YO/Prabhupada 0536 - What is the Use of Studying Vedas if You do not Understand Krishna?



Janmastami Lord Sri Krsna's Appearance Day Lecture -- London, August 21, 1973

nigbati Krsna wa lori oju ogun Kurusetra, seti ri iworan na, gege bi okurin omo odun ogun, tabi omo odun merinlelogun. sugbon nigbana, oti ni awon omo omode na. Nitorina lon se sowipe nígbà èwe ni Krsna wa. Navayauvanam ca. Awon oro lati iwe Veda niyen.

advaitam acyutam anādiṁ ananta-rūpam
ādyaṁ purāṇa-puruṣaṁ nava-yauvanaṁ ca
vedeṣu durlābhaṁ adurlābhaṁ ātmā-bhaktau
(Bs. 5.33)

lati ni oye nipa Krsna, lawa sen ka awon iwe Veda, Oma soro gan lati ni oye nipa eni ti Krsna je. Vedesu durlābhaṁ gbogbo awon Veda lon wa fun lati monipa Krsna. Bhagavad-gita sowipe, vedaiś ca sarvair aham eva vedyo. Aham eva vedyo. kinidi pe eyin ka awon Veda teyin o ba monipa Krsna? nitoripe ipinnu fun gbogo eto-eko yini lati ni oye, nipa Olorun, baba wa togaju, orisun gbogbo nkan. wansi so fun wa ninu Vedānta-sūtra, janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Athāto brahma jijñāsā. Brahma-jijñāsā, lati soro nipa otito to gaju, Brahman. kinitumo Brahman? Janmādy asya yataḥ. ibiti gbogbo nkan ti wa ni itumo Brahman. itumo sayensi ni lati waadi gbogbo nkan. awa timo lati awon sastra pe Krsna ni orisun gbogbo nkan. Sarva-kāraṇa-kāraṇam. Sarva-kāraṇa-kāraṇam.

īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ
sac-cid-ānanda-vigrahaḥ
anādir ādir govindaḥ
sarva-kāraṇa-kāraṇam
(Bs. 5.1)

orisun gbo nkan. Egbiyanju koye yin bayi. lati baba mi nimoti wa, lati baba re ni babatemi tiwa. lati baba re loun na ti wa... ele waadi titi lo bayi, lehin na ema de enito je orisun gbogbo eleyi. sugbon oun na oni orisun kankan. Anādir ādir govindaḥ (Bs. 5.1). emi ni idi fun omo mi, sugbon emi na ni ibajade baba mi. sugbon sastra sowipe anādir ādir, ounni orisun gbogbo nkan, sugbon koseni to mo eyan to da oun sile. Krsna niyen. nitorina Kṛṣṇa se sowipe janma karma ca me divyaṁ yo jānāti tattvataḥ (BG 4.9). Ojo ifarahan Krsna se pataki gan. Agbudo gbiyanju lati mo nipa Krsna, kilode tonse farahan. kilode tose wa sinu ile-aye yi, kini ise tonse, iru nkan wo lon se. tab gbiyanju lati monipa Krsna kini abajde na? abajade na ni tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti kaunteya (BG 4.9). eyin na madi alainipaari. Ipinnu aye yi ni basele di eyan tioni Ku. Amṛtatvāya kalpate.

ninu ojo ifaraan Krsna, agbudo gbiyanju lati mo nipa imoye Krsna. Olori giga wa si lori nipa alaafia. Krsna ti funwa ni itosoan fu alaafia. kini yen?

bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ
sarva-loka-maheśvaram
suhṛdaṁ sarva-bhūtānāṁ
jñātvā māṁ śāntim ṛcchati
(BG 5.29)

ti awon oloselu, ateyan pataki fe da alaafia sile ninu gbogbo agbaye... Awon Orile-ede apaapo,ati gbogbo awon egbe na ton fe ni alaafia gidi ati ifokanbale, laisi ija kankan laarin awon okurin tabi laarin awon orile-ede. Sugbon kosele. sugbon kosele. alebu to wa niwipe, alti ibere ni gbogbo nkan ti baje. gbogbo eyan ronu pe, ilumi leleyi, ebi leleyi. Awujo mi leleyi. ohun -ini mi leleyi." itanra-eni ni oro " temi".