bi Krsna sefe sirorun.

Prabhupada: Beeni. Ti awon Mayavadi ba sowipe oro Krsna yi wa ninu maya, Beena nkan ton so niwipe gbogbo awon eda wanyi wa ninu maya teletele.' Rara, teletele ikan soso nigbogbo wa je sugbon pelu asepo maya ni gbogbo wa se yasoto." Ti awon Mayavadi ba so bayi, beena Krsna ti di ikan ninu awon eda lasan. Kosi bosele je Olori mo. Nitoripe awon eda aye yi o kosi bonsele fun yin looto oro. Eda lasan nimi. Mio le so nkan to wa ni pipe. Sugbon pipe ni Krsna je. beena t'awa ba gba imoye awon Mayavadi, lehin agbodo ti imoye Krsna segbe kan. T'aba ti Krsna segbe kan.lehin kinidi lati ka awon iwe Krsna tabi Bhagavad-gita. Ilokulo asiko wa loje. Tobaje eda bi iru tawayi... nitoripe awa o le gba itosona kankan lati awon eda lasan. Beena oluko wa, teyin ba tie rowipe eda lasan loje, sugbon ko so nkankan latenu ara re. Awon oro Krsna lon so. Beena afi.. Afi teyan bati ni idari lori awon ipo aye yi, kosi bosele funwa ni imoye to daju. Awon eda lasan, botilejee alakowe loje, kosi bosele funwa l'ogbon to daju. Afi awon eya ton ti koja awon ofin ile ayi yi, O le fun wa l'ogbon to daju. beena Śaṅkarācārya, toje alainigbagbo si gba pe Krsna ni eda pelu idari to gaju. Sa bhagavān svayaṁ kṛṣṇa. "Kṛṣṇa ni Eledumare." Awon alakowe Mayavadi, wan o kin so awon oro Sankaracarya. lati tan awon eyan je. Sugbon oro Sankaracarya si wa nbe. A le jerisi. O gba pe Krsna ni olori to gaju. O ti ko awon ewi ton s'adura si Krsna. Eyi to keyin o sowipe, bhaja govindaṁ bhaja govindaṁ bhaja govindaṁ mūḍha-mate. " Eyin didirin. Oh eyin sin gbekele awon oro lasan lati ni oye na." "Iranu ni gbogbo eleyo." Bhaja govindam. " E s'adura si Govinda." Bhaja govindaṁ bhaja.... O so lee meta. " E gbadura si Govinda." Bhaja govindaṁ bhaja govindaṁ bhaja govindam. gege bi Caitanya Mahāprabhu se so fun igba meta, harer nāma harer nāma harer nāma (CC Adi 17.21). Lee meta, lati jeki awon eyan mope o se pataki. Gege bi awa na sen so nigbami, " se bayi, se bayi, se bayi." Itumi re niwipe, ogbodo se. Beena lesekese teyan ba so nkan fun igba meta, itumo re niwipe otan. Beena Śaṅkarācārya sowipe, bhaja govindaṁ bhaja govindaṁ bhaja govindaṁ mūḍha-mate. Mūḍha, mūḍha Moti salaaye aimoye igba pe ketekete tabi asiwere nitumo Mūḍha. Eyin sin gbekele imoye yin, dukṛn karaṇe. Dukṛn, awon ìmö ìlò örö dájúdájúgírámà, pratya, prakarana. Eyin sin gbekele awon oro wanyi, esin da isotunmo teyin na sile. Iranu nigbogbo eleyi. dukṛn karaṇe, awon ìmö ìlò örö dájúdájúgírámà, kole funyin nigbala lasiko ti'ku bade. Didirin yi, s'adura si Govinda, Govinda, Govinda. Itosona Śaṅkarācārya leleyi. Nitoripe olofokansi loje, olufokansi pataki. sugbon osi huwa biwipe alainigbagbo loje lati paarapo pelu awon eyan bayi Afi toba sowipe alainigbagbo loje, awon alainigbagbo o le feti si nkan ton so. Nitorina lose da imoye Mayavada yi sile fun igba die. Kosi besele lo imoye Mayavadi yi tayeraye. Imoye tayeraye ni ti Bhagavad-gta. Otooro leleyi.