YO/Prabhupada 0511 - Real Starvation is of the Soul. The Soul is not Getting Spiritual Food



Lecture on BG 2.25 -- London, August 28, 1973

enikeni toba rope ara yi se pataki... gege bi ijokan, oni awon asiwere kan ton wa sibi. wansi feran ounje gan. awon ti ebin pa... ebi to walati inu ara. Sugbon awon eyan mi wa to jepe ebi awon nkan mimo lon pa wan. oyeka foju si awon eyan bayi. awon ton feran ounje lasan , sugbon isoro ko niyen je. nitoripe orisirisi nkan wa lati toju ara wa. ounje toye ka wa ni ounje fun emi wa. Emi wa sini ounje mimo. Ninu ipade wa yi, afe fun awon eyan ni ounje fun emi wan. lesekese ton ba ri ounje mimo gba, gbogbo wa leni idunnu. Ipo to wa niyen. Yayātmā suprasīdati. Afi teba ri ounje mimo je kosi besele ni idunnu ninu emi. Apeere kanna lowa, pelu eye ninu agọ ẹyẹ. teba toju ile-eye na dada, te kun pelu oda, tesin fi eye na ninu e, lai fun lounje, iru awujo wo niyen? gege na wanti ti emi wa mo ara wa, ipinnu aye wa ni lati ni ominira lati itimole yi. bi eye yi sen sise lati jade ninu ile-eye yi. gege na, kosi basele ni idunnu ninu ara wa. Ni ana asi ko ninu Bhagavad-gītā, pe sarva-gataḥ ni ipo emi wa. Emi wa le losi ibikibi toba fe. Ominira toni niyen. awon eyan tonni agbara idan, le losi ibikibi tonbafe. Aṇimā, laghimā siddhi. Osi ni awon yogi ni Orile-ede India ton we laaro ni dhāma merin: Hardwar, Jagannātha Purī, Rāmeśvaram, ati Dvārakā. Awon yogi bayi si wa. wanle losibi merin toyato ninu wakati kan. Sarva-gataḥ, iyara. wakan joko sibi kan ni iseju die, wanti de ibo mi, wansi we ninu omi nibe. Kasowipe, ewo inu omi ni ilu London, ninu odo Thames, sugbon nigbate gbori soke eri ara yin ninu Ganges ni Ilu Calcutta. agbara idan awon yogi niyen. Sarva-gataḥ. Emi sini ominira to po gan, Sarva-gataḥ, ibikibi toba fe lole lo. sugbon ara je inira tawa ni. gege na teba kuro inu ara yi temu ara mimo... gege bi Narada Muni, o le losi ibkibi tobafe, irin ajo ni ise toni. nigbami a lo si Vaikuṇṭhaloka, tabi nigbami o le wasi ile-aye yi. Mimo ni ara re je, nitorina o le lo si ibikibi toba fe, aredumare okurin. Awon eyan ni aye isin fe losinu ofurufu pelu awon ero ton da. kosidi fun awon ero wanyi. Yantrārūḍhāni māyayā (BG 18.61). lati māyā lonti da awon ero wanyi. sugbon eyin na si lagbara yin. iyara to po gan. Sugbon wanti da yin duro. Nitorina agbudo se jeje tabafe yo emi wa kuro ninu ara to wa yi Ise alakoko tani leleyi. sugbon awon ton feran ara wan, awon eyan bayi dabi erankp, malu ati ketekete. Sa eva go-kharaḥ (SB 10.84.13).