YO/Prabhupada 0535 - We Living Entities, We Never Die, Never Take Birth



Janmastami Lord Sri Krsna's Appearance Day Lecture -- London, August 21, 1973

Olori giga, eyin Okurin jeje ati Obirin, mosi dupe lowo gbogbo yin tewa si ayeye wayi, Janmastami, ijo ifaraha ti Krsna. Wansi ti sofu mi kin soro lori ifarahan Krsna. ninu Bhagavad-gita Krsna sowipe,

janma karma me divyaṁ
yo jānāti tattvataḥ
tyaktvā dehaṁ punar janma
naiti mām eti kaunteya
(BG 4.9)

otooro niwipe ale de ipo yi laye wa, nigbata le fiipari si ibimo ati iku.... Sa 'mṛtatvāya kalpate. Ni aro yi nimo salaaye itumo ese-iwe yi:

yaṁ hi na vyathayanty ete
puruṣaṁ puruṣarsabha
sama-duḥkha-sukhaṁ dhīraṁ
so 'mṛtatvāya kalpate
(BG 2.15)

Alainipari ni itumo Amrtatva. Awon awujo wayi o mo, tabi awon alakowe, tabi awon oloselu tabi awon onisayensi, ale de ipo tojepe awon eyan ole ku mo. Amrtatva. amrta ni gbogbo je. Bhagavad-gita sowipe na jāyate na mrīyate vā kadācin. kosi bi awon eda sele ku tabi kon ni ibimo. Nityaḥ śāśvato yaṁ, na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). gbogbo wa laje awon eda ayeraye, nityaḥ śāśvato; Purāṇa, todagbaju. lehin igbati ara wa b apaari, awa o ni ku. Na hanyate. Ara yi titan, sugbon mogbudo gba ara imi. Tathā dehāntara prāptir dhīras tatra na muhyati. Dehino 'smin yathā dehe kaumāraṁ yauvanaṁ jarā (BG 2.13).

awon eyan o ni imoye, nkan to rorun ju nisin, pe, nkankanna laje pelu Krsna, ayeraye lam wa, gbogbo igba lani idunnu, asi logbon. Wanti juwe Krsna ninu awon sastra Veda:

īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ
sac-cid-ānanda-vigrahaḥ
anādir ādir govindaḥ
sarva-kāraṇa-kāraṇam
(Bs. 5.1)

Sac-cid-ānanda-vigrahaḥ. Olorun, Krsna tin ba sowipe Krsna, Oloruni nitumo re. ti oruko kankan bawa to se pataki... Nigbami awon eyan man sowipe Olorun o loruko. Otooro niyen. sugbon ise re ni oruko re tin wa. gege bi awa se gba Krsna bi omo-okurin Mahārāja Nanda, tabi Yasodamayi, Tabi Devaki tabi Vasudeva. Baba alakoko Krsna ni Vasudeva ati Dveaki. Koseni toje Baba tabi Iya fun Krsna nitoripe oun gan ni Baba gbogbo agbaye. Sugbon ti Krsna ban wa sinu aye yi, ole jeki awon elesin re se bi iya tabi baba fun. ādi-puruṣaṁ, t'alakoko ni Krsna. Ādyaṁ Purāṇa-puruṣam nava-yauvanaṁ ca (Bs. 5.33). Oun lo dagba ju. Se arugbo lowa je? Rara. Adyam purāṇa puruṣam nava-yauvanam ca. Nigbogbogba nígbà èwe re. Krsna niyen.