YO/Prabhupada 0494 - Napoleon Constructed Strong-built Arches, but Where He Has Gone, Nobody Knows



Lecture on BG 2.14 -- Germany, June 21, 1974

Ninu eto imi nitumo Anyathā rūpam, gbigbe aye wa l'ona imi. Itumo Bibeko niwipe emi nimi. Moni ara emi. sugbon bakana tabi keji, nitori ife okan mi, Mosi ni ara eda gba, tabii ara aja, nigbami ara ologbo, nigbami ara igi, nigbami ara orisa. Ara orisirisi 8,400,00 lowa. Beena mosin paaro won bi ife okan mi se je si. gege bi aisan mi se jesi, kāraṇaṁ guṇa-saṅgaḥ asya, awon nkan emi leleyi je. Imoye eda gidi leleyi, konsepe ka da nkan sile lati le ni idunnu fun igba die. Iwa didinrin niyen Iwa didinrin niyen, ilokulo asiko. T'awa ba da nkan sile fun igbadun ara eda tani nisin, Pe mofe gba ninu ile aye yi dada, sugbon - " Eyin o le gbe ninu aye yii lasi isoro kankan." Oye ke mo l'alakoko. kasowipe okurin kan sin kole to da, ile to l'agbara gan. Kosi bosele wolule leyikeyi asiko. Sugbon ko buru, sugbon kileyin ti se fun ara yin, pe eyin ma wa laye tayeraye lati gbadun awon nkan wanyi? "Rara. e jeko wa bose wa. E jekin kole to lagbara gan." Beena ile na ma wa . E le losibe. Orile-ede to lagbara. Gege bi Napoleon se ko awon ile to lagbara, sugbon ibo towa nisin koseni to mo. Beena Bhaktivinoda Ṭhākura ti korin wipe, jaḍa-bidyā jato māyāra vaibhava tomāra bhajane bādhā. T'awa base ni ilosiwaju to ninu eto igbadun ile-aye yi tabi ilosiwaju ile aye yi, T'awa base gbagbe idanimo wa t'alakoko. Ibajade to wa niyen. Beena agbodo ni oye na wipe awa ni ise imi toyato, ise gidi. Nkan ton pe ni imora-eni niyen, pe " ara mi konimi." Imora-eni leleyi. Nkan ti Krsna ti salaaye niyen ni bere, pe " Ara yin o leje." Oye talakoko, Imoye t'alakoko, ni lati ni oye wipe " ara ni ko nimi. Emi nimo je. Moni ise im toyato lati se." Konsepe awon ise fun igba die wanyi tabi awon ise bi t'aja, tabi eda eyan, tabi bi ekun, tabi igi tabi eja, Āhāra-nidrā-bhaya-maithunaṁ ca. Ofin kanna lowa ninu eto ohun ini ara wa. Jijeun, sisun, imo ako ati abo ati igbeja ara wa. Sugbon ninuara eda, moni ise imi toyato, imora eni, lati jade kuro ninu idimu ara eda yi. Nkan tonpe ni imoye niyen. Laisi ioye yi, ounkoun tawa ba ni ilosiwaju ninu re, iwa didinrin lasan loje, otan. Śrama eva hi kevalam (SB 1.2.8).