YO/Prabhupada 0577 - So-called Philosophers, Scientists, All of Them, Rascals, Fools - Reject



Lecture on BG 2.19 -- London, August 25, 1973

Bi Kṛṣṇa seje sac-cid-ānanda-vigrahaḥ (Bs. 5.1), Irisi re, irisi re to gaju, ara taye raye, to kun fun imoye, idunnu, beena lawa seje, Ni iwonba kekere, sugbon amuye kanna. Nitorina lonse sowipe, na jāyate. Isoro to wa niwipe awon awujo asiwere to wa leni kole ye won pe - fun tayeraye lawa, Moti bosinu ipo ibimo ati iku yi. Koleye awon asiwere wanyi. gbogbo awon oni sayensi, awon asiwere, ode. E tiwon segbe kan. E fi won sile lesekese Ise lile tonse yi. Nkankana: : nūnaṁ pramattaḥ kurute vikarma (SB 5.5.4). Gege bi ise were. Kini iyi ise ti were base? To ban sise lataaro d'aaale, mon'sise. Beena kileyin se? Were ni e. Opolo ori re ti fo, were. Beena kin iyi ise teyin se? Sugbon nkan ton sele niyen. Beena seyin le siro iyi ti egbe imoye Krsna yi ni. Ise ore-ofe to gaju fun awon eda eyan leleyi. Ode ati asiwere ni awon eyan wanyi, tio ni imoye kankan, nipa eni ton je, wansin sise lat'aro titi d'aale. Nitorina won ti sowipe, ketekete nitumo mūḍha. Mūḍha Ketekete yin ma sise laataro daale fun alaso fun ewe die. Ewe yi wa nibikibi, sugbin asi rowipe " Ti mio ba sise fun alaso yi, kin sise gan, mio ni ri ewe yi gba." Ketekete niyen. Nitorina lehin igba teyan ba logbon leyin igba toba ti ni impye.... Eyan ma logbon. NI alakoko brahamacari. Lehin na teyan o ba le duru sinu ipo brahmacari, o da, ko fe yawo, grhastha. Lehin na ko fisile, vanaprastha. Lehin na ko gba sannyasa. Ilana to wa niyen. Awon mudhga wonyi ma sise lataaro dale lati gbadun iye ara won. Nitorina, lehin igba die oye kon fi iwa didinrin yi sile kon gba sannyasa. Rara. Otan. Sannyasa niyen. Nisin ipo aye yi wa fun ise fun Krsna nikan. sannyasa gidi niyen. Anāśritaḥ karma-phalaṁ kāryaṁ karma karoti yaḥ (BG 6.1). Ise mi ni lati sise fun Krsna. Oni ranse re nimi.. Kāryam. Mo gbodo se, mogbodo sise fun Krsna. Ipo aye mi niyen. sannyasa niyen. Anāśritaḥ karma-phalaṁ kāryam karma karoti yaḥ. Awon karmi, won wa ijeere latii igbadun ara won. karmi niyen Ati sannyasi itumo re ..... Awon na sin sise gan, sugbon konse fun igbadun ara won. fun igbadun Krsna. sannyasa niyen. sannyasa ati karmi niyen. Awon karmi na sin sise gan, sugbon gbogbo e wa fun āmiṣa-mada-sevā. Āmiṣa-mada-sevā. Vyavāya, fun imo ako ati abo, eran jije ati oti mimu. awon olufokansin na man sise gan, sugbon fun itelorun Krsna. Iyato to wa niyen. tein ba sise fun Krsna lai sise fun igbadun ara yin, lehin na ele bosi ipo, na jāyate, kosi iku mo, kosi ibimo mo. Nitoripe na jayate ni ipo aye yin.... Sugbon nitoripe eyin ni aimokan, pramattah, eyin ti ya were, eti ya were; nitorina eyin ti gba ilana igbadun iye ara. Nitorina, eti daapo ninu ara eda yi, ara na sin yipo. Nkan ton pe ni ibimo ati iku niyen.