YO/Prabhupada 0554 - In the Midst of the Pacific Ocean of this Mayika World



Lecture on BG 2.62-72 -- Los Angeles, December 19, 1968

Tamāla Kṛṣṇa: 67 " gege bi ategun to lagbara le gbe oko omi lo, beena ikan ninu awon iye ara eyan le mu ogbon ori re lo."

Prabhupāda:Beeni. kasowipe eyin wa lori omi okun Pacific ninu oko omi lori aga too da, sugbon eyin o mo oko omi na wa, ìrúmiìgbì omiìbilù-omi kan soso lati omi oku pacific le muyin losabe omi okun na. Beena nkan tafe niyen. Awa laaarin omi okun Pacific ti ile aye mayika yi. Saṁsāra-samudra. Nkan ton pe ni samudra niyen. Beena leyikeyi asiko oko wa le takiti t'awa o ba le ni idari lori e. Beeni.

Tamāla Kṛṣṇa: 68: "Nitorina, Alagbara, eni ti iye ara re o si lori ohun elo re, ogbon eyan bayi daju."

Prabhupāda: Beeni. Nisin, enikeni toba ni idari lori iye ara re.... lati ni idari lori iye ara wa nidi fun ile aye yi. Tapaḥ. Nkan ton pe ni tapasya niyen, awe gbigba pelu inira. kasowipe igbadun kan ti momi lara. Nisin, Moti gba imoye Krsna. Oluko mimo ti sowipe, " Mase mo." Beena ni alakoko, inira die le wa, sugobn teba faramo , tapasya leleyi. tapasya leleyi. Itumo Tapasya niwipe inira yi le wan'be sugbon masi faramo. Nkan ton pe ni tapasya niyen. Ati ile aye eda yi wa fun tapasya. Konse pe nitoripe iye ara mi sin bere fun igbadun mo gbodo fun lesekese. Rara. Mo gbodo ko ara mi lona to jepe ti awo iye ara mi ba bere, " E dakun sa, e jekin gbadun die," Mole sowipe " Rara, kolese se." Nkan ton pe ni gosvami tabi svami niyen. Lasiko tawayi, eyin ma di olori iye ara yin nigba teyin ba ni idari lori iye ara yin, lehin na lema di svami tabi gosvami. Itumo svami ati gosvami niyen. Kon se aso teyin wo. Eni to lagbara lati ni idari, eni ti iye ara re o le so nkan to ma se fun, eni tio kin se oniranse iye ara re. Ahin mi sin sofun mi , " E dakun mumi losi ile-ounje kin jeran." Kini eran dindin? eran dindin?

Olufokansi: Adiye dindin.

Prabhupada: Adiye ton din? bawo lonse ko sile?

Olufokansi: S-t-e-a-k.

Prabhupada: Beena... tabi adiye dindin yi. Beeni. Ahin re sin sofun mi. sugbon eyin le ni idari lori ahom, " Rara. Ma fun e ni adun. Malo sibe." (Erin) Lehin na eyin ma di oga iye ara yi. Se ti ri bayi? Awon iyoku won sowipe " Ma losibe" Nikan. Kolese se. Ahon gbodo towo nkan to rewa. Bibeko kolese se. Nkan eke niyen. Sugbon teyin ba fun ni nkan to da ju adiye dindin yi, o si paari. Boseje niyen. ilana eto wa niyen. Ale fun won ni iresi. Osi da gan. A gbagbe eran jije. Beena ilana eto wa niyen, imoye Krsna. Agbodo fun gbogbo iye ara wa ni nkan. Konsepe ka fi ipaari eke si. Kolese se bayi. kolese se. Awon elomi won gbiyanju lati fi ipaari si ise iye ara wa. Rara. Kolese se.