YO/Prabhupada 0489 - By Chanting on the Street, You are Distributing Sweetballs



Lecture -- Seattle, October 18, 1968

Viṣṇujana: Nigbat'awa ban korin pelu ohun diedie tabi ta ban korin soke ninu kirtana, soye ki okan wa ma ronu?

Prabhupada: Se koye ko ronu?

Visnujana: Oti bere na...

Prabhupada: Ona to daju leleyi. T'okan yin ba jina, orin kiko yi ma je ke fokan le. Se ti ri bayi? Ohun Krsna ma je ke se. Orin kiko yi da gab, osi daju fun asiko tawayi. EYin o le sasaro. Okan yin o bale, eyin o le fokan sibikan. Nitorina egbodo korin, ohun yi, asi wole sinu okan yin. teyin o ba fe Krsna gan, Krsna ma wole sinu okan yin. pel'agidi. Ona to rorun ju leleyi. Eyin o gbodo gbiyanu ju bayi lo. Krsna ma wa. Ona to da gan leleyi. Ona ton fun wa fun asiko tawayi leleyi. awon eyan to wa na ba jere. Ekorin pel'ohun soke. Awon eyan tio mo nipa re,k na gege bi oju titi , awon eyan ma sowipe " Hare Krsna!" Bawo lonse ko? Lati igboran na. Otan Nigbami ti awon omode ba ri wa, lesekese lon ma kigbe " Oh, Hare Krsna!" Ni Montreal awon omode, ton rin loju titi, awon omo kekere, awon onitaja, gbogbo won lon pariwo " Hare Krsna!" Otan. Ati fi Hare Krsna sinu okan won. teyin ba se yoga ole da fun yi sugbon eleyi da fun awon eyan na, Kasowipe eyin gbadun nkan to da, awon adun,- ipo kan leleyi sugbon teyin ba pin adun yi , ipo imi niyen. Beena orin kiko yi lori titi, eyin pin adun yi (erin) Alaun ko niyin, tefe danikan je. Eyin si l'okan rere pe efe pin fun gbogbo eyan. Nisin e korin, e pin fun awon eyan (erin).