YO/Prabhupada 0473 - Darwin has Taken the Idea of Evolution From this Padma Purana



Lecture -- Seattle, October 7, 1968

Darwin timu ero itankale yi lati Padma Purana. Eyin o le ri imoye kankana ninu aye yi, tio si ninu awon iwe Veda. Osi wa ni pipe, gbogbo nkan lowa nibe. Beena ikeeko nipa eda eyan,? eto ti Darwin yi wa ninu Padma Purana, wanti salaaye dada. Darwin o le salaaye iwonba eda orisirisi melo lowa, sugbon ninu Padma Purana wanti salaye wipe eda 900,000 lowa ninu omi okun. lesekese t'omi okun ba gbe, ile na ma jade, lesekese ni awon igi ma bere. Orisirisi igi at'eso lo ma jade. Beena jalajā nava-lakṣāṇi sthāvarā lakṣa-viṁśati. ọgọ́rùn ọkẹ́, meji, lakṣa-viṁśati, ọgọ́rùn ọkẹ́. se ọgọ́rùn ọkẹ́ niyen? bakanna.. Sthāvarā lakṣa. awon tiole rin nitumo Sthāvarā. Awon eda meji lowa. Awon igi, tiole rin. Awon eda iyoku, awon eye, awon eranko, awon eda eyan won le rin. Beena sthāvarā ati jaṅgama. Awon tio le rin nitumo Jangama, ati sthāvarā awon tio le rin. Awon ori-oke, awon ipata, gbogbo won lon wa ninu awon sthāvarā. Eda na niwon. Awon ipata to po gan wa, wansi dagba soke. Itumo re niwipe emi wa ninu won, sugbon ninu awon okuta. Beena bayi lasen tesiwaju. Sthāvarā lakṣa-viṁśati kṛmayo rudra-saṅkhyakāḥ. Awon afàyàwọ́ ati kokoro. oke maarun ati egbaarun nitumo Rudra-saṅkhyakāḥ Lehin na awon afayawo, kokoro, apa ma jade - awon eye. Lehin na awon eye na ma wa. Pakśiṇāṁ daśa-lakṣaṇam: ẹgbàárùn awon eye. lehin na paśavaḥ triṁśal-lakṣāṇi, awon eranko pel'ese meta, aadota oke lona meta eye. Beena mesan at'ogun, mokandinlogbon, lehin na okanla, ogbon. Lehin na awon eye, adota, eranko, aadotaoke lona mejo. lehin na.. adota oke lona mejo .. ati oke maarun lona merin eda eyan. awon eda eyan o fibe po. ninu gbogbo won, opolopo ninu won o laju, awon die lonwa lati awon ebi Aryan. Awon ebi Aryan - awon ebi Indo-Europu, Aryan na niwon - sugbon iwonba die lonje. Awon olugbe Europu, won pelu awon Indo-Europu. Awon olugbe America lati Europu lon ti wa. Beena egbe eda eyan yi o fibe po rara. awon egbe imi si wa tio laju. Nitorina ni Vedanta se sowipe, atha atah: nisin eyin ti ni ara eda yi to daju eyin ti s'eto latini aye to rorun. Nipataki ni orile-ede America eyin ni awon ohun igbadun aye yi. Eni awon oko, eni awon titi, at'ounje, ile to dara, aso gidi, ara to lewa. Gbogbo nkan t'Olorun ti fun yin dara.