YO/Prabhupada 0463 - If You Train up Your Mind Simply to Think of Krishna,Then You are Safe



Lecture on SB 7.9.8 -- Mayapur, February 28, 1977

Pradyumna: Isotunmo - " Prahlāda Mahārāja saadura; Bawo lose se funmi, ton bi ninu ebi awon asura, lati sadura tole jeki inu Olorun dunsi? Titi d'isin, gbogbo awon orisa, pelu Brahma olori won, ati awon eyan mimo o si le fun won lati le fun Olorun nitelorun pelu oro gidi, botilejepe awon eyan wanyi ni amuye gidi to po, nitoripe won wa ninu ipo inu rere. Kilon fe so nipa mi nisin? Mio ni amuye kankan."

Prabhupāda:

śrī prahlāda uvāca
brahmādayaḥ sura-gaṇā munaya 'tha siddhāḥ
sattvaikatāna-gatāyo vacasāṁ pravāhaiḥ
nārādhituṁ puru-guṇair adhunāpi pipruḥ
kiṁ toṣṭum arhati sa me harir ugra-jāteḥ
(SB 7.9.8)

beena itumo ugra-jāteḥ ni awon ebi esu. Ugra. awon amuye meta lo wa ninu aye yi. Nitorina lonse sowipe guṇa-mayī. Daivī hy eṣā guṇa-mayī (BG 7.14). guna meta nitumo Guṇa-mayī, awon ipo meta lowa laye yi: sattva-guṇa, rajo-guṇa ati tamo-guṇa. Beena okan wa sin fo. Gbogbo wa lamo wipe iwa okan wa niyen, nigbami a gba awon nkan, nigbami atun fi won sile. Saṅkalpa-vikalpa. Iwa okan wa leleyi. Nigbami okan wa ma fo sori sattva-guna, nigbami lori rajo-guna, nigbami lori tamo-guna. Beena lasen ni orisirisi ironu. bayi lasiko iku, ironu to wa lokan wa, lasiko tinba fe farale, nkan to ma u mi losi ara ikeji mi ti sattva-guna, rajo-guna, tamo-guna. Ilana ti ipaaro ara kan fun keji fun emi wa leleyi. Nitorina agodo fun ko okan wa leeko titi di gbat'awa ba ni ara imi. ilana lati gbe ninu aye yi leleyi. Beena teyin ba ko okan yi leeko lati ronu nipa Krsna, beena kosi'alebu kankan. Bibeko asise to wa po gan. Yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ tyajaty ante kalevaram (BG 8.6). Lasio tawa bafe fi ara yi sile, t'okan wa o ba keeko lati fokan sori ese Krsna, .. (isinmi) Ara kan t'awa ba gba.

beena Prahlada Maharaja, botilejepe ko wa sori ipo irori... Nitya-siddha loje. Kos'aye kankan, nitoripe gbogbo'gba lon ronu nipa Krsna. (ariwo) (segbe:) Kiniyen? Sa vai manaḥ... (ariwo na) Sa vai manaḥ kṛṣṇa-padāravindayor (SB 9.4.18). e gbiyanju lati se nkan to rorun yi. Krsna wa nibi. Awa sin ri irisi lojojumo, ati ese Krsna. E fi okan yin bayi, lehin na ema ni idaabo gidi. Nkan to rorun leleyi. Ambarīṣa Mahārāja, olufokansi pataki loje. Oba loje, eyan dada, ninu eto oselu. sugbon osi se adase toje ko gbokanle ese to dabi ododo ti Krsna Sa vai manaḥ kṛṣṇa-padāravindayor vacāṁsi vaikuṇṭha-guṇānuvarṇane. Egbodo gbiyanju. Ema so isokuso. ( Ariwo na) (segbe:) Wahala wo niyen? E mu jade.