YO/Prabhupada 0453 - Believe It! There Is No More Superior Authority Than Krishna



Lecture on SB 7.9.5 -- Mayapur, February 25, 1977

Ema rowipe Olorun o le ronu. Rara. Gbogbo nkan lowa. Afi tobajepe, Olorun fun ara re ni awon iwa okan rere, nibo lati ri gba? Nitoripe lat'Olorun ni gbogbo awon nkan wanyi ti wa. Janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Athāto brahma jijñāsā. Kini Brahman? Orisun t'alakoko gbogob nkna ni Brahaman je. Brahman leleyi. Bṛhatvāt bṛhanatvāt.

Beena t'Olorun o ba ni awon iwa wanyi, bawo lese je Olorun? Ti omo kekere wa teriba fun wa, lesekese lama rowipe; " Oh, omo dada leleyi." Beena Oluwa Krsna, Nrsimha-deva, Oun na di pariplutah, osi ni okan rere pe " Omo kekere yi dara." Pelu ironu okan yi, lesekese lo gbe omo na soke: "Omo mi dide." lesekese na lo f'owo re sori re. Utthāpya tac-chīrṣṇy adadhāt karāmbujam. Karāmbhuja, owo re to dabi ododo. awon iwa wanyi siwa. Nitoripe idamu si wa lokan omo na bi iru irisi nla yi se jade latinu ogiri, ati baba re to tobi gan, tiku, beena awon nkan wanyi si fun ni idamu die. Beena vitrasta-dhiyāṁ kṛtābhayam: " Omo mi, ma jek'eru ba e. Gbogbo nkan wa dada. Mo wa nibi, ma beru mo. Je k'ikan re bale. Mo ma toju re." ṣàfirọ́pò towa leleyi. Beena koside lati... d'alakowe, Vedantist ati .... Nkan toye ke se niwipe: E je k'okan yi dabi t'omode, egba Olorun kesi doobale fun - gbogbo nkan ti daju niyen. Nkan tafe niyen: iwa nirorun. Irorun. Kesi nigbagbo ninu Krsna. Bi Krsna se so, mattaḥ parataraṁ nānyat kiñcid asti dhanañ... (BG 7.7). E gbaagbo! Kosi olori imi to gaju Krsna lo.

O si sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Itosona to wa niyen. Koko oro gbogbo awon itosoana to wa leleyi. E nigbagbo ninu Krsna, Eledumare. Krsna leleyi. Enigbagbo pe Krsna leleyi. Awon omode kekere ma nigbagbo na sugbon opolo wa ti kuna, asi ma bere, " Boya lati'gi tab'okuta tabi irin lonti se irisi na?" nitoripe okan wa o mo. Asin rowipe lati irin loni se irisi Olorun. Boba tiejepe irin ni, s'Olorun ko ni irin an? Olorun n'irin na je. Nitoripe Krsna sowipe bhūmir āpo 'nalo vāyuḥ khaṁ mano buddhir..., apareyam..., bhinnā me prakṛtir aṣṭadhā (BG 7.4). Krsna ni gbogbo nkan je. Laisi Krsna kos'aye kankan. Beena kilode ti Krsna o le farahan bose fe? O le farahan ninu irin na. O le farahan ninu okuta. O le farahan ninu igi. O le farahan ninu ileke. O le farahan ninu oda ton kun. Bose fe lole wa... Agbara re niyen. sugbon agbodo mowipe " Krsna leleyi." Ema rowipe " Krsna yato si irisi re, ati wipe nibi awa ni irisi ton se lati'rin." Rara. Advaitam acyutam anādim ananta-rūpam (Bs. 5.33). Advaita. Osi ni aimoye irisi na, sugbon ikanna nigbogbo wan.

Beena, osi wa ninu oruko re. Abhinnatvān nāma-nāminoḥ (CC Madhya 17.133). nigbateyin ban korin oruko mimo Krsna, ema rowipe iyato wa laarin ohun teyin se ati Krsna. Rara. Abhinnatvān. Nāma-cintāmaṇi-kṛṣṇaḥ. Bi Krsna seje cintamani, beena l'orukko re se je cintamani. Nāma cintāmaṇiḥ kṛṣṇaś caitanya-rasa-vigrahaḥ. Caitanya, imoye to pe, nāma-cintāmaṇi-kṛṣṇaḥ. Teyin ba ni asepo pel'oruko na oye ke mo wipe, Krsna mo nipa ise teyin se Eyin s'adura si, " He Krsna! He Radharanai! E dakun e fun mi nise yin se." Itumo Hare Krsna mantra yi, Hare Krsna, " He Krsna, he Radharani, he agbara, e dakun e fimi sinu ise yin." Ayi nanda-tanuja patitaṁ kiṅkaraṁ māṁ viṣame bhavāmbudhau. Ikeeko Caitanya Mahāprabhu leleyi. " Olorun mi, Nanda-tanuja..." Inu Krsna man dun gan teba ni asepo pelu Oruko re, Ise re pelu awon olufokansi. Eyan loje. Krsna o l'oruko sugbon toba ni asepo pelu awon olufokansi, lehin oma l'oruko. Gege bi Krsna se ni nkan se pelu Nanada Maharaja, bata igi ti Nanda Maharaja... Yaśodāmayī si bere lowo Kṛṣṇa - seeti ri aworan na - " S'ole mu bata baba re wa?" "Beeni!" Lesekese o gbe sori. Seri? Krsna niyen. Inu Nanda Maharaja si dun gan: "Oh omo re dara gan. O le gbe eru to tobi bayi." iwa to wa niyen. Nitorina ni Caitanya Mahaprabhu sen pe Krsna ni, ayi nanda-tanuja: "O Krsna, ton bi latinu ara Nanda Maharaja.." gege bi baba seje eni ton fun awon omode l'ara, beena Krsna, botilejepe, oun ni orisun gbogbo nkan, sugbon, wantinu ara Nanda Maharaja. Krsna-lila leleyi. Ayi nanda-tanuja patitaṁ kiṅkaraṁ māṁ viṣame bhavām-budhau (CC Antya 20.32, Śikṣāṣṭaka 5). Caitanya Mahāprabhu o pe Kṛṣṇa ni " Eledumare" ri. Iwa awon ton rowipe Olorun o kin seyan niyen. O sowipe, ayi nanda-tanuja,, " Omo-okurin Nanda Maharaja." Omo-okurin Nanda Maharaja. bhakti leleyi. Alailopin loje. Gege bose ya Kuntidevi lenu nigbto rowipe Krsna n.beru Yasodamayi. Se mo sloka na. Oy alenu pe " Krsna, toje eni to daju ti gbogbo awon eyan'beru, sugbon oun na beru Yasodamayi."

Beena awon olufokansi nikan lole gbadun iwa yi, kole ye awon alainigbagbo. Nitorina Krsna sowipe, bhaktyā mām abhijānāti (BG 18.55). awon olufokansi nikan, elomi ko. Awon eleomi ole raye ninu ijoba re yi, lati ni oye na. Teba fe ni oye nipa Krsna lat'ona bhakti nikan. Kosi nkankan tole ranyin lowo kobaa je imoye, karma tabi jnana. E gbodo d'olufokansi. Bawo lesele d'olufokansi? Bawo lose rorun to? Seri nibi bi Prahlada Maharaja, omo kekere lasan sen s'adura. Krsna na ti bere lowo yi, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). teba se awon nkan merin wanyi dada - ke ronu nigbogbo gba nipa Krsna... Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare, (awon ajo na bere sini korin) Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare. ironu nipa Krsna leleyi, man-mana. Ele gba ofin Hare Krsna mantra yi nikan teyin ba je olofokansi to daju. Laidi awon olufokansi to daju o ma lee gan. Sugbon agbodo gbiyanju. Abhyāsa-yoga-yuktena (BG 8.8).