YO/Prabhupada 0456 - The Living Entity Which is Moving The Body, That is Superior Energy



Lecture on SB 7.9.6 -- Mayapur, February 26, 1977

Ninu Bhagavad-gītā wan sowipe,

bhūmir āpo 'nalo vāyuḥ
khaṁ mano buddhir eva ca
bhinnā me prakṛtir aṣṭadhā
(BG 7.4)

awon eyan aye yi - oni sayensi, ati awon elejo won sise pelu awon ohun elo aye, - ile, omi, ina, ategun, ofurufu, okan, ogbon, ati ogbon ori die, sugbin ko ju bayi lo. Won sise ninu awon ile-eko giga won sise pelu awon ohun elo aye yi kosi imoye Krsna kankan ninu aye won. Krsna sowipe... Ati ni awon imoye yi latinu Bhagavad-gita, apareyam: "Awon ohun eleo mejo wanyi, wan kere." Nitorina, nitoripe won sise pelu awon ohun eleo aye yi to kere, imoye ton ni na kere. Otooro leleyi. Konsepe mon bu won. Rara. Awon eyan yi o ni iroyin kankan. Awon alakowe giga, won sowipe ara wa ti tan.... " Ara wa ti tan" itumo re ni pañcatva-prāpta. won o mope ara imi tunwa, ara eda lasan - okan, ogbon, igberaga. won o mo. won ronu nipa ile,omi, ategun, ina, bayi bayi lo... " Eleyi ti tan. Tabi ke sin oku ara yi tabi ke fisinu ina, gbogbo e ti tan niyen. nibo ni nkan to ku?" won o ni imoye kankan. Beena awon eyan yi o ni imolye kankan nipa ara eda mimo, ile, omi, ton gbe emi wa kilon fe mo nipa emi?

Beena Krsna ti fun wa ni iroyin nipa Bhagavad-gita, apareyam: " awon ohun elo aye yi, tit de okan wa, ogbon, ati'igberaga," bhinna, " agbara mi loototo lonje. ati apareyam, " eleyi kere, imi tun wa to gaju elelyi lo." Apareyam itas tv viddhi me prakṛtiṁ parā. To gaju nitumo Parā Nisin won le bere, " Kini yen? Awa mo nipa awon ohun elo aye yi. Agbara woo lo gaju won lo?" Jīva bhūtaḥ mahā-bāho, wan ti salaaye dada: " won rowipe kos'agbara kankan ju awon agbara mejo wanyi. Nitorina lon se wa ninu okunkun. Fun asiko t'alakoko lon ni imoye gidi gba, Bhagavad-gita, gege boseje, latibe na won le mo nipa agbara imi tonpe ni jīva-bhūtaḥ. eda to wa ninu ara yim agbara to gaju. Beena awon eyan wanyi o ni ioryin kankan nipa eto yi, kode si igbiyanju kankan lati mo. ninu ile eko giga won. Nitorina lonse je mūḍha, mūḍhas. won le ni igberaga gan nitori nkan ton mo sugbon awon Veda sowipe mūḍha niwon. teyan o ba le ni oye nipa agbar to gaju yi, prakrti, iseda, bawo lose fe mo nipa Olorun? Kolese se. Lehin na awon asepo laarin Olorun ati agbara to gaju yi lonpe ni bhakti. O si le gan.Manuṣyāṇāṁ sahasreṣu kaścid yatati siddhaye (BG 7.3). Itumo siddhaye niwipe afe mo nipa agbara to gaju yi. siddhi leleyi. lehin na leyan le mo nipa Krsna.

Beena o si lee gan ninu asiko tawayi. Mandāḥ sumanda-matayo (SB 1.1.10). Awon eyan yi o fe mo, toba tie jo won loju, o soro fun wan lati mo. imoye yi o le ye won. ji alakoko egbodo mo nipa re, athāto brahma jijñāsā, imye to gaju. Nkan ta fe niyen. Sugbon awon eyan o fe se. Kosi iwaadi kankan lati mo nkan ton rin ninu ara wa. Kosi iwaadi kankan. won rowipe.. wan si jiyan lori oro na, teba si bere lowo won, " Emu awon kemika yi ke daa aye kan sile," Won a sowipe, " Mio le seyen." Kile leyi? Teyin o ba lese kilode tesen so iranu wanyi, pe " ipaapo awon kemika wanyi lo daa aye yi sile"? E mu awon kemika wanyi... Dokita Svarupa Damodara t'awa ninu ile-eko gia California, oni alakowe kan to wa soro bayi lesekese lo sofun ", ma fun yin ni awon kemika wanyi sele da aye sile?" O sowipe " Mio lese." (erin) Bonse wa niyen. Kosi bonsele se. Kosi bonsele se.