YO/Prabhupada 0467 - Because I Have Taken Shelter of Krishna's Lotus Feet, I am Safe



Lecture on SB 7.9.8 -- Mayapur, February 28, 1977

Prabhupāda: Beena Prahlāda Mahārāja, eyan pataki bayi, olori osi resile gan, o sowipe, kiṁ toṣṭum arhati sa me harir ugra-jāteḥ: " won bimi sinu ebi tio da. bakana moti mu iwa baba mi, iwa esu. Awon eyan bi Brahma ati awon orisa to ku o si le funwon lati fun Oluwa nitelorun, kini mofe se?" Bi awon Vaisnava sen ronu leleyi. Vaiṣṇava, Prahlāda Mahārāja, botileje eyan mimo pataki loje, nitya-siddha, O si ronu nipa eto ebi re, gege bi Haridas Thakura. Haridāsa Ṭhākura o gba lati wole sinu ile-adura Jagannātha Nkankana odun ogorun seyin, Awon eyan wanyi o gba k'eni tio kin se Hindu wole inu ile adura Jagannatha. nkankana lo sin sele. sugbon Haridasa Thankura o sagidi kankan lati wole. O si rowipe, " Beeni eyan to woole nimi, ton bi sinu ebi awon eyan lasan. Kilode ti mofe lofun awon pujari nidamu ati awon ton nise lati se fun Jagannatha? Rara, rara." Sanātana Gosvāmī, ko tie summo ilekun ile-ajosin na. Osi ronu wipe, " Ti awon pujari ba fowokan mi gbogbo won lon ma doti. kaada o da kin ma lo." Sugbon Jagannaha funa ra re wa ki lojojumo. Ipoa won olufokansi leleyi. Awon olufokansi resile, sugobn lati fi amuye awon olufokansi fihan Olorun man toju won. Kaunteya pratijānīhi na me bhaktaḥ praṇaśyati (BG 9.31).

beena oye ka gbekele onígbowó ti Krsna. Ninu gbogbo nkan, ati awon alebu, Krsna... Avaśya rakṣibe kṛṣṇa viśvāsa pālana (Śaraṇāgati). Iteriba leleyi, Itumo iteriba ... Eyan gbodo ni igbagbo to daju fun Krsna, pe " Ninu ise ifarasi Oluwa ti monse awon alebu to po ma jade, sugbon nitoripe mo wa labe idaabo Krsna, kosi nkankan tole semi." Igbagbo fun Krsna leleyi.

samāśritā ye pada-pallava-plavaṁ
mahat-padaṁ puṇya-yaśo murāreḥ
bhavāmbudhir vatsa-padaṁ paraṁ padaṁ
padaṁ padaṁ yad vipadāṁ na teṣām
(SB 10.14.58)

Padaṁ padaṁ yad vipadāṁ na teṣām. "nkan pelu alebu" nitumo Vipadam Padaṁ padam, gbogbo nkan taba se ninu ile aye yi - na tesam, fun awon olufokansi ko. Padaṁ padaṁ yad vipadāṁ na teṣām. Śrīmad-Bhāgavatam leleyi. Fun awon eyan pataki gan. Beena Prahlada Maharaja.. gege bi Kaviraja Gosvami. Nigbaton ko Caitanya-caritāmṛta, osi salaye nipa ara re pe,

purīṣera kīṭa haite muñi se laghiṣṭha
jagāi mādhāi haite muñi se pāpiṣṭha
mora nāma yei laya tāra puṇya kṣaya
(CC Adi 5.205)

bayi. Akowe Caitanya-caritāmṛta, ti salaye nipa ara re: " to woole ju era ninu egbe." Purīṣera kīṭa haite muñi se laghiṣṭha. ninu Caitanya-līlā, Jagāi-Mādhāi, awon aburo meji tonje elese to gaju. sugbon osi fun wan nigbala. Kavirāja Gosvāmī sowipe, " Elese to gaju Jagāi-Mādhāi nimi."

jagāi madhāi haite muñi se pāpiṣṭha
mora nāma yei laya tāra puṇya kṣaya
(CC Adi 5.205)

" Ese mi po toje wipe, enikeni toba p'oruko mi gbogbo ohun rere ninu aye re ma tan." Bose juwe ara re leleyi, ati Sanātana Gosvāmī na, nīca jāti nīca karma nīca saṅga... Nkan eke ko leleyi. Bi awon Vaisnava sen ronu leleyi. Vaisnava niyen. Koni igbera ga kankan.. "Oh moni nkan bayi bayi. Talo tomi? Olowo nimi. Bayi bayi nimi." Igberaga bayi. Beena agbodo ko tṛṇād api sunīcena taror api sahiṣṇunā ka tele iwa Prahlāda Mahārāja. Lehin na o daju pe Nrsimha-deva, Krsna na ma gbawa, laisi isoro kankan

Ese pupo.

Ajo: Jaya Prabhupada!