YO/Prabhupada 0545 - Real Welfare Activity Means to See to the Interest of the Soul



His Divine Grace Srila Bhaktisiddhanta Sarasvati Gosvami Prabhupada's Appearance Day, Lecture -- Mayapur, February 21, 1976

Prabhupāda: nigbati Caitanya Mahāprabhu fe se para-upakāra...

bhārata bhūmite manuṣya-janma haila yāra
(manuṣya) janma sārthaka kari' kara para-upakāra
(CC Adi 9.41)

awon ise iranlowo wanyi, iranlowo fun ara wa ko fun emi wa loje, nkankanna ni Krsna si sofun Arjuna, Oyato s'ara yi, Emi loje" Antavanta ime dehaḥ nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ, na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Iranlowo to gaju ni besele se nkan fun emi wa. Kini nkan t'emi wa fe? anfanni emi ni wipe nkankanna loje pelu Krsna, Olorun. gege bi awon ina kekere to wa ninu in nal, gege na awon eda, asi kere gan, iwonba die lati Brahman to gaju lati wa, Para-brahman tabi Krsna gege bi awon ina kekere se rewa lati wo tonba wa ninu re, ina yi si rewa, beena ni ina kekere na si rewa, sugbon lesekese t'ina yen ba subu si ilele, otan niyen. ipo wa niwipe, ati jade kuro ninu ona yi, toje Krsna. Wansi ti salaaye pelu owe ninu ede Bengali:

kṛṣṇa bhūliyā jīva bhoga vāñchā kare
pasate māyā tāre jāpaṭiyā dhare

Aimokan nitumo Maya. apere yi si da gan. ijo awon ina kekere ati ina nla si da gaan, osi tana sugbon lesekese toba subu le ilele adi eeru, apaada si eeru, koni si ina mo. gege na, oye ka ma jo, ka sere, ka rin pelu Krsna. Ipo wa niyen. Vrndavana niyen. Gbogbo eyan loni nkan pelu Krsna. Nibe awon igi, awon ododo, omi, awon maalu, awon omo-maalu, awon omo-okurin. tabi awon agbalagba, Nanda Mahārāja, ati awon eyan pelu odun kanna bi ounna, Yasodamayi , awon mama, awon gopi - aye Vrndavan, Iworan Vrndavan niyen. Ti Krsna ba wole sinu iworan Vrndvan, asi fi aye Vrndavan fi han, cintāmaṇi-prakara-sadmasu, lati fi fawamora, " Eyin gbiyanju lati gbadu ninu aye yi, sugbon kosi besele gbadun nibi nitori pe, alainiopin leje. Kosi besle ni aye tiolopin nibi. Epada wa bami. . Wa bami". Tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti kaunteya (BG 4.9). Egbe imoye Krsna leleyi. (looto) Edakun esofun wan kon duro fun Prasadam. Tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti. ifiwepe niyen. Mām eti: " A pada losi ijoba Orun". gbobo itosona Bhagavad-gita niyen. nipaari osowipe sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). kilode teyin sen seto to po fun ile aye yo? Kolese se. Kolese se nibi. teba ni ara ninu abasepo yi, egbudo bo. Prakṛteḥ kriyamāṇāni... (BG 3.27). Prakṛti-stho. kini ese-iwe na? Puruṣaḥ prakṛti-stho 'pi...

Hṛdayānanda: Bhuñjate prakṛti-jān guṇān.

Prabhupāda: Ha. Bhuñjate prakṛti-jān guṇān