YO/Prabhupada 0550 - Don't Run After this Mirage - Just Turn Back to Godhead



Lecture on BG 2.62-72 -- Los Angeles, December 19, 1968

Prabhupāda: Ewa aye yi tio daju ti di wa mu. ìÿìnàëtànìrújú. Apeere to daju ni ìÿìnàëtànìrújú. Kinitumo ìÿìnàëtànìrújú? Awojiji orun ninu ile-gbigbe si dabi omi. Nibo l'omi wa nibe. Kos'omi kankan. Eranko to'fun gbe sin sa tele ìÿìnàëtànìrújú yi. " Oh, omi wa nibi. Ma ri mu." Beena lawa sen sa teloe awon ìÿìnàëtànìrújú yi. kos'alafia kankan, kosi idunnu kankan. Nitorina agbdo yi okan wa pada s'Oluwa. Ema sa tele ìÿìnàëtànìrújú yi. E yipada s'Oluwa, pada si Krsna. Ise apinifunni wa niyen. Ema lo iye ara yin ninu ise ewa eke aye yi. E lo iye ara yin fun Krsna, ewa to daju. Imoye Krsna niyen. Tesiwaju.

Tamala Krsna: " Nigba Siva sin sasaro, sugbon nigbati Parvati to lewa gan si bere sini fowokan lati ni imo ako abo pelu re, osi gba lehin na lon bi Karttikeya."

Prabhupada: Oh, oun re Karttikeya ti jade ( erin) Beeni. Hare Krsna. Tesiwaju ( erin)

Tamala Krsna: Nigbati obirin toje Mayadevi fun ara re wa ba Haridasa Thakura toje olufokansi ewe t'Oluwa ."

Prabhupada: Nisin iyato towa leleyi. Siva oun ni orisa to lagbara ju. sugbon Parvati si poo lokan, lehin na lon bi Karttikeya. Nkan tonpe ni rikisi awon orisa niyen, pe afi ti omo-okurin kan bajade lati ato-omo Siva, kosi bonsele ni idari lori awon esu. Beena Karttikeya ni olórí egbêögáköögágunbalógun fun awon orisa. sugbon nibi, apeere imi. Haridasa Thakura. Omo-okurin merinlelogun ni Haridasa Thakur je, osin korin Hare Krsna, sugbon onile abule na, sini itara to po fun Haridasa Thakura. Osi wa asewo kan lati lo dan wo. Beena asewo na si gba lati lo ba laale, pelu aso to lewa gan, obirin na si wa lasiko ewe re, osi wa lati sun pelu Haridasa Thakura. Sugbon ko joo loju. Iyato to wa niyen. Enito ba ni imoye Krsna, tobatie je eyan lasan, tio si lori ipo Siva tabi Brahma, maya o leni idari lori e. Sugbon eni tio ba wa dada niu imoye Krsna, bobatie je Siva tabi Brahma, maya ma ni idari lori re, kama wa soti awon iyoku. Ipo to wa niyen. tesiwaju. " Nigbati Haridasa Thakura toje olufokansi Oluwa, lasiko ewe re

Tamala Krsna: ".... Mayadevi si wa lati danwo, sugbon Haridasa si koja idanwo yi nitoripe oni ife tiosikeji fun Oluwa Krsna. Olufokansi to daju si mo lati ni ikorira si awon igbadun aye yi nitori igbadun to daju to ni fun awon nkan mimo ninu asepo re pel'Oluwa. Asiri aseyori leleyi."