YO/Prabhupada 0593 - As Soon as You Come to Krsna Consciousness, You become Joyful



Lecture on BG 2.20 -- Hyderabad, November 25, 1972

nkankana laje pelu Krsna, mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7). Beena ibasepo wa tayeraye. Nisin awa ti gbagbe. Awa sin rowipe " Krsna ko nimi, Olugbe America nimi, olugbe India nimi. Itanraeni wa leleyi. Beena pelu ona to daju... igboran l'ona yi. Kasi korin si leti pe " Olugbe America ko nie . Ti Krsna ni e. Olugbe America koni e." " Olugbe India koni e, ti Krsna loje." bayi to ba gbo dada, o le bere sinu ronu " Oh, beeni, ti Krsna nimi." Ona to wa leleyi. Agbodo tenumo nigbogbo'gba: Olugbe America ko ni e. Olugbe India koleje. Olugbe Russia ko leje. Ti Krsna niyin. Ti Krsna niyin." Lehin na gbogbo awon mantra yi le niyin, " Oh, beeni, ti Krsna nimi." Brahma-bhūtaḥ prasa... "Kilode ti mo sen rowipe olugbe Russia tabi America nimi?" Brahma-bhūtaḥ prasannātmā na śocati na kāṅkṣati (BG 18.54). Lesekese teyin ba wa sori ipo yi, koni si ibanuje mo Nibi, Olugbe America tabi India tabi Russi, awa si ni awon nkan meji: ekun sisun ati ibanuje. gbogbo eyan lon ni isoro, kini nkan ti mio ni: " Mo gbodo ni." Ounkoun toba ni, toba ti sonu, asi sukun. " Oh, O ti sonu." Beena awon ise mejeji wanyi. Beena teyin o ba wa si imoye Krsna yi, awon ise mejeji wanyi ma tesiwaju, ekun sisun ati isoro. lesekese teyin ba wa si imoye Krsna, eyin ma ni idunnu. Kosidi fun ekun sisun. Kosidi fun ibanuje yi. Gbogbo nkan wa ni pipe. Krsna wa ni pipe. Beena asi ni igbala. brahma-bhūtaḥ leleyi. Beena ale jisoke pelu igboran. Nitorina lonsepe awon mantra Veda yi ni sruti. Eyan gbodo ji imoye yi soke lati igboran. Śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ (SB 7.5.23). Nigbogbo'gba eyan gbodo gbo kosi korin nipa Visnu. Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare/ Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare. Lehin na ceto-darpaṇa-mārjanam (CC Antya 20.12), gbogbo nkan ma ya si mimo, asi wa lati ni oye pe " " Oniranse tayeraye Krsna nimi." ( isinmi)

Teyin bani Vaisnava, pelu brahmana na. Afi teyan o ba wa sori ipo sattva-guna, kole ni imoye Krsna. Ofin to wa niyen. Sugbon ise ifarafun si Krsna yi, egbe imoye Krsna yi si da gan pe teyin ba gbo nipa Krsna, eyin le wa sori ipo brahmana. Naṣṭa-prāyeṣu abhadreṣu nityaṁ bhāgavata-sevayā (SB 1.2.18). Abhadra. Awon amuye meta ile aye nitumo Abhadra. Ati awon amuye brahmana Amuye sudra, amuye vaisya, tabi amuye ksatriya, tabi amuye brahmana. abhadra ni gbogbo eleyi. Nitoripe ninu amuye brahmana, idanimo yi na si wa. " Oh, brahmana nimi. Koseni tole di brahmana lai ni ibimo. Alagbara nimi. brahmana nimi." Igberaga yi ma wa. Beena oti ni idimu. Ninu amuye brahmana na Sugbon nigbato wa sori ipo mimo yi, Caitanya Mahāprabhu sowipe, " brahmana ko nimi, sannyasi ko nimi, grhastha ko nimi, brahmacari ko nimi." Awon ofin mejo wanyi, varṇāśrama, oti jiyan. Lehin kileyin je? Gopī-bhartuḥ pada-kamalayor dāsa-dāsānudāsaḥ (CC Madhya 13.80). " Oniranse awon oniranse ti Krsna leleyi." Imoara eni leleyi.