YO/Prabhupada 0564 - I Say, 'Please obey God. Please try to love God.' That is My Mission



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Akoroyin: Mio sebeere wanyi latenu nikan. Edakun eje koyeyin. Kini yato laarin isotunmo yi si awon ofin mewa t'onigbagbo jew? Kini iyato to wa?

Prabhupada: Kosi iyato kankan.

Akoroyin: O daa. Tiba jebe kileyin ni lati fun awon eyan.... Nigbati mo sope eyin Mofe sowipe (kose gbo).

Prabhupada: Beeni, Beeni.

Akoroyin: Kileyin ni lati fun awon eyan to yato si si awon onigbagbo tabi Jew?

Prabhupada: Nitoripe, bimo se so tele koseni ton tele awon ofin Oluwa ni pipe. Moti wa sofun yin " E tele awon Ofin Olorun." Ise apinfunni timoni niyen.

Akoroyin: L'oro imi, " Eyin tele aown ofin wanyi."

Prabhupada: Beeni. Mio sowipe " Awon onigbagbo ewa ni Hindu tabi ewa bami." Mo kon sowipe " E tele awon ofin wanyi." Ase mi niyen. Mofe ke di onigbagbo to da. Ise apinfunni temi niyen. Mio sowipe " Oluwa o si nibi, Oluwa wa nibi," sugbon nkan ti mon so niwipe " E tele ofin Oluwa." Ise apinfunni temi niyen. Mio sowipe ewa sori ipo yi keba Krsna bi Oluwa, kodesi elomi. Rara. Mio sobe. Nkan ti mon so, " Edakun e gboran s'Oluwa. Edakun enife s'Oluwa." Ise apinfunni temi niyen.

Akoroyin: Sugbon lehin na..

Prabhupada: Mosin salaaye besele nife Oluwa. Ona to rorun, besele nife, teba gba.

Akoroyin: Seri ati pada sori eto yi...

Prabhupada: Beena seyin riwipe kosi'yato kankan

Akoroyin: Beeni, O yem. Ese pupo.

Prabhupada: Beeni. Eyin nigbagbo ninu Oluwa, Mosi nigbagbo ni Oluwa. Nkan timon so niwipe " E gbiyanju lati nife s'Oluwa."

Aoroyin: Mio ni idamu kankan. Nkan teyin so yemi...

Prabhupada: seyin ni idamu na?

Akoroyin: Rara, rara, Oyemi nkan teyin so. Nkan tio yemi ni... Emi nikan ko, ati awon ton ka iwe iroyin wa... Eje kin tun bere. eje kin biyin kobale ye emi gan. Mio fe foros'enu yin, sugbon eje kin salaaye bayi. Seyin sowipe ise apinfunni teyin ati ti awon Jew, onigbagbo, ati oni geesi nkankana loje, eje kin tun bere, kilode ti awon eyan ewe tabi gbogbo awon eyan o nife kankan, kilode ton sa tele esin ton wa lati ilu asia, ti ipinnu gbogbo e baje nkankana bi awon esin ni ilu geesi. Kilode ton sin lo ba awon elesin lati ilu yin toba je nkanna?

Prabhupada: Nitoripe awon onigbagbo yi o le ko won lona to daju. Mosin ko won ni ona to daju.

Akoroyin: L'ooro imi eyin ko won ni nkan terope ni ona to daju lojojumo, bonsele ni itelorun ninu emi won lojojumo.

Prabhupada: Beeni. Ife Olorun wa ninu Bibeli, tabi apa atijo ati Gita, iyen da bee. Sugbon won o koo won bonsele nife Olorun. Emi fe ko won bonsele nife Oluwa. Iyato to wa niyen. Nitorina ni awon eyan ewe se nifarasi.

Akoroyin: O da bee. Beena opin kanna lajoo ni. Ona lati de bee loyato.

Prabhupada: kon s'eto ona. Eyin o tele rara, ona gan wan'be. gege bi mo se so tele, ona yi ti wa, " Ema fiku pa" eyin sin fiku pa.

Akoroyin: O emi sugbon ooin kanna lowa. Opin teyin..

Prabhupada: Opin kanna loje.

Akoroyin: Nkankana loje, sugbon beyin se...

Prabhupada: Nkankana l'ona yi je, sugbon won o ko awon eyan binsele tele. Emi sin ko won bonsele tele lona to daju, ati bonsele se.