YO/Prabhupada 0471 - Easiest Way to Please Krishna - Simply You Require Your Heart



Lecture on SB 7.9.9 -- Mayapur, March 1, 1977

Prabhupāda: Beena Prahlāda Mahārāja si rowipe, botilejepe won bi binu eb awon asura, ugra, ugra-jātam, beena toba gbokanle lati sise fun Kṛṣṇa, Oluwa Nṛsiṁha-deva, pelu bhakti, pelu iwa gaja-yūtha pāya,oba awon erin... Eranko loje. Se mo itan akoole yi, pe ọ̀nì si dimu ninu omi. Beena awon meejeji bere sini tiraka, sugbon eranko omi l'ọ̀nì je, osi lagbara gan. ati erin, botilejepe eranko nla to lagbara gan loje, sugbon eranko lat'omi ko loje, beena kosi nkan tole se. Beena osi bere sini korin oruko Oluwa, bosi nigbala niyen. nitoripe ọ̀nì to mu ese erin na, oun n si nigbala nitoripe Vaisnava na loje. eranko yi, ọ̀nì , owa labe ese Vaisnava, beena oun na sini igbala. (erin) Itan akoole na leleyi. Beena, chāḍiyā vaiṣṇava sevā. bakana o sise fun Vaisnava, oun na si ni'gbala.

Beena nkan rere ni bhakti, nitoripe o si rorun lati ni ore-ofe Olorun. ti inu Krsna ba dun siyin, kilo ku? Gbogbo nkan leyin ma ri gba. Gbogbo nkan lema ni. Yasmin vijñāte sarvam eva vijñātaṁ bhavanti (Muṇḍaka Upaniṣad 1.3). Ona to rorun ju lati fun Krsna ni'telorun.... Eyin ni'di fun owo repete, ikeeko to po, ati awon nkan bayi. okan yin nikan lofe: O Krsna, Oluwa mi leje. Eyin l'oga mi tayeraye. Emi ni oniranse yin, efunmi nise yi." Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare/ (ajo daaunsi) Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare. itumo mantra Hare Krsna yi: O Krsna, O agbara Krsna, oniranse yin nimi. Sugbon bakana moti jabo sinu ile aye yi. E mu kuro ke fimi sinu ise yin." Ayi nanda-tanuja patitaṁ kiṅkaraṁ māṁ viṣame bhavaṁ budhau. Ikeeko Caitanya Mahaprabhu leleyi. Bhavaṁ budhau. Ile aye yi daabi omi okun nla, bhava. iyika ninu ibimo ati'ku nitumo Bhava omi okun nitumo ambudhau. Beena asi tiraka lati le gbe ninu omi okun yi. Beena Caitanya Mahāprabhu sowipe, ayi nanda tanuja patitaṁ kiṅkaraṁ mām: " Iranse tayeraye nimo je siyin. Bakana tabi keji moti jabo sinu omi okun aye yi. Emu mi jade." Ayi nanda-tanuja patitaṁ kiṅkaraṁ mām viṣame bhavāmbudhau kṛpāya. Pelu ore-ofe re...

ayi nanda-tanuja patitaṁ kiṅkaraṁ māṁ viṣame bhavāmbudhau
kṛpāya tava pāda-paṅkaja-sthita-dhūlī sadṛśsaṁ vicintaya
(CC Antya 20.32, Śikṣāṣṭaka 5)

Ona bhakti-mārga, leleyi, agbodo resile, ka sadura si Krsna, "E dakun e mu mi bi ikan ninu iyepe to wa labe ese yin." Nkan to rorun yi. Man-manā. Beena e ronu nipa Krsna, e d'olufokansi re, e teriba fun, ounkoun teba ni bi patraṁ puṣpaṁ, idodo kekere, omi, e le fun. Bayi ele gbe l'aye yi ni alafia pelu idunnu. Ese pupo.

Ajo: Jaya Prabhupada.