YO/Prabhupada 0513 - There are so Many Other Bodies, 8,400,000 Different Types of Bodies



Lecture on BG 2.25 -- London, August 28, 1973

ibeere towa niwipe, kilode ti eni kan ni ara Oba, ikeji sini ara elede. orisirisi ara lowa, wansi koja Ẹgbẹgbẹrun mẹjọ lo kilode ti iyato wa? Wanti salaaye iyato yi ninu Bhagavad-gītā. Kāraṇam. idi ni itumo Kāraṇam. kilode ti gbogbo iyato yi wa..., kāraṇaṁ guṇa-saṅgo 'sya. Asya, jīvasya. Osini asepo pelu orisirisi amuye aye yi, nitorina lose ni orisirisi ara. Kāraṇaṁ guṇa-saṅgo 'sya.

Nitorina awa o gbudo ni asepo pelu awon amuye aye yi. titi de inu rere. itumo inurere ni awon amuye awon brahmana. Sattva śama damas titikṣā. Ise ifarafun oluwa si gaju gbogo awon amuye yi lo. teyan ba ni ibimo ninu ebi awon brahmana tabi ton sise bi brahmana, osi wa labe ofin ile-aye yi. kilale sofun awon eyan tio ni inu rere, tonni nítara; tabi aimokan. ipo wan losi kere ju. Jaghanya-guṇa-vṛtti-sthā adho gacchanti tāmasāḥ: (BG 14.18) awon eyan ton wa ninu ipo aimokan na, ipo to kere ju lon wa. ni asiko tawayi... śūdra lonje. Kalau śūdra-sambhavaḥ. Ninu asiko Kali tawayi, gbogbo eyan lonwa ninu ipo aimokan. Śūdra. Awon eyan yi o mo nitoripe.. awon eyan ton mowipe " Emi nimoje; ara mi ko nimi. brāhmaṇa ni eyan bayi. awon eyan tiomo śūdra, kṛpaṇa loje. Etad vidita prāye sa brāhmaṇa. Gbogbo eyan loma ku, sugbon eni toba ku tosi mo nipa otito yi... gege bi awon akeko wanyi ton ko lati mo nipa aye mimo, toba le mowipe emi loun je, bakanna tabi keji eni na ledi brāhmaṇa. oledi brāhmaṇa. Etad vidita. enitio ba mo, kṛpaṇa loje. alaun ni itumo kṛpaṇa. Inurere ni itumo Brahmana. oro sastra leleyi. agbudo di brahmana kato di Vaisnava. Brāhmaṇa mowipe " emini moje" ahaṁ brahmāsmi. Brahma jānāti iti brāhmaṇa. Brahma-bhūtaḥ prasannātmā (BG 18.54). pelu iru imoye bayi eyan ledi prasannātmā. Eyan ani ifokan bale... teyan ba gberu sori, tabsi yoookuro, lesekese lomani ifokanbale, gege na ironu wipe " arami nimo je" eru to pogan lori wa. teba si gbe eru yi sile, ema ni ifokan bale. Brahma-bhūtaḥ prasannātmā (BG 18.54). Itumo re niwipe agbudo mowipe " moyato s'ara mi, emi nimo je" lehin na ogbudo sise gan lati le toju ara re, tobaya asi ronu "kilode ti mo sen sise gan fun awon nkan kekere wanyi? Eje kin sise toye kinse". Ifokonbale to gaju niyen. Ifokonbale to gaju niyen. Brahma-bhūtaḥ prasannātmā na śocati na kāṅkṣati (BG 18.54). itumo ifokanbale yi niwipe tosejo ibanuje mo, tabi isoro. brahma-bhūtaḥ niyen.