YO/Prabhupada 0581 - If You Engage in the Service of Kṛṣṇa, You'll Find New Encouragement



Lecture on BG 2.21-22 -- London, August 26, 1973

Yan maithunādi gṛhamedhi sukhaṁ hi tuccham (SB 7.9.45). Beena imo ako ati abo nitumo ile aye yi. Nkan ewo, tuccham. Enikeni toba ti ni oye nipa oro yi, lehin na oti nigbala. Sugbon teyan basi ni ifarasi, oye koye wa pe idaduro ma wa ninu igbala aye re. teyan ba ni oye na, ninu ara eda yi gan eyan bayi tini igbala. Won pe ni jīvan-muktaḥ sa ucyate.

īhā yasya harer dāsye
karmaṇā manasā girā
nikhilāsv apy avasthāsu
jīvan-muktaḥ sa ucyate

Beena bawo lasele bolowo awon ife okan wanyi? Īhā yasya harer dāsye, teyin bafe sise fun Krsna, lehin na ele jade. Bibeko, kolese se. Teyin ba fe nkan imi ju ise fun Oluwa lo, Lehin na maya ma fa okan yin, " kilode teyin o fe gbadun nkan bayi?" Nitorina Yāmunācārya sowipe,

yad-avadhi mama cetaḥ kṛṣṇa-padāravinde
nava-nava-rasa-dhāmany udyataṁ rantum āsīt
tad-avadhi bata nārī-saṅgame smaryamāne
bhavati mukha-vikāraḥ suṣṭhu niṣṭhīvanaṁ ca

"Yad-avadhi, latii'gba, mama cetah, moti fi aye at'emi mi, at'imoye mi, ninu ise ese Krsna..." Yāmunācārya lo salaaye nipa ese-iwe yi. Oba pataki loje, awon oba si feran igbadun, sugbon osi di olufokansi mimo. Beena ijeerisi re, o sowipe " lati gbati moti fi okan mi ninu ise ese bi ododo Krsna, yad-avadhi mama cetaḥ kṛṣṇa-padāravinde..." Nava-nava. Itumo ise mimo niwipe nigbogbo'gba lo dabi tuntun. Kole darugbo. Awon eyan ton ni imoye mimo yi, wan ma sise fun Krsna itumo re ni ilaju tuntun, ilaju tuntun. Nava-nava-rasa-dhāmany udyataṁ rantum āsīt. Nibi, ninu ile aye yi, ele gbadun, lehin igba die o ma gbo. Punaḥ punaś carvita; nitorina ibanuje ma mu yin. Sugbon teyin ba wa ninu ise Krsna, Eyin ma ri awon iwuri tuntun. Mimo niyen. Teba riwipe on gbo, lehin na egbodo mowipe eyin sin sise lori ipo aye yi, eyin o ti bere sini sise lori ipo mimo. sugbon teyin ba ni agbara tuntun, lehin na o ye koye yin pe eyin sise lori ipo mimo. Idanwo towa niyen. Ifarasi teni ma posi, koni dinku.