YO/Prabhupada 0523 - Avatara Means who Comes from a Higher Sphere, Higher Planet



Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

Madhudviṣa: Prabhupāda, kini iyato laarin avatara ati awon eda pelu orisirisi irisi?

Prabhupāda: Nkankanna ni wan pelu Avatāra. ninu iwe itumo yin, wanso wipe " .... Sugbon orisirisi avatara lo wa. Eni ton wa ni itumo avatara.. avatarana ni oro na je, to sokale wa. Enito wa lati aye to gaju tawa lo itumo Avatara niyen. lati aye yi ko lonti wa Lati ijoba orun lotin wa, avatara niwan. orisirisi avatara lowa śaktyāveśāvatāra, guṇāvatāra, līlāvatāra, yugāvatāra, wansi po gan. eyan to wa lati ijoba orun ni itumo avatara. isotunmo to fun avatara ni eyan to wa lati aye toyato si tawa, sugbon nkan temi roniwipe itumo oro na ni onitoun to tun aye wa. Se beeko? gbogbo eyan loni ara lati ile-aye yi. awon avatara Visnu na wa, ati awon avatara awon elesin orisirisi avatara lo wa. Ele ka ninu iwe Akeko Oluwa Caitanya, nipa eyi to ma wa.