YO/Prabhupada 0546 - Publish Books as Many as Possible and Distribute Throughout the Whole World



His Divine Grace Srila Bhaktisiddhanta Sarasvati Gosvami Prabhupada's Appearance Day, Lecture -- Mayapur, February 21, 1976

Prabhupāda: Bi eda ba wa ninu aye yi, ogbudo ni asepo pelu awon ipo aye yi. Apeere kanna. Ti ina kekere ba jabo si ilele. orisirisi ipo lon ni. ewe to gbe wa, ewe to si tutu wa, ilele lasan de wa. gege na ipo meta lowa laye: sattva-guṇa, rajo-guṇa, tamo-guṇa. itumo sattva-guna niwipe in yi jabo sori ewe to gbe, asi gbina ninu sattva-guṇa, prakāśa, wansi fi agbara ina fihan. sugbon toba jabo si ilele ina re ma ku tan. ipo meta niyen. Gege na tawa ba wa sinu aye yi, tani asepo pelu sattva-guna, ale sowipe anfanni die ma wa sugon ninu rajo-guna kosejo anfanni, beena ni tamo-guna. Rajas-tamah. Rajas-tamo-bhāva kāma-lobhādayaś ca ye. Rajas-tamaḥ. taba ni asepo pelu rajo guna ti tamo-guna, gbogbo anfanni lokan wa ati imotaraenikan. Kāma-lobhādayaś ca. Tato rajas-tamo-bhāva kāma-lobhādayaś ca taba si gbokan le sattva-guna, lehin na kāma-lobhādaya awon nkan meji wanyi o le summon wa mo. Ale jina si Kama-lohba wanti salaaye ninu Śrīmad-Bhāgavatam:

śṛṇvatāṁ sva-kathāḥ kṛṣṇaḥ
puṇya-śravaṇa-kīrtanaḥ
hṛdy antaḥ-stho hy abhadrāṇi
vidhunoti suhṛtsatām
(SB 1.2.17)

agbudo koja awon amuye meta wanyi:sattva-guṇa, rajo-guṇa, tamo-guṇa, nipataki rajo-guṇa, tamo-guṇa. teyin o ba gbiyanju bayi kole si afanni fun aye mimo, tabi igbala lati idimu ile-aye yi. sugbon ninu Kali yuga kosi sattva-guna to daju, rajo-guṇa, tamo-guṇa. nipataki tamo-guna. Jaghanya-guṇa-vṛtti-sthaḥ (BG 14.18). Kalau śūdra-sambhavaḥ. nitorina ni Śrī Caitanya Mahāprabhu sen ti egbe imoye Krsna Ekorin Hare Krsna mantra.

latibi ni Śrī Caitanya Mahāprabhu ti bere egbe wa yi, egbe imoye Krsna nigbogbo orile-ede India, osi fe ki pṛthivīte āche yata nagarādi grāma: awon ilu ati abule to wa si po gan, egbudo ti egbe yi siwaju.(CB Antya-khaṇḍa 4.126) egbe imoye Krsna yi wa lowo yin. ni odun 1965 (1922), Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura, si fe kin sen nkan to jo nkan bayi. Osi fe ki gbogbo awon akeko re si se bayi. nipataki osi sofun mi " Se bayi" Ounkoun toti ko, tunso dada ni ede geesi". ni odun 1933, nigbato wa ni Rādhā-kunḍa, nigbana mowa ni ilu Bombay nitori ise. Mosi wa ri, osi ni oremi kan to si fe fun wan ni ile kan ni Bombay, lati bere Gauḍīya Maṭha ni Bombay. Oremi loje. iroyin to gun gan ni, sugbonn mofe sofun yin, ise apifunni ti Bhaktisiddhānta Sarasvatī Gosvāmī' nigbana oni ikan ninu awan arakurin ninu ise olorun to si wanbe Osi ranmi leti nipa iranlowo toremi fe funwan, lesekese ni Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura Prabhupāda gba ile na osi sowipe " kosi idi lati da ile-olorun to po sile. Kada bee ka te awon iwe jade" Nkan to so niyen. Osowipe abeere Gauḍīya Maṭha ni Ultadanga. owo-ile tansan si kere gan, taba si le ri 2- 250 rupees, osi da gaan funwa. sugbon latigbati J.V. Dattati fun wa ni awon okuta didan wanyi ija laarin awon akeko mi tin posi, mio femo. Otemi lorun tinba le tewe jade, inumi adun gan taba ta awon okuta didan wanyi latifi tewe jade" mosi feti kan to so ye, osi funmi ni imoran toba lowo " tewe jade" pelu ibukun re ati ise asepo gbogbo yin ati ni ilosiwaju. wantin ta awon iwe wa ni gbogbo agbaye, oden ta dada. ni eni ojo ifarahan Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura mosi gbiyanju lati ranti awon oro to so; iyeniwipe ofe kin tewe to po gan jade fun awon eyan nipa imoye wa, ni ede geesi fun awon eyan to mo geesi ka, nitoripe ede-geesi tigba gbogbo agbaye. Awa si se iri-ajo ninu gbogbo agbaye yi Ibikibi taba so ede geesi awon eyan mo, afi awon ilue die. ni eni ojo ifarahan Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura mosi fe bere lowo awon akeko mi pe ejeka sise po, ka tewe to po jadekasi pin fun gbogbo aye. Eleyi ma fun Śrī Caitanya Mahāprabhu ati Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura ni idunnu. Ese pupo.

Elesin: Jaya Śrīla Prabhupāda.