YO/Prabhupada 0450 - Don't Bring any Material Desire in Executing Devotional Service - Prabhupada



Lecture on SB 7.9.4 -- Mayapur, February 18, 1977

Pradyumna: Isotunmo - " Narada Muni tesiwaju: Oba mi, botilejepe olufokansi Prahlada Maharaja je omode, osi gba oro Brahma. Die die o si sumo Oluwa Nrsimha-deva, lehin na o teriba fun pelu owo mejeji paapo."

Prabhupāda:

tatheti śanakai rājan
mahā-bhāgavato 'rbhakaḥ
upetya bhuvi kāyena
nanāma vidhṛtāñjaliḥ
(SB 7.9.4)

mahā-bhāgavata ni Prahlāda Mahārāja je, olufokansi lasan ko loje. Arbhakaḥ. Omode kekere nitumo Arbhakaḥ, omo-okurin odun marun. sugbon mahā-bhāgavata. kon sepe nitoripe omode loje... Ahaituky apratihatā (SB 1.2.6). Omode na le di mahā-bhāgavata, alakowe pataki na le d'esu. Ipo Bhakti si ga toje pe awon idan mu wanyi wa. Arbhakaḥ. Didinrin tabi omode nitumo Arbha, sugbon maha-bhagavata lasiko kana. O lese se. Itumo Maha-bhagavata ni.. Agbodo seyato laarin awon olufokansi to wa: kaniṣṭha adhikārī, madhyama-adhikārī ati mahā-bhāgavata, uttama adhikārī. Uttama-adhikārī.

Beena mahā-bhāgavatam ni Prahlāda Mahārāja , mahā-bhāgavata, konsepe nitoripe omo odun marun loje.. Rara. Latinu oyun iya re loti di mahā-bhāgavata. Nigbati awon orisa gbe iya re Narada Muni n'koja nigbana: "Kileyin se?" "Iyaw Hiranyakasipu loje, osi ti loyun. Afe pa omode yi na." Narada Muni sofun won lesekese, "Rara, rara, rara. Omode lasan ko loje. mahā-bhāgavata loje. Ema fowokan." Beena won si gba. Narada Muni ... devata loje. Botilejepe osi se asise die, lesekese ti Narada Muni si sofun pe " E fi sile. mahā-bhāgavata loje," lesekese.... Beena Narada Muni sowipe, " Omo mi, wa pelu mi, tit di gba t'oko re ba pada." Hiranyakasipu lo sadura latile ba awon orisa ja. Adura awon esu leleyi. Awon awe ati inira to po gan ni Hiranyakasipu se. Kinidi fun? Ijeere aye yi.

Iru awe ati inira wanyi, tapasya, iranu loje. Śrama eva hi kevalam (SB 1.2.8). Awon eyan ile aye yi, wan sin gba'we bayi. Afi ton ba se bayi kosi bonsele ni ilosiwaju ninu eto oro aje, tabi ninu eto oselu. Won gbodo sise gidi gaj. Gege bi ilu wa, Olori pataki Mahatma Gandhi si sise gidi gan. Ogun odun ni ilu Durban si ba asiko re je, pelu odun ogbon ni India. Mo sowipe o ba asiko re je. Kilode? Fun awon eto oselu. Kini idi fun eto oselu na? Nisin ati di awujo ton pe ni India. Agbodo le awon olugbe geesi jade ka gba ijoba wa." Idi gbogbo e niyen. Beena anyābhilāṣitā-śūnyaṁ leleyi (CC Madhya 19.167). Kini'di gbogbo e? Leni olugbe India leje; lola eledi nkan toyato. Tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13). Egbodo tun ara imi gba. Beena iru ara wo lema gba? Sema tun ara India gba? Ko daju. teyin ba tie ni ife to po fun India, gege bi karma yin seri beena lema tun ara imi gba. Teba gba ara igi ni India, lehin na ema duro sibikan fun odun egberun marun. Kini ijeere na? Krsna ti sowipe tathā dehāntara-prāptiḥ. Kosowipe eda eyan le pada di eda eyan. Ko daju. Awon olosi kan sowipe lehin igba teba ni ara eda yi, kole dinkun mo. Rara. Otooro ko leleyi. Otooro niwipe ninu awon eda 8,400,00. gege bi karma yin seri beena lema ni ara na. Otan. Ko daju pe eyin ma ni.. teyin ba tie gba ara olugbe India, talo fe mo gan? beena laisi imoye Krsna, ounkoun awe taba gba, awon inira taba faramo, ilokulo asiko loje. Oye ka mo. Ilokulo asiko loje. Nitoripe egbodo tun ara imi gba. Gbogbo ikan ati yipo. Egbodo wa ni ihoho; egbodo pada ni ihoho. Kosi besele jeere kankan. Mṛtyuḥ sarva-haraś cāham (BG 10.34). Sarva-haraś ca. Ounkoun teba ti ni, gbogbo e lo ma lo. Mṛtyu... gege bi Hiraṇyakaśipu. Hiraṇyakaśipu,ounkoun toni, Prahlāda Mahārāja sowipe, "lasiko kan, E ti mulo. Beena Olorun mi, kilode teyin fe funmi ni awon ibukun aye yi? kinidi fun? Moti ri baba mi. to ba kan mi oju re eru ma ba gbogbo awon orisa. sugbon iru ipo yi, eti paari e lasiko kan. Kinidi fun iru ipo bayi?"

Beena nitorina ni awon olufokansi mimo, o fe ni oun aye yi.

anyābhilāṣitā-śūnyaṁ
jñāna-karmādy-anāvṛtam
ānukūlyena kṛṣṇānu-
śīlanaṁ bhaktir uttamā
(Brs. 1.1.11)

Agbodo ranti nigbogbo'gba pe ema mu awon ife okan ile aye yi wa sinu ise ifarasi fun Olorun. Kole je mimo to be ribe. Na sādhu manye yato ātmano 'yam asann api kleśada āsa deha. Lesekese teyin ba mu awon nkan aye yi wonu e, eti lo asiko yin nilokulo. Nitoripe eyin ma tun ara imi gba. Ema ri oun te fe gba. Krsna si dara gan - ye yathā māṁ prapadyante tāṁs tathaiva bhajāmi (BG 4.11) - teyin ba ni awon ife okan tefe fi bhakti fi gba, Krsna si dara gan: " O da bee." Sugobn egbodo tun ara imi gba. teyin ba si yasi mimo, tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti (BG 4.9). Nkan tafe niyen, awon olufokansi mimo. Nitorina ati salaye fun awn eyan kon gbiyanju lati di olufokansi mimo. Olufokansi mimo... apeere to wa niyen, maha-bhagavata. Omo-okurin odun marun yi,, koni ise imi ju latii di olufokansi mimo fun Krsna.