YO/Prabhupada 0506 - Your Eyes Should be the Sastra. Not these Blunt Eyes



Lecture on BG 2.18 -- London, August 24, 1973

awon orisirisi igi to Ọgọrun-Ọkẹ, Sthāvarā lakṣa-viṁśati kṛmayo rudra-saṅkhyayaḥ. awon kokoro koja egberun logorun. iyanu loje bi awon Veda sen salaaye awon nkan gege bon se je egberun logorun, Ogorun oke, gege bon seri. Idaju leleyi. sugbon awon eyan omuni pataki. sugbon awa si mowipe olori ni oro Veda, nitorina imoye tafe wa ninu e, teyan ba beere lowo mi tabi eyin, sele sofunmi iwonba eda melo lowa ninu omi? O le gan, awon oni sayensi gan kosi bonsele so. Ologbon niwan, sugbon kosi bonsele mo. sugbon awa le sofun yin pe Ẹgbẹrun lọna ẹdẹgbẹrun eda lowa nbe lai sewaadi kankan, sugbon awon iwe-mimo Veda ti salaaye, mole sofun yin. Nitorina, Vedanta-sutra sowipe tebafe rin nkankan... gege bi awon asiwere ton wa beere lowo wa, "Sele fi Olorun han mi?" Beeni. ALe fi Olorun han, teyin ba loju lati ri. Awa o le fi oju lasan wo Olorun Awon oju yi ko. sastra ti salaaye, Ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved grāhyam indriyaiḥ (CC Madhya 17.136). iye-ara nitumo Indriya pelu iye-ara tani kosi basele monipa, irisi Olorun, tabi iwa toni, tabi nkan ton se. Orisirisi nkan lafe mo nipa Olorun. sugbon awon sastra ti salaaye nipa awon amuye Olorun, irisi Olorun, ise Olorun. eyin na le ko. Śāstra-yonitvāt. Orisun nitumo Yoni. Śāstra-yonitvāt. Śāstra-cakṣus. Egbudo wo pelu oju Sastra, ema foju lasan riran ale fi sastra mo ounkoun tabafe mo. agbudo ka awon iwe yi tonse pataki, lati le mo nipa awon nkan to gaju wa lo. Acintyāḥ khalu ye bhāvā na tāṁs tarkeṇa yojayet. Tarkena,lati mo awon nkan to koja nkan tale f'ogbon wo. Orisirisi nkan. lojojumo laman ri awon irawo l'ofurufu sugbon awa o ni iroyin kankan nipa wan. awon eyan si fe lo si Osupa sugbon wansi pada wa ko daju pe wan tie lo. wansi ti fisori pe ko s'emi kankan lori awon planeti afi tawa". Imoye to daju ko leleyi. awa fe ke ri gbogbo nkan lat'oju sastra, gege bi osupa awa ti mo lati iwe Śrīmad-Bhāgavatam wipe awon eyan n'gbe nibe fun odun egbaarun bawo lasele mo iwonba odun yi? Osu mefa wanibi ojo kan pere loje nibe. eyin na esiro iwonba odun to bosi daiva-varsa loje. gege bi awon orisa sema siro niyen Ojo kan ni aye Brahma, isiri Orisa niyen Sahasra-yuga-paryantam ahar yad brahmaṇo viduḥ (BG 8.17). awa tini iroyin lati iwe-mimo Bhagavad-gita, ti krsna ti sowipe, besele siro odun awon orisa. wanti siro odun onikaluko Awon onisayenis gan gba. awon kokoro gan ni odun ogorun ni ori-ojo, sugbon tiwan yato sitawa. iyato to wa niyen, gege bi ara wa se yato na. Odun ogorun tawa na si yato si ti Brahma. Nitorina ni Krsna se siro re bayi: sahasra-yuga-paryantam ahar yad brahmaṇo viduḥ (BG 8.17).