YO/Prabhupada 0448 - We Should Take Lessons of God from Sastra, from Guru and from Sadhu



Lecture on SB 7.9.3 -- Mayapur, February 17, 1977

Pradyumna: Isotunmo - " lehin Brahma si bere lowo Prahladfa Maharaja to wa legbe re : Omo ni, Inu n'bi Oluwa Nrsimha-deva nitori baba esu toni. Dakun lo ba soro k'okan bale."

Prabhupāda:

prahrādaṁ preṣayām āsa
brahmāvasthitam antike
tāta praśamayopehi
sva-pitre kupitaṁ prabhum
(SB 7.9.3)

Beena inu sin bi Nrsimha-deva gidi gan. nisin awon alainigbagbo okurin, tio mo nipa eni t'Olorun je, won ma sowipe, " Kilode tinun'bi Olorun?" Kilode ti ibinu wa ninu Olorun? Olorun gbodo ni gbogbo nkan bibeko bawo l'Olorun se je pipe? Pūrṇam. Iwa awon eda to wa laye na ni'binu je. Kosi b'okuta se fe binu, nitoripe okuta loje. Sugbon awon eda to wa laaye le binu. Iwa toni leleyi. Kilode t'Olorun o ye ko binu? Wan foriro eni t'Olorun je; awon wanyi o ni ijerisi kankan nipa Olorun. Won kan ronu " bayi bayi l'Olorun se ri. Olorun o le binu. Eda alafia nikan l'Olorun je." Kilode? Latibo ni ibinu na tiwa? Lat'Olorun na. Bibeko kosibi ibinu se le wa .

Gbogbo nkan lo w anibe. Janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). isotunmo Brahman niyen. Ounkoun t'awa ba le jerisi ati ati ounkoun tawa o le jerisi.... Gbogbo nkna ko lale jerisi. Gege bi Nrsimha-deva wan sowipe Laksmi gan ko riri, pe Olorun le di idai kiniun ati idaji okurin. Laksmi gan, kama wa soro nipa awon iyoku. Laksmi, to wa pel'Olorun nigbogbo'gba. beena wa saaley wipe, aṣruta. Kini yen je? Adṛṣṭa. Adṛṣṭa aṣruta pūrvatvāt. Eru ba nitoripe ko riri, iru eda to tobi bayi, idaji kiniun ati idaji okurin. Olorun ni irisi to po: advaita acyuta anādi ananta-rūpam (Bs. 5.33). Ananta-rūpam; beena, advaita. beena ninu Bhagavad-gita won sowipe awon irisi Olorun dabi ìrúmiìgbì omiìbilù-omi lat'odo tabi t'okun Koseni tole ka gbogbo e tan. Oma ree yin teba fe ka iye ìrúmiìgbì omiìbilù-omi to wa. Kolese se. Beena awon irisi olorun po to awon ìrúmiìgbì omiìbilù-omi . beena eyin o le ka awon ìrúmiìgbì omiìbilù-omi ; nitorina kosi bosele ye yin, iwonba irisi toni. Laksmi gan, ati Anantadreva gan koi ti ye won. Iriri wa ko po - o kere gan. kilode tan sowipe " Olorun o ni nkan bayi bayi, Olorun o le ni ... Iwa alainigbagbo leleyi. Awon lon soro bayi. ninu Ārya-samājī ti Veda gan, won sowipe kosi b'Olorun sele ni irisi wanyi. Kilode?

T'Olorun baje eni to l'agbara ju kilode ti kole gba ara toba fe? Nitorina awa ogbodo fetisi ikeeko nipa Olorun lodo awon asiwere wanyi. Agbodo keeko nipa Olorun lati awon sastra,lati guru lati sadhu - eni toti ri Olorun, tattva-darśina. Tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā, upadekṣyanti tad jñānam (BG 4.34). Imoye mimo nitumo Tad jñānam. Tad-vijñānam.

tad-vijñānartham sa gurum evābhigacchet
samit-pāṇiḥ śrotriyaṁ brahma-niṣṭham
(MU 1.2.12)

Beena tad-vijñānam, kosi besele foriro. Kolese se. Egbodo ko lateni toje tattva-darsinah, toti ri Olorun. Pe eyin ti ri gan ko to... Gege bi Laksmidevi, ton ri Olorun nigbogbo'gba Oun gan o mo. Asruta-purva. Adrstāsruta-purva. beena ounkoun tawa ba ri, tabi tawa o le ri gbogbo e lo wa n'be. Ahaṁ sarvasya prabhavaḥ (BG 10.8). Kṛṣṇa sowipe, " Oukoin teba ri, ounkoun teba jerisi, emi lorisun gbogbo e." Beena ibinu gbodo wa nibe na. Bawo leyin sele sowipe " Olorun o gbodo binu. Olorun o gbodo se bayi. Olorun o gbodo..? Rara, otooro ko leleyi. Iriri tawa leleyi.