YO/Prabhupada 0604 - If I continue Krsna will be Pleased to Place me on the Transcendental Platform



Vanisource:Lecture on SB 1.5.11 -- New Vrindaban, June 10, 1969

Totitan nitumo Nivṛtta, toti pari. Kilo paari? Tṛṣṇa. idamu nitumo Tṛṣṇa . Eni toti pari idamu aye yi, awon lole korin ogo Oluwa. Awon iyoku o le korin. Gege bi egbe saṅkīrtana wa, eyin ti mu idunnu to po. Beena awon iyoku ma sowipe, " Kini awon eyan wanyi sen? Awon were, wan korin wan jo, won lulu." Won ronu bayi nitoripe igbadun aye yi o ti tan lokan won. Nitorina nivṛtta.

Looto, oruko mimo oruko Krsna, tabi Olorun, afi teyan ba ni igbala kosi bosele korin na. Nitorina lawa sen fun itosona wanyi, awon ipo meta lowa. Ipo talakoko pelu ese, ipo awon tonti igbala, ati ipo awon eyan lori ife oluwa. Ipo to gaju fun orin kiko na. Ni ibere awa'n korin pelu ese - awon ese mewa. Sugbon iyen owipe awa o le korin. Ti awon ese wanyi ba wa, ale ma korin lo. Orin kiko yi ma yoo awon ese wanyi kuro. Looto, agbodo gbiyanju ka ma se awon ese . Nitorina lonse funwa ni atojo awon ese mewa wanyi. Agbodo gbiyanju lati fi won sile. Lesekese t'awa ban korin laisi ise mo, lehin na oti wa sori ipo pipe. Ipo to gaju niyen, lehin ipo yi, orin kiko yi ma dun mo wa, nitoripe o wa lori ipo pipe, eyin ma ni ife gidi fun Krsna ati Olorun. Orin kiko yi... Lori ipo pelu ese, ati ipo to wa pipe... sugbon lori ipo to dagba.. Gege bi Rūpa Gosvāmī sen sowipe "Kini mofe ko pel'ahon kan soso ati kini mofe gbo pelu eti meji? Tinba ni aimoye eti, ati aimoye ahon, lehin na mole korin tabi in gbo." Nitoripe won wa lori ipo pipe. Sugbon awa o gbodo ni ibanuje nitorina. Agbodo tesiwaju beena. Utsāhād dhairyāt. Pelu oyaya ati dhairyat, ifaramo. Utsāhāt. Niścayāt. Niścayāt, ipinnu to daju: " Beeni, Moti bere sini korin. Awon asise lewa, sugbon tinba tesiwaju, Inu Krsna ma dun lati fimi sori ipo to gaju ti mole bere sini gbadun nkan toje lati korin Hare Krsna." Gege bi Viśvanātha Cakravartī se fuwa ni apeere mongoro dudu ati ey to pon. Mangoro dudu koro lenu, sugbon toba pon, osi dun gan. Awa gbodo duru fun ipo yi, agbodo se jeje kama se awon asise na. Lehin na odaju pe oma wa. Gege bi ailasan, toba tele itosona ologun tosi mu ogun, oma ni iwosan.