YO/Prabhupada 0530 - One Can be Out of Distress when he Approaches Vishnu



Radhastami, Srimati Radharani's Appearance Day -- London, August 29, 1971

Athāto brahma jijñāsā. Ile aye yi wa fun iwaadi nipa Brahman. Brahman, Paramātmā, Bhagavān. Awon iwaadi gbudo wa. Jijñāsu. Jijñāsu lon pe wan, brahma-jijñāsa, jijñāsu, iwaadi. basen bere lojojumo, " Kini iroyin towa leni?" lesekese lama mu iwe-iroyin. iwa iseebere wanbe. awa femo nipa awon nkan aye yi nikan. awon eyan o fe sewaadi nipa eto tose pataki ju, brahma-jnana. aini awujo aye isin niyen. wan sewaadi lati mo bonsele pa owo si: divā cārthehayā rājan kuṭumba-bharaṇena vā (SB 2.1.3). Ninu aye yi nikan ko.. Oti di eto tose pataki gan, sugbon ninu ile-aye yi, gbogbo eyan sise lati leni itelorun ara wan. Nidrayā hṛiyate naktam: wa sun lale, wan bere sini horun. tabi imo laarin ako ati abo. Nidrayā hṛiyate naktaṁ vyavāyena ca vā vayaḥ (SB 2.1.3). bonse lo asiko nilokulo niyen. ni oju ojo, divā cārthehayā rājan... tojo bade, " nibo ni owo na wa? nibo ni owo na wa? nibo ni owo na wa? Artha ihāya. Kuṭumba-bharaṇena vā. lesekese teyan bati lowo, base ran nkan fun awon ebi re, otan. ka ran nkan , ka toju e. Ise ile-aye yi niyen. laarin gbogbon eleyi, enikeni to ba logbon.. Manuṣyāṇāṁ sahasreṣu kaścid yatati siddhaye (BG 7.3). laarin gbogbo awon ode ton sun, ton ni imo laarin ako ati abo, ton pa owo, ton si seto ebi wan pelu ile at'ounje.... Ise ti gbogbo aye n'se niyen. Ninu gbogbo awon eyan bayi, ikan ninu wan asebeere bosele se ki aye re ni ilosiwaju. Manuṣyāṇāṁ sahasreṣu kaścid yatati siddhaye.

Siddhaye. pipe ni itumo Siddhi. Ilosiwaju ni'di fun ile-aye yi. Kini itumo Ilosiwaju yi? Itumo ilosiwaju yi niwipe awa o si jabo sinu ipo aye tioda, asi fe jade kuro ni eyi tawayi. Ilosiwaju niyen. Gbogbo wa lafe jade kuro ninu isoro aye tani. sugbon awon eyan yi o mo nipa ipo aye to daju. isoro aye: tri-tāpa-yantanaḥ. nkan ton pe ni mukti niyen, tabi igbala,.. Ātyantika-duḥkha-nivṛttiḥ. Duḥkha, ibanuje ni itumo duḥkha gbogbo eyan lofe jade kuro ninu ibanuje aye yi. sugbon kinidi lati jadi ninu ibanuje yi, ko mo. Na te viduḥ. awon eyan i mo. Na te viduḥ svārtha-gatiṁ hi viṣṇum (SB 7.5.31). teyan ba sunmo Visnu nigbana lole jade kuro ninu ibanuje. Tad viṣṇuṁ paramaṁ padaṁ sada paśyanti sūrayaḥ. Tad viṣṇoḥ paramaṁ padam. PLanet Visnu.. gege bi ile-aye yi, gbogbo wan lon seto ati losi osupa, sugbon awon ode wanyi ole so nkan tofe lo se lori osupa. ikan ninu awon planeti ile-aye loje. Krsna ti salaaye ninu Bhagavad-gītā, abrahma-bhuvanāl lokān. kama wa soti osupa to sumon wa gan - teba losi planeti to gaju ton pe ni Brahmaloka.. eleyi si wani iwaju yi, lojojumo leyin man ri sugbon kosi besele losi be Eyin fe losi planeti to sumo ju. Sugbon ipadanu na niyen. Iru ilosiwaju sayensi wo lewa ni? sugbon o le sese. Ā-brahma-bhuvanāl lokān. Ele lo. Isiro awon oni sayensi niwipe teyan ba losiwaju, fun odun Oke-meji, pelu iyara ina, lehin na eyan le de planet ti to gaju ninu aye yi. nitorina pelu isiro awon oni sayensi kolese se. sugbon elelosi be teba fe: ilana konn wa. ati salaaye ninu iwe kekere wa Iri-ajo si awon planet imi. pelu agbara yoga eyan le losi be tobafe. losiwaju yoga niyen. ti yogi na ba ni ilosiwaju ninu yoga, o le losi ibikibi tabi planeti toba fe, lehin na asi tesiwaju, afi ti yogi na ba rowipe kosidi fun lati tesiwaju mo lati lo si planeti toba fe. Ilosiwaj adase yoga niyen ilosiwaju aye gidi niyen kon se awon sputnik yin ton fo l'ofurufu.. (Erin) awon eyan o mo bonsele yonju aye wan. Ele lo lati ibikibi toba wun yin