YO/Prabhupada 0487 - Whether it is Bible, Koran or Bhagavad-gita, - We Have to See What is the Fruit



Lecture -- Seattle, October 18, 1968

Prabhupāda: se ibeere imi wa?

Jāhnavā: Imoye Kristi ati imoye Krsna, awon oro yi joora gan. E dakun sele salaaye bi awon oro yi se wa.

Prabhupada: Moti salaaye aimoye igba - iwe isotunmo kekere ati iwe isotunmo nla. Eyin o le sowipe iwe isotunmo kekere o kin se iwe isotunmo, sugbon fun awon akoko lori ipo kan lo wa fun. iwe isotunmo nla fun gbaye wa fun awon akeko to yato. Sugbon akeko ni gbogbo won je. nkan ti Kristi so, imoye Oluwa na loje, sugbon fun awon ipo okurin to yato. Iru awo okurin wo niyen je? Awon eyan tio laju dada. Nitoripe Kristi n'soro nipa imoye Oluwa, asise re niyen, wan si kan lori igi. Iru awon okurin wo leleyi? Eyin e daajo. Asise kan soso to ni niwipe o salaaye nipa Oluwa, wan si pa. ijeere ton fun ni wipe won pa. Iru awon eyan wo leleyi? Ipo aye yi leleyi, egbiyanju koba le ye yin. Nitorin nkan ti Jesu Kristi sofun nigbana to. Sugbon nigbaton so Bhagavad-gita si Arjuna, nkan imi niyen. Beena agbodo soro pel'asiko tawa, pelu nkan ton sele, ati fun iru awon eyan ton gbo. Seyin o ri wipe nibe awon eyan die lon wa? Kilode? Sayensi imoye Krsna yi o le ye won. Fun gbogbo awon eyan ko lo wa fun. Ipo to gaju lori eto imoye Oluwa leleyi. Ife. Ife Oluwa. Beena awon ikekeo ife Oluwa si wa, o daju. Iyato to wa niyen. Nkankanna. Egbiyanju lati ni oye na. Iwe isotunmo kekerewa fun awon akeko ni ile-iwe akobere, iwe isotunmo fun agbaye wa fun awon akeko ile-iwe giga, iwe isotunmo ni awon mejeji je. Sugbon fun awon ototo lowa fun. phalena pariciyate ni idanwo to wa. Phalena paricīyate, ogbodo ye yin. kasowipe eyin ni irin ajo ninu aginju. awon igi si po nibe Sugbon eyin o le da awon igi mo. sugbon lesekese teyin ba ri awon idodo lori igi na, " Oh, eso oro oyinbo leleyi. Igi re leleyi." Gege bi ijokeji to sofunmi pe iwo ori igi eso oro oyinbo ri? Beeni. Nisin nigbato ri igi na, oye e, " Igi eso orro leleyi. Oh!" Idanwo fun awon iwe mimo niwipe bi iwe na sen salaaye nipa ife Oluwa. Phalena paricīyate Teyin ba riwipe awon ofin esin, sin fun yin ni iranlowo lati jeki ife yin s'Oluwa posi, lehin nkan to da niyen. Kosejo pe Bibeli tabi Korani tabi Bhagavad-gita loje. Konse nkan pataki. Agbodo wo ibajade to wa nibe. Ti eso re niwipe awon eyan tini ife Oluwa, nkan pipe loje. Ema gbiyanju lati mo boya nkan bayi bayi da tabi rara... Rara Ewo ibajade to wa. teyin ba rii esona, t'ipo kini loje. Beena konse nkan pataki toba je Bibeli tabi Gita. Teyin bale nife Oluwa lati kika BIbeli, nkan to daju niyen, teyin basi le nife Oluwa lati kika Bhagavad-git, nka n to daju niyen. teyin o ba se, lehin boya Bibeli tabi Koran tabi Bhagavad-git a loje, Koni ipa kankan lori yin. Owo yin lowa. Kon se nkan ifiwera, sugbon ise owo yin loje. Teyin ba tele awon ilana ti Jesu Kristi ti fun wa, eyin na ma ni ife Oluwa. O daju. Beena, teyin ba tele awon itosona Krsna, eyin na le ni. Beena owo yin lowa. Egbiyanju lati se. Teyin o ba le tele, e gbiyanju lati se ikekoo awon mejeji, " Se eleyi da" tabi " Se eleyi o da" , "Se eleyi o da" tabi " Se eleyi da" nkan tonpe ni śrama eva hi kevalam (SB 1.2.8) - ise lasan. kilode tefe se ikeeko ifiwera yi? Lati mo beyinsele nife Oluwa si,otan. Phalena paricīyate. " Boya eso oro lowa nibe, o dabe; ema ronu nipa igi na. Mofe mo nipa eso oro."