YO/Prabhupada 0605 - Love Vasudeva then there is no Chance of Contacting Material Body



Lecture on SB 5.5.6 -- Vrndavana, October 28, 1976

Beena.. ipinnu to gaju ni vasudeve. Prītir na yāvan mayi vāsudeve. Ipinnu to gaju niyen. Egbodo wa sori ipo yi, vāsudeva sarvam iti, to daju lokan yin wipe " Vasudeva ni aye mi. Vasudeva ni gbogbo nkan. Krsna ni aye mi." ipo to gaju yi si wa ni bugamu Vrndavana, nipataki fun awon gopi. Gbogbo eyan ni Vrndavan, awon igi ati eso gan, awon iyepe gan, gbogbo eyan lo nife Krsna Vrndavana niyen. Beena konse lesekese leyan le de ipo to gaju bi ifarasi ti Vrndavana, sugbon ibikibi taba wa, taba se adase bhakti-yoga yi, b'a sen waasu yi.. Oti ni iaseyori. Awon eyan tin gba s'okan. Awon eyan toon je mleccha ati yavana, awon na sin gba Vasudeva. Ife won fu Krsna si dagbasoke. Nkan adayeba niyen. Wantii salaye ninu Caitanya-caritāmṛta, nitya siddha kṛṣṇa bhakti. Nitya siddha. gege bi mose je, tabeyin, awa tayeraye. Nityo śāśvato 'yam na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Awa o le paari ti ara eda tani ba paari. Asi ma wa titi na. Beena, ise ifarsi fun Krsna na ma tesiwaju. Idabo kan wa lori re nisin. Avidyayātmāny upādhiyamāne. Avidya. avidya leleyi. Ati gbagbe Krsna, avidya niyen. Lesekese taba mu Krsna bi aye wa ati emi wa, vidya niyen. Eyin na lese. Enikeni lese, o rorun gan. Krsna sowipe, nitorina, sarva dharmān parityajya mam ekam śaraṇaṁ (BG 18.66). Kilode? awon esin eke to ku, avidya nigbogbo won - won ma fi yin sinu okunkun. Kosi ina kankan. Itosoona Veda imi tun wa tosowipe " Ema duro sinu okunkun ati aimokan." Tamasi mā jyoti gamaḥ.

Itumo jyotiḥ ni'fe fun Kṛṣṇa. ati awon eto ife ti Krsna ninu odo metalokan. jyotiḥ niyen, jyotirmāyā dhāma, ton tana fun ara re. Yasya prabhā prabhavato jagad-aṇḍa-koti (Bs. 5.40). Kos'okunkun nibe. T'orun ba jade kole s'okunkun. Awon apeere wanyi wa nibi. Ale mo nkan ti jyotih je. Ale riwipe kos'okunkun kankan lori isogbe orun. Gbogbo e lon tanna. Beena, ninu odo metalokan, kosi aimokan. śuddha-sattva ni gbogbo awon eyan. konse sattva-guna nikan sugbon suddha-sattva Sattvaṁ viśuddhaṁ vāsudeva-śabditaḥ. Ninu ile aye yi, amuye meta to wa ni, sattva-guṇa, rajo-guṇa, tamo-guṇa. Beena kos'eyi ninu awon guna wanyi toje mimo. Ipaapo ni gbogbo e. Nitoripe ipaapo yi wa, nitorina lasen ri orisirisi nkan bayi. Sugbon agbodo wa sori ipo sattva-guna. igboran lona yi. Ona to daju. Śṛṇvatāṁ sva-kathāḥ kṛṣṇaḥ puṇya-śravaṇa-kīrtanaḥ (SB 1.2.17). Teyin ban gbo awon oro ninu Śrīmad-Bhāgavatam... Nitorina lsen tenumo. " E gboran nigbogbo'gba, e kawe nigbogbo'gba, e gboran nigbogbo'gba Nityaṁ bhāgavata-sevayā (SB 1.2.18). Nitya. teyin bale gbo ke korin fun wakati merinlelogun Igboran yi niwipe, enikan korin tabi eyin korin fun ara yin, tabi ki ore re korin ki'wo gbo. tabi ko gbo kiwo korin. Ilana yi gbodo tesiwaju. śrāvaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ. Viṣṇoḥ (SB 7.5.23). Bhāgavata niyen. Ema soro iranu imi, oro abosi. E gbo kesi korin. Lehin śṛṇvatāṁ sva-kathāḥ kṛṣṇa. teyin ba korin tegba dada, nipatai - " Beeni, ninu aye yi mofe jeki ife fun Vasudeva ko posi" - teyin ba mu ni pataki, e le se. Ko le rara. lesekese teyin bale se, ife yi fun Vasudeva ma posi, lehin na kos'aye kankan lati gba ara eda imi.

janma karma ca divyam
me yo janati tattvataḥ
tyaktvā dehaṁ punar janma
naiti...
(BG 4.9)

Nkankana loje.

Teyin o ba ni oye nipa Krsna, teyin o ba jeki ife yin fun Krsna posi, lehin na mucyate deha-yogena tāvat. Kos'aye kankan. Kos'aye kankan. Eyin leni ibimo ninu ebi awon olowo, ninu ebi brahmana, yogo-bhrastah, sugbon ko daju, nitoripe eyin le wolule na. Awa ti ni apeere to po.... Gege bi eyin olugbe America, ton bi yin sinuu awon ebi olowo, sugbon e ti wolule teti di awon oniranu. Isokale. Beena o le sele.. Ko daju pe kolese. " Nitoripe won bimi sinu ebi awon olowo tabi brahmana, ko daju. Ko daju. maya yi lagbara gan tojepe lati fayin sile ni ise kan soso to ni - lati fa yin sile. Awon ipa re po gan. Beena nitorina awa ti riwipe nigbami awo olugbe America, orire won po gan won bi won sinu orile-ede ti awon eyan o kinse talaka, kosejo aini. Sugbon awon asiwere ni olori orile-ede na, wanti s'eto fun eran jije, imo ako ati abo laise igbayawo ati tete. Polowo. Won polowo awon obirin ton tusi ihoho, kilon pe awon eleran ati oti. Nkan ton sele leleyi, Won polowo siga, latii fa awon eyan sle. E lo si orun appadi. Punar mūṣika bhava. Won o mo alebu buruku wo ti awujo na sin fa won si. Nitorina awon okurin arugbo ton logbon, wansi wa pade mi lati dupe: " Swamiji, nkan rere loje pe eyin ti wa si ilu wa." Won mo be, Beeni, otooro loje. Egbe orire l'egbe imoye Krsna yi je. ni awon ilu geesi nipataki, otooro niyen. Beena awon tonti gba, ton mu ni pataki. E jeki ife yi fun Krsna posi.. Prītir na yāvan mayi vāsudeve na mucyate deha yogena... won o mo nkan ti awon isoro aye yi je. deha-yoga yi ni isoropo tani, ara eda ojiji yi. Ati gba kan, bhūtvā bhūtvā pralīyate (BG 8.19), ati gba ara eda kan yi. Nitorina awon asiwere wanyi, awon olori ni Europu ati America, won ti sowipe kosi ibimo. Otan Nitoripe tonba gba eto aye atun wa, lehin na nkan to buru fun wan niyen. Beena wanti tisegbe: Rara, kosi ibimo." Awon alamodaju eke wanyi, awon alakowe,, ton soro iranu lenu: " Swamiji, lehin igba ti ara eda yi batan,, gbogbo nkan ti tan." Ipinnu oro won niyen. ara eda yi kon dede wa, kim anyat kāma-haitukam. Asatyam apratiṣṭhaṁ te jagad āhur anīśvaram (BG 16.8).

Beena, iru awujo bayi ewu loje si awon eyan. ewu nla. Beena awon eyan tonti pade imoye Krsna yi oye kan se jeje gan ninu awujo tol'ewu nla bayi. Awon eyan jiya E gba egbe imoye Krsna kinuyin dun.

Ese pupo.

Ajo: Jaya Prabhupada. (opin)