YO/Prabhupada 0560 - Unless One Is Accepting Moral Character, We Don't Initiate



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Akorohin... Cosmi Star ati yi oruko January pada, ni iwe iroyin talakoko. Iwe iroyin talakoko, ti jade,oma wa lati oni'tewe leni.

Prabhupāda: se won se itejade ni gbogbo osu?

Akorohin: L'ososu, nkan to daju niyen, o dabee. asin soro nipa awon esin lati awon ilu asia. A se iroyin die losu yi nipa Alufaa James Pike, UFOs, ìtòràwọ̀. Se mo nipa Dr. Bode, Frambose Bode lati .. O wa pelu Manley Hall. Semo Manley Hall?

Prabhupada: Rara.

Akorohin: Seyin o mo Frambose Bode?

Prabhupada: Rara.

Akorohin: Lati India loti wa. Parsee.

Prabhupada: Oh oye mi . Parsee, beeni.

Akorohin: Oma se iwe oriyin imi funwa l'osu to kan. Sugbon mo soro pelu Dan mosi sofun nipa awon nkan ti mofe bi yin, mosi rowipe opolopo ninu awon ton ka iwe iroyin wa, ati opolopo awon eyan ninu America won n i idamu to po laarin gbogbo awon eyan ton pe ara won ni avataras ton wa lati India si ilu wa, gbogbo won, lati ikan sikeji, wan sowipe..

Prabhupada: Mole sofun yin, oniranu ni gbogbo won.

Akoroyin: Sele salaaye die ori nkan teso yi.

Prabhupāda: Mole tunso pe, asiwere ni gbogbo won.

Akorohin: Fun apeere Maharishi....

Prabhupada: Oniranu talakoko niyen. Mti so tele nita.

Akoroyin: Sele salaaye die fun awon ton ka iwe iroyin wa, nitoripe..

Prabhupada: Mio mo sugbon lati iwa toni mo mope asiwere to gaju loje. Mio mo nipa re sugbon nkan tose... Sugbon nkan to yamilenu niwipe awon eyan ninu ilu geesi yi, oye kon ni ilosiwaju. Bawo loseje pe awon asiwere wanyi le tan wan je?

Akoroyin: Mo rope awon eyan le nigbagbo ninu nkan ton ba fe. O ni nkan ton wa, o de wa ...

Prabhupada: Beeni won fe nkan ofe. Asise won niyen.

Akorohin: Beeni.

Prabhupada: Nisin fun awon akeko wa, awa o funwon ni nkan ofe. Ipo talakoko wa ni iwa, iwa rere. Se ti ri bayi? Beena afi teyin ma gba iwa rere, awa o le fun yin ni itebomi, ema jeko wole sinu egbe wa. Sugbon Maharishi yi, " Oh, se ounkoun teba fe. E funmi ni dollar marundinlogoji masi funyin ni mantra." Se ri bayi. Beena awon eyan yi fe kan tan won je, nitorina awon ton tan awon eyan je ti wa. Awon eyan yi o fe se oun toma fun won ni inira, se ri bayi? Ounkoun Won lowo. Won rowipe " Mole sonwo," lesekse loma gba owo na.

Akoroyin: Orun lesekese.

Prabhupada: Beeni. Ipo won niyen. Gege bi awon eyan ton fe losi isogbe osupa. Moti fu won ni iwonba okan mi. Seti ri ninu iwe iroyin Los Angeles Times? Aye toni kere gan.

Akoroyin: Oh?

Prabhupada: Beeni. kilode? Kasowipe ninu orile-ede, eyin ni awon ofin fun isiwa. ninu isogbe yi, teyan ba wa, lai gba ofin isiwa yin, koseni tole wole. Bawo leyin se rowipe nin awon isogbe wanyi ti awon eyan ni ilosiwaju ju yin lo, orisa lon pe awon eda, won wa laaye fun odun egbaarun mewa, bawo leyin se rowipe ele losibe lesekese ele wole sinu isogbe osupa? wande ti bere sini ta iwe iwole. Seri ayi? Won rowipe nkan tonle fi sere leleyi.