YO/Prabhupada 0549 - The Real Purpose of Yoga is to Control the Senses



Lecture on BG 2.62-72 -- Los Angeles, December 19, 1968

Tamāla Kṛṣṇa: ".lati iye ara, eyan na asi ni ifarafun won, lati ifarasi bayi, ifekufe ma jade, lati ifekufe yi ibinnu ma jade. (BG 2.62)" Akoonu: " Enikeni tio ba ni imoye Krsna mani awon ife okan aye yi toba tin ronu nipa awon ohun iye ara. Agbodo fun awon iye ara wa ni'se to daju, ti awon iye ara wanyi o ba nise ife okan s'Oluwa, won ma wa ise si awon nkan aye yi."

Prabhupada: Beeni. Asiri ilana yoga leleyi. Yoga indriya-saṁyama. àfojúsùn gidi ti yoga ni lati le ni idari lori awon iye-ara wa. Ise aye yi wa lati lo aawon iye ara yi ninu igbadun aye yi. Ise aye yi niyen. Itumo ilana yoga ni wipe agbodo ni idari lori iye ara wa kasi yo awon iye ara kuro ninu igbadun ile aye yi, tabi igbadu aye yi, ati inira, kasi yipada si Oluwa lokan wa Visnu. àfojúsùn gidi ti yoga niyen. Looto nibere awon ofin orisirisi lowa, awon ijoko, lati jeki okan wa bale. Sugbon ipaari gbogbo eto na koni yen je. Lati fi ipaari si awon idimu aye yi ati lati bere ise ninu eto mimo ni opin gbogbo e. Nibi won ti salaaye. Tesiwaju.

Tamāla Kṛṣṇa: " Ninu ile aye yi gbogbo eyan, Oluwa SIva ati Oluwa Brahma - kama soro nipa awon orisa toku ni awon isogbe orun - gbogbo won lon wa labe agbara ohun iye ara."

Prabhupada: Ohun elo iye ara, beeni.

Tamāla Kṛṣṇa: " Ohun elo iye ara. ona abayo kan soso tani lati jade kuro ninu igbese aye yi ni lati ni imoye Krsna."

Prabhupada: Awon iwe mimo Veda ti salaaye funwa wipe... Looto, won fi han wa pe, Oluwa Siva, Oluwa Brahma. Awon na si ferann ohun aye yi na. Gege bi Brahma, omo-obirin re Sarasvati... Sarasvati l'eda obirin to lewa ju, Sarasvati. Beena Brahma si bere sini ni ifarasi ewa omo-obirin re lati fi hon wa pe awon eda pataki bi Brahma na, awon na le ni ifarasi wanyi. māyā yi lagbara gan. O gbabe pe " Omo-obirin mi leleyi." lehin Brahma si gbawe, lati paaro ara toni. Awon itan wanyi wa ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Beena, Siva, nigbati Krsba farahan si ninu irisi Mohini-murti.... Mohinī-mūrti... Obirin pel'ara to lewa ju nitumo Mohinī. Siva na si ya were tele. Beena ibikibi to lo, Siva bere sini sa tele. Won sowipe nigbaton le Mohinī-mūrti, Siva sini ìdàsílè . Awon apeere wanyi wa nibe. Want salaaye ninu Bhagavad-gita, daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā duratyayā (BG 7.14). Agbara ile aye yi sin fa gbogbo wa sara lati ewa awon obirin. Looto, kosi ewa kankan. Itanraeni. Śaṅkarācārya sowipe " Eyin sa tele ewa yi, Sugbon seyin ti sewaadi s'ewa yi? Kini ewa yi?" Etad rakta-māṁsa-vikāram. Gege bi awon akeko wa, Govinda dāsī ati Nara-nārāyaṇa, tonsise pelu ohun èlò amö ti paris. Lasiko yi kosi ifarasi kankan. Sugbon awon ohun èlò amö paris yi tonba kun loda dada, osi lewa gan. Beena, ara wa si jo ipaapo eje ati isan ati ison eje. teyin ba ge idaji ara yi, ke wonu re, ema ri awon nkan iranu to po ninu e. sugbon nita agbara itanraeni maya ti kun loda to dara gan, osi lewa gan. nkan to fawa mora niyen. Idi fun idimu wa niyen.