YO/Prabhupada 0547 - I Thought 'I shall first of all become very rich man; then I shall preach'



Lecture -- New York, April 17, 1969

Prabhupada: se kosi?

Elesin: Jaya.

Prabhupāda: Hare Kṛṣṇa. (erin) Ārādhito yadi haris tapasā tataḥ kim (Nārada-pañcarātra). Hari ni Govindam ādi-puruṣa "enito le mu gbogbo ibanuje e lo" itumo Hari niyen Hari niyen. Hara. mu lo itumo Hara niyen. Harate. gege bi ole man mu nkan lo, sugbon amu nkan to se pataki ju lo, nigbami Krsna na le mu awon nkan tose pataki si wa lati fi ore-ofe re han wa. Yasyāham anugṛhṇāmi hariṣye tad-dhanaṁ śanaiḥ (SB 10.88.8). Yudhiṣṭhira Mahārāja bere lowo Krsna " eyan dada niwa. jagun jagun ton lagbara gan ni awon aburo mi, gege bi orisa owo ni iyawo mi se ri, lori gbogbo e, ore loje siwa. Kilode tojepe gbogbo nkan tani ti lo? ( Erin) Ijoba wa na ti lo, Iyawo wa ti lo, ola wa titan - gbogbo e ti lo." Krsna si dauun yasyāham anugṛhṇāmi hariṣye tad-dhanaṁ śanaiḥ: "Ore-ofe mi t'alalakoko niwipe magba gbogbo nkan ti awon elesin mi ba ni" nitorina ni awon o fe wa si imoye Krsna. Sugbon gege bi awon Pandava tonni isoro ni ibere, sugbon nigbato ya wandi awon eyan pataki ninu gbogbo itankale agbaye. Ore-ofe Krsna niyen. ni alakoko ole se bayi nitoripe asiferan awon nkan aye yi.

Ijerisi mi niyen. ni beere nigbati Guru Mahārāja ranmi, mosi rowipe " oyekin koko di olowo na, lehin na ni moma sewaasu" (Erin) Osini ise to da gan timon se nigbayen. Mosi ni oruko to da gaan gbogbo awon eyan tin bon ba sise, gbogbo wan loni itelorun pelu ise mi. Sugbon Krsna si da gbogbo ru. Osi se kin gba sannyasa. Hari niyen. mosi wa si ilu yin pelu Dollar 7 pere. awon soro nisi, " Swami yi wasibi laini owo kanna, nisin oti di olowo" (Erin) wan soro mi leyin, seti ri oda ju pe moti jeere to po mosi fi ile mi sile, pelu awon omode. Mosi wa sibi pelu dollar mesan pere, bi talaka. owo koniyen. Sugbon nisin motini ile to po gan ati awon to po si (erin) mio de ni lati ronu nipa bonsefe gbe, awon lon ronu nipami. ore-ofe Krsna niyen. Nibeere obabiwipe o koro. nigbati mo gba sannyasa eminikan nimon daagbe, inu si bimi gan nigbami matun ronu , " kilode timo gba kin yi"? Nijokan nigbati mon seto Back to Godhead lati Delhi, Ako-maalu kan si fori gba sile, mosubu silele mode sise gan. Eminikan mode wa. moden ronu, "kini gbogbo eleyi "? gbogbo awon ojo isoro timoni tele, wansi papa paari si nkan to da. ema beru awon isoro aye yi. seti ri ? Elosiwaju. Krsna ma so yin. Ijerisi Krsna niyen ninu Bhagavad-gita Kaunteya pratijānīhi na me bhaktaḥ praṇaśyati: (BG 9.31) Kaunteya, Omo Kunit, Arjuna, mofe ko sofun gbogbo agbaye awon elesin mi oni se aigbe. Sofun gbogbo eyan bayi" Kilode to sofun Arjuna pe ko soro? Kilode toje pe oun ko loso fun ara re? Itumo re niwipe, tobajepe oun lo se adehun yi, onigbatojepe ko le jerisi awon adehun to se sugbon ti elsin re ba e adehun, ogbudo pase si. Krsna ma so yin, nitorina lose so fun elesin re pe " soro". kole sejo pe kole jerisi tobaya. Krsna si dara gan to jepe nigbami kole jerisi nkan to so, sugbon ti awon elesin re ma se adehun, asi gbogbo tole se lati jeki adehun elesin re duro. Ore-ofe re niyen.