YO/Prabhupada 0498 - As Soon as I Give up this Body, all my Skyscraper Building, Business



Lecture on BG 2.15 -- Hyderabad, November 21, 1972

Beena itosona too wa leleyi. E gbiyanju lati ni imoye Krsna. Beena awon nkan ile aye yi, o ni fun yin ni idamu, awon iyika igba die ile aye yi. Konse ara eda yi nikan, niotooro enikeni toba ni ilosiwaju ninu ile aye mimo, awon isoro oselu o le fun ni ibanuje kankan. Rara, O mo wipe awon nkan lasan leleyi je, Gege bi eni ton laala. Alaa lasan loje. Ipo wa nisin, bi alaa loje. gege bi awa sen laala ni ale. Ninu alaa na, ale daa awon nkan sile. Beena bi ala ni ile aye yi je. Ala pelu oju tola. Ala wa nigba t'awa ban sun. Sugbon ala pel'oju lila leleyi. Ise okan, ara at'ogbon re leleyi, ala lon la. nibi, ise awon oun elo marun: ile, omi, afefe, ina.... Sugobn gbogbo won, awonn mejo, oun elo lasan niwon. Beena awa sin rowipe " Moti kole to da, ile oke giga." Konse nkan gidi, ala lasan loje. Ala nitoripe, lesekese tinba f'ara yi sile, gbogbo ile oke giga, ati ile ise timo ni- gbogob e loma tan. gege bi ala se ri. Ala fun iasiko die, tabi wakati die. fun odun die. Otan. Ala loje. Beena eyan gbodo ni idamu nitori ala tan la yi. Ile aye mimo leleyi. Eyan o gbodo ni idamu. Gege bi awa o se ni idamu kankan. Kasowipe, ninu ala, won fimi sori aga ijoba, mosin sise bi oba, ti ala na ba tan, se mofe bere sini sukun. Beena, ninu ala mori ekun ton le mi. Mosin sukun " Ekun! Ekun! Egbami!." eyan ton sun segbe. asi sowipe, "Oh kilode to sen sukun? Nibo ni ekun na wa?" Beena toba tiji, asi riwipe kos'ekun kankan. Beena bi gbogbo nkan se je niyen. Sugbo ninu ala yi, awon ala gidi ati awon tawa o le fofju ri, bi woye lonje. Kini ala je? Lasiko ojo tinba ronu, woye ni ala yi je. Baba mi n'se oro aje aso. Beena nigbami to ban sun asi ma soro nipa iye: " Iye aso niyen>" Beena ala ni gbogbo e. Igbese aye yi, lati awon nkan marun wanyi tale fojuri ati awon nkan meta t'awa ole foju ri lonti wa, gege bi ala. Smara nityam aniyatām. Nitorina Cāṇakya Paṇḍita sowipe, smara nityam aniyatām. anitya, fun igba die.... Fun igba die ni ala yi wa fun.

Beena agbdo mowipe ounkoun taba ni, taba n'ri, ala ni gbogbo e je. fun igba die. Nitorina t'awa ban lo asiko wa pelu awon nkan towa fun igba die, awon nkan bi eto awujo, orile-ede, ebi, bayi bayi lo, ilokulo asiko wa loje, lai ni imoye Krsna, nkan ton pe ni śrama eva hi kevalam (SB 1.2.8), ilokulo asiko wa, akonfe da ara imi sile. ise niwipe agbodo mope " Mo yato si ala yi. Nkan pataki, oun mimo pataki nimi. Beena ise mi yato." Nkan ton pe ni ile aye mimo niyen. Ile aye mimo, toba yewa pe " Brahman nimi, mio kin se oun ile aye yi." Brahma-bhūtaḥ prasannātmā (BG 18.54). Nigbana lawa ma ni idunnu. Nitoripe awa ti ni inira lati gbogbo awon iyika ninu aye yi, ibanuje wa si po nitori awon ise lasan wanyi. sugobn t'aba ni oye wipe " awon nkan wanyi o kan mi," lehinna ni inuu wa ma dun. " Oh, mio ni nkankan se mo. Mio ni nkankan semo pelu awon nkan wanyi."