YO/Prabhupada 0445 - This Has Become a Fashion, to Equalize Narayana With Everyone



Lecture on SB 7.9.2 -- Mayapur, February 12, 1977

Pradyumna: Isotunmo - Orisa ola, Laksmiji, awon orisa to wa si bere lowo re pe ko losiwaju Olorun, sugbon nitoripe on beru ko lo. Sugbon oun gan koi ti ri iru irisi Olorun bayi, nitorina kole summo."

Prabhupāda:

sākṣāt śrīḥ preṣitā devair
dṛṣṭvā taṁ mahad adbhutam
adṛṣṭāśruta-pūrvatvāt
sā nopeyāya śaṅkitā
(SB 7.9.2)

Beena, Śrī, Lakṣmī, wa nigbogbo'gba pelu Nārāyaṇa, Bhagavān. Lakṣmī-Nārāyaṇa. Ibikibi ti Narayana ba wa ni Laksmi na ma wa. Aiśvaryasya samāgrasya vīryasya yaśasaḥ śriyaḥ (Viṣṇu Purāṇa 6.5.47). Śriyaḥ. Beena Bhagavan, Olorun, sini awon auye mefa: aiśvarya, ola, samāgrasya, gbogbo ola.. koseni tole farawe. Ninu ile aye yi awon eyan sin tiraka. Eyin ni egberun kan, elomi ni egberun meji, okurin imi ni egberun meta tabi millionu meta. Koseni tole sowipe, " Otan, emi ni mo lowo ju ninu aye yi." Rara. Kolese. wan gbodo tiraka. Sama ūrdhva. Egbe nitumo Sama, to gaju nitumo ūrdhva Koseni tole j'egbe pelu Narayana, ati koseni tole gaju Narayana. Asa to wa lenujometa nisin leleyi, pe daridra-nārāyaṇa. Rara. kosibi daridra se fe je Narayana, kode si bi Narayana se fe daridra, nitoripe nigbogbo'gba ni Śrī, Lakṣmījī wa pelu Narayana. Bawo lose je daridra? Awon ironu awon didinrin leleyi, aparādha.

yas tu nārāyaṇaṁ devaṁ
brahmā-rudrādi-daivataiḥ
samatvena vikṣeta
sa pāṣaṇḍi bhaved dhruvam
(CC Madhya 18.116)

Śastra sowipe, yas tu nārāyaṇaṁ devam. Nārāyaṇa,Olorun... Brahmā-rudrādi daivataiḥ. kama wa soro nipa daridra, teyin ba tie fi Narayana lori ipo awon orisa to ku bi Brahma tabi SIva, Teyin ba rowipe " Nkankana ni Brahma ati Siva je pelu Narayana," samatvena vikṣeta sa pāṣaṇḍi bhaved dhruvam, lesekese pāṣaṇḍi leni na. Eni to kun fun irira. Oro sastra leleyi. Yas tu nārāyaṇaṁ devam brahmā-rudrādi-daivataiḥ samatvena.

Iwa yi ti d'asa, lati farawe Narayana pelu gbogbo eyan. Beena asa India ti baje. Kosi besele s'egbe pelu Narayana. Nārāyaṇa gan so ninu Bhagavad-gītā, mattaḥ parataraṁ nānyat kiñcid asti dhanañjaya (BG 7.7). Oro imi ton lo nibi ni: asamaurdhva. Koseni to le wa lori ipo kanna pelu Narayana, Viṣṇu-tattva. Rara. Oṁ tad viṣṇoḥ paramaṁ padaṁ sadā paśyanti sūrayaḥ (Ṛg Veda 1.22.20). Ṛg mantra leleyi. Viṣṇoḥ padaṁ paramaṁ padam. Arjuna ti pe Bhagavān , paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān (BG 10.12). Paramaṁ bhavān. ironu awon pasandi wanyi ole pa ilosiwaju wa ninu eto mimo. Māyāvāda. Māyāvāda. Beena Caitanya Mahāprabhu ti sowipe ema ni nkankan se pelu awon Māyāvādī. Māyāvādī bhāṣya śunile haya sarva-naśa (CC Madhya 6.169): "Enikeni toba ni nkankan se pelu awon Mayavadi, ile aye mimo re ti tan." Sarva-naśa. Māyāvādī haya kṛṣṇe aparādhi. E gbodo gbiyanju lati ma ni nkankan se pelu awon asiwere Mayavadi wanyi. Kosi nkankan biwioe " Narayana ti di daridra." Kolese se. beena Nārāyaṇa wa pelu sākṣāt śrīḥ ni gbogbo'gba. Śrī, nibi nipataki, Śrī, Lakṣmījī, want saalaye wipe nigbogbo'gba lowa pelu Narayana. Śrī expansion wa ninu Vaikuṇṭhaloka. Lakṣmī-sahasra śata-sambrahma sevyamānaṁ.

cintāmaṇi prakara-sadmasu kalpa vṛkṣa
lakśāvṛteṣu surabhīr abhipālayantam
lakṣmī sahasra-śata sambrahma-sevyamānaṁ
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi
(Bs. 5.29)

Kon se Śrī, Lakṣmī kan soso, sugbon lakṣmī-sahasra-śata. wan sise fun Olorun, sambrahma sevyamānaṁ. Awa na sin gbadura si Laksmiji pelu sambrahma, " Mama, edakun e fun mi lowo. E funmi l'ebun die, inu mi a dun." Asin gbadura si Sri. Sugbon koni duro pelu wa, Śrī. Oruko imi fun Śrī ni Cañcalā. Cañcalā, bose wa ninu aye yi niyen. Lehin mole je olowo, lola mole di talaka loju titi. Nitoripe gbogbo ola aye yi wa lori owo. beena, koseni tole lowo tan ninu aye yi.Kolese se. Sri yi kole joko sibi kan, wan s'adura s'Olorun pelu sambrahma, pelu iwa dada. Nibi asin ronu, " Laksmiji o le lo," sugobn nibe Laksmiji si ronu pe ki Krsna ma lo." Iyato to wa niyen. Nibi awan beru pe Laksmiji le loleyikeyi asiko, sugbon nibe awon eyan n'beru pe Krsna lelo. Iyato to wa niyen. Beena iru awon Krsna, tabi Narayana, bawo lonsele je daridra? Ironu ni gbogbo e.