YO/Prabhupada 0455 - Do Not Apply Your Poor Logic in The Matters Which is Inconceivable By You



Lecture on SB 7.9.6 -- Mayapur, February 26, 1977

Pradyumna: Isotunmo - " Lati owo Nrsimha-deva lori Prahlada Maharaja, Prahlada si bo lowo gbogbo idoti aye yi biwipe wan fo gbogbo idot kuro lara re. Nitorina lesekese losi bere sini ni awon aami awon eda mimo ton jade latinu ara re. okan re si kun fun ife, oju re kun fun ekun, beena osi mu ese Oluwa sokan."

Prabhupāda:

sa tat-kara-sparśa-dhutākhilāśubhaḥ
sapady abhivyakta-parātma-darśanaḥ
tat-pāda-padmaṁ hṛdi nivṛto dadhau
hṛṣyat-tanuḥ klinna-hṛd-aśru-locanaḥ
(SB 7.9.6)

beena Prahlāda Mahārāja, tat-kara-sparśa, "ifowokan owo Nrsimha-deva," owo kanna tol'ekana. Tava kara kamala-vare nakham adbhuta-sṛṅgam. Owo kana toni nakha adbhuta... Dalita-hiraṇyakaśipu-tanu-bhṛṅgam. lesekese, pel'ekana nikan.... Olorun o si niwulo fun ohun-ijagun kankan lati pa esu nla yi, pel'ekan lasan. Tava kara-kamala. Apeere yi da: Kamala. Ododo nitumo Kamala. itele owo Olorun dabi idodo. Nitorina owo re dabi idodo, bawo ni awon ekan yi se wa? Nitorina adbhuta. Tava kara-kamala, adbhuta. Nakham adbhuta-sṛṅgam. kolese se pe idodo lotu yi koni awon ekana. Idamu to wa niyen. Ntorina ni Jayadeva se sowipe: "Iyanu loje." Nitorina agbara Olorun niyen, agbara ati ekana yi, gbogbo e loje iyanu. Śrīla Jīva Goswami ti salaaye wipe, " Afi teyin ba gba, agbara alailopin t'Olorun, kosi besele ni oye nipa re." Acintya. Acintya-śakti. Tokoja imoye wa nitumo Acintya. Kosi besele salaaye bon sen sele pe ododo yi si leekana lesekese, niseju kan, toje pe o le pa esu nla bi Hiranyakasipu. Nitorina lose je acintya. Koleye wa. Acintya. Nitorina ni itosona Veda se je acintyā khalu ye bhāvā na taṁś tarkeṇa yo jayet: " Ema fi ogbon ori kekere yin lati fi ni oye nipa awon nkan to ju yin lo." Kosi be sefe salaaye bi ododo se ni ekana. Awon eyan ma sowipe " itan akoole" loje. Nitoripe kole ye opolo won, kosi bonsele gba pe iru nkan bayi wa, wan sowipe " itan akole" loje. Konse itan akoole. Otooro leleyi. Sugbon nkan toju wa lo leleyi. Kolese se.

Beena, kara kamala yi lon gbe sori Prahlada Maharaja. Prahlādāhlāda-dāyine. Prahlāda Mahārāja si ni ife okan yi pe " Owo yi da gan." iwa nikan ko, sugbon lesekese nigbogbo awon ibanuje to ni si kuro. Ilana ifowokan mimo leleyi. Ale ni ijerisi kanna ninu aye yi. konsepe inu Prahlada Maharaja si dun leekanna nigbati owo Olorun kan ori re.... Ele ni ijeere kanna lesekese teyin ba di Prahlada Maharaja. Leyin na lee lese. Krsna ni advaya-jnana, ninu asiko tawayi Krsna ti sokale ninu ohun mimo yi: kali yuga nama rūpe kṛṣṇāvatāra (CC Adi 17.22). Asiko yi... nitoripe awon eyba aye yi ti wo lule.. kos'amuye kankan ninu won. Mandah. Gbogbo eyan lo buru. Koseni to daju. Kosi imoye mimo kankan ninu won. Kosejo na. Ninu awon ilu geesin yin awon si ni igbear gan nitori imoye aye yi ton ni, sugbon kosi imoye momi kankan lori won. fun igba t'alakoko laaye won lon ti ni imoye mimo bayi gba.

Ajo: Jaya.

Prabhupada: Bibeko kosi imoye mimo kankan. Won o mo. Oto oro niyen.