YO/Prabhupada 0590 - Purification means One Must Know that 'I am Not This Body, I am Spirit Soul'



Lecture on BG 2.20 -- Hyderabad, November 25, 1972

Beena āruhya kṛcchreṇa paraṁ padaṁ tataḥ patanty adhaḥ (SB 10.2.32). Beena fun igbadun yi lawan se gbogbo eto wanyi. pelu opolo kekere tawa ni asin'se gbogbo awon eto wanyi. Gege bi ijoba sen seto na. Awon eyan, awon onitaju, gbogbo eyan lon seto nkan tabi keji. Idimu nitumo gbogbo eto wanyi. won gbodo pada si aye yi lati jeki eto yi jeere. Vāsanā. Nkan tonpe ni Vāsanā niyen. Beena agbodo ya Vāsanā yi si mimo, ife okan. Nkan tafe niyen. T'awa o ba yasi mimo, lehin na agbodo ni ibimo, ibimo ati iku, iyika ninu ibimo ati iku. Beena ife okan yi, bawo lase le yasi mimo? Awa le ya ife oakn na si mimo. Sarvopādhi-vinirmuktaṁ tat-paratvena nirmalam (CC Madhya 19.170). Agbodo fi gbogbo yiyan wanyi sile, " brahmana nimi," " sudra nimi," " ksatriya nimi," " Olugbe America nimi," " olugbe India nimi,"... awon yiyan to po gan bayi. Nitoripe emi nimi, sugbon idaboo yi ni yiyan timoni. Beena tinba ni idanimo pelu ara yi, lehin na mo gbodo ni iyika ninu ibimo ati iku yi. Ele ya si mimo. Bawo lesele ya si mimo? Ele yasi mimo pelu ise ifarasi fun Oluwa. Nigbateyin ba ni oye wipe nkankana leje pelu Krsna, nigbatin ba ni oye wipe " Moni asepo taye raye pelu Krsna. Oun ni eledumare, emi ni oniranse," Tinba si sise fun, iyasimo ife okan wa niyen. Laisi iloye Krsna yi, gbogbo wa kan sise lori ipo aye yi. " Olugbe America nimi. Nitorina mo gbodo sise bayi. Mogbodo ba awon olugbe Russia ja." Awon olugbe Russia na won rowipe " Olugbe Russia nimi, mogbodo ba awon olugbe America ja." tabi China... ipo orisirisi. Nkan ton pe ni māyā, itanraeni.

Beena agbodo yasi mimo. Iyasi mimo yi niwipe eyan gbodo mowipe " ara mi konimi. Emi nimi." Beena kini monse bi emi? Ounkoun ti mon se lasiko yi, lori ipo ara eda... Sugbon ise wo nimon se bi emi? imoye tafe leleyi. Tabati yasi mimo ni awon imoye yi mawa.

brahma-bhūtaḥ prasannātmā
na śocati na kāṅkṣati
samaḥ sarveṣu bhūteṣu
mad-bhaktiṁ labhate parām
(BG 18.54)

Mad-bhaktiṁ labhate parām.Nigbawo? Leyin igba teyin ba ni igbala lowo awon nakn aye yi, brahma-bhūtaḥ. Leyin igba teyin ba nigbala, kole siwaju re. Beena bhakti o kin se nkan tan fori da. " Awon eyan tio keeko, kosibon sele keeko nipa iwe mimo Veda dada, beena wonle gba ona bhakti." Rara. Bhakti, bhakti to daju lehin igba teyan ba tide ipo brahma-bhutah lole wa.

brahma-bhūtaḥ prasannātmā
na śocati na kāṅkṣati
samaḥ sarveṣu bhūteṣu
mad-bhaktiṁ labhate parām
(BG 18.54)

Ipo to gaju ninu ise ifarasi Oluwa niyen, Leyin igba taba ti bo lowo awon ipo aye yi. Sarvopādhi-vinirmuktaṁ tat-paratvena nirmalam (CC Madhya 19.170). Nkan ton pe ni nirmala niyen. Mukti niyen. Nitoripe tayeraye ni emi wa, wa fun. Agbdo fo awon idoti iole aye yi kuro. Beena toba ti mo, lehin na hṛṣīkeṇa hṛṣīkeśa-sevanaṁ bhaktir ucyate (CC Madhya 19.170). Ti awon iye ara wa bati mo...Konse owo olugbe America tabi owo olugbe India. " Owo Krsna leleyi. Agbodo lo owo na ninu ise Krsna, lati gbale ninu ile-ajosin." toba ronu bayi, o gaju awon Vedantist lo. Toba mowipe " Krsna loni owow yi," beena o gaju awon Vedantist lo. Looto gbogbo awon olufokansi Vedantist na niwon. Sugbon awon elomi rowipe awon nikan lonje Vedanta. Imoye nitumo Veda. to gaju nitumo Anta. Beena Imoye to gaju nitumo Vedanta. Beena Krsna ni imoye to gaju. Vedaiś ca sarvair aham eva vedyaḥ (BG 15.15). Beena awon Vedantist wanyi, ti kobale ni oye nipa eni ti Krsna je, kinitumo Vedantist to je? Kositunmo kankan. Vedantist pipe loje toba mowipe " Krsna ni eda to gaju. Oluwa mi loje. Iranse tayeraye re nimi." Imoye Vedanta leleyi.

Ese pupo. Hare Krsna.