YO/Prabhupada 0598 - We cannot Understand How Great God is. That is our Folly



Lecture on BG 2.23 -- Hyderabad, November 27, 1972

Beena, oro to keyin ninu otito to gaju , l'eyan Sugbon awon eyan tonj mudha tabi awon eyan tio logbon, avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritam (BG 9.11), "Oh Krsna? Odabi wipe Oluwa loje, sugbon oti deyan to wa labe māyā." Imoye Māyāvāda niyen. Won kawe nipa Māyā; won si fi Oluwa na sinu maya. Imoye Māyāvāda leleyi. Sugbon Oluwa yato si Māyā. Kosi bi Māyā se fe ni idaboo lori Oluwa. Kṛṣṇa sowipe mām eva ye prapadyante māyām etāṁ taranti te: (BG 7.14) " Enikeni toba teriba funmi, aasi ni igbala lowo idinmu maya." Bawo ni Krsna se fe waninu maya? Imoye tio da leleyi. Teyan ba teriba fun Krsns, eyin le ni igbala lowo maya. Bawo leda, eda to gaju, Krsna,sefe wa ninu maya? Nitorina Kṛṣṇa sowipe, avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritam, paraṁ bhāvam ajānantaḥ (BG 9.11). Awon eyan yi o mo nipa agbara Oluwa, bose lagbara to. Won fi agbara Oluwa yi fi we agbara ara won. Imoye awon opolo. Dokita. Opolo sin rowipe, " Omi Okun Atloanti si tobi ju omi konga." Nitoripe o wa ninu e nigbogbo'gba. Kūpa-maṇḍūka-nyāya loje, ninu ede Sanskrit lonpe ni kūpa-maṇḍūka-nyāya. kanga nitumo Kūpa, ati opolo nitumo maṇḍūka. opolo yi wa ninu konga nigbogbo'gba, teyan ba wa sofun pe omi to tobii ju konga re wa nibomi. Omi okun Atlantic, Asi bere sini siro pe " iwonba die lofi tobi ju omi konga re." Sugbon kole ye bi omi okun yi se tobi to. Beena alagbara l'Oluwa. Awa o le mo bose lagbara to" Iwa didinrin wa niyen. Awa kan siro: " O le fi die fu ju mi lo. Tabi iwonba die fi lagbara ju mi." Irori wa niyen. Nitorina Kṛṣṇa sowipe, manuṣyāṇāṁ sahasreṣu kaścid yatati siddhaye: (BG 7.3) " Ninu aimoye aown eda, enikan le gbiyanju lati jeki ile aye re ni aseyori, lati ni oye nipa otito to gau." Ati yatatām api siddhānāṁ kaścin māṁ vetti tattvataḥ (BG 7.3).

Beena awa o le ni oye nipa Oluwa pelu iro ri wa. kodesi basefe ni oye nipa bi emi wa se tobito. Kolese se. Nitorina agbodo gba iroyin yi lati awon olori to gaju, nipa iru iwa wo l'Olorun ni, kini iwa otito to gaju yi, kini wa emi wa. Agbodo gbo. Agbod gbo. Nitorin lonsen pe awon Veda ni sruti. Eyin o le sewaadi. Kolese se. Sugbon, oni awon eyna ton rowipe won le sewaadi lati mo nipa eda to gaju pelu irori ori. Brahma-saṁhitā sowipe:

panthās tu koṭi-śata-vatsara-sampragamyo
vāyor athāpi manaso muni-puṅgavānām
so 'py asti yat prapada-sīmny avicintya-tattve
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi
(Bs. 5.34)

Panthās tu koṭi-śata-vatsara-sampragamyaḥ. Fun aimoye odun, teyin ba ni ilosiwaju lori ofurufu lati sewaadi nipa Oluwa, nibi t'Oluwa wa... Panthās tu koṭi-śata-vatsara-sampragamyo vāyor athāpi. konse lorii awon oko afefe lasan, sugbon lori oko afefe ton se lat'ategun. tabi okan wa. Iyara okan wa sin lo kiakia. Lesekese, teyin ba joko sibi, okan yin le losi aimoye mili sibi teyin tin l'ero. Beena lori oko afefe okan wa tabi oko afefe ton se lategun, kesi se irin aji yi fun aimoye odun, eyin o le sewaadi na. Panthās tu koṭi-śata-vatsara-sampragamyo vāyor athāpi manaso muni-puṅga... (Bs. 5.34). Muni-puṅgavānām. Awon eyan lasan nikan ko, sugbon awon eda pataki bi awon alagbara idan, kosi bonsele se.