YO/Prabhupada 0615 - Work for Krishna with Love and Enthusiasm, that is Your Krishna Conscious Life



Lecture on BG 1.30 -- London, July 23, 1973

Awon Māyāvādīs, Māyāvādīs meji lowa: awon ton sowipe Oluwa o kin seyan ati awon ton sowipe ofurufu loje. Māyāvādīs ni gbogbo won. Imoye won si da, nitoripe eyan tio logbon o le mo ju bayi lo. Teyin ba sofun didirin okurin pe ile aye imi wa ni odo metalokan, lati di iranse Oluwa, won ma rowipe, " Modi iranse ile aye yi. Mode ti jiya bayi. Etun fe kin di iranse Krsna?" "Oh.." ko da won loju," Oh, rara, rara. Koda bayi. Koda bayi." Lesekese tonba gbo nipa ise, won ma ronu nipa ise yi, ise iranu yi. Won o le ronu pe ananda kankan wa, afi ise yi. Eyan si fe sise fun, Krsna. Odo meta lokan niyen. Kole ye won. Beena awon nirviśeṣavādī, awon ton rowipe Oluwa o kin seyan, bonsen ronu niyen. Gege bi okurin to laisan ton sun lori ibusun, tonba si sofun pe "T'ara re ba ya, waa le jeuin dada, wa si bere sini rin ," asi ronu " matun bere sini rin? Matun bere sin jeun?" Nitoripe ogun to kooro yi ti baa lara mo ati sāgudānā, tio da lenu, ati awon nkan to po, igbe yiya at'ito, gbogbo e lori ibusun. Beena lesekese tonba sofun pe " Lehin igba t'ara re ba ya wasi ma yagbe ati ito, wa si jeun, sugbon awon awon nkan too da leleyi, " kole ye. A sowipe " nkan bayi lo jo." Beena awon Mayavadi wanyi, koleye wan pe ise si Krsna le funwa ni idunnu ati igbadun. Kole ye won. Nitorina lonse di awon eyan ton rowipe Oluwa o kin seyan: " Rara. Otito to gaju kosi bosele j'eyan." Apa imi ninu imoye Buddha niyen. Itumo odo niwipe ko l'ara kankan. Odo na niyen je. Beena imoye Buddha, won ti sowipe ofurufu ni ipinnu aye won, awon Mayavadi na, ipinnu aye won... Na te viduḥ svārtha-gatiṁ hi viṣṇum (SB 7.5.31). Koye won pe idunnu wa ninu ise si Krsna. Nitorina, nibi Arjuna sin huwa bi eda lasan. Beena o sowipe, " Efe kin ja, ki inu mi baale dun, lati gba ijoba, sugbon seyin fe kin pa awon ebi mi? Oh, nimittāni viparītāni. Eyin tan mi je." Nimittāni ca paśyāmi viparītāni. " Inu mi o le dun tinba pa awon ara ebi mi. Kolese. Kilode teyin fe kin se iru nkan bayi?" Beena o sowipe, nimittāni ca viparītāni paśyāmi. "Rara, rara." Na ca śaknomy avasthātum: " Mio lo duro sibi. E je kin pada. Emu oko telesin mi pada. Mio le duro sibi." Na ca śaknomy avasthātuṁ bhramatīva ca me manaḥ (BG 1.30). " Idamu loje funmi. Koye mi mo."

beena ipo to wa niyen, ile aye yi. Awa ninu isoro nigbogbo'gba, teba si fun awon eyan aye yi ni nkan to da pa " E gba imoye Krsna yi, inu yin ma dun," nimittāni viparītāni, loma ri,odi keji. Se imoye Krsna yi fe funmi ni idunnu? Awon ebi mi wa ninu isoro tabi moni awon isoro to po gan. Iranlowo wo ni imoye Krsna yi fe funmi?" Nimittāni ca viparītāni. Ipo ile aye yi leleyi. Nitorina egbodo lo asiko to da lati fi ni oye nipa re. C'est la Bhagavad-gita. Arjuna kanna, oti ri nisin, nimittāni ca viparītāni. Toba ti ni oye nipa Bhagavad-gita, asi daun pe, " Beeni, Krsna, nkan teyin so, o daju" Nitoripe leyin igba ti Krsna ba ko Arjuna asi bere lowo re, " Nisin kilo fe se?" Nitoripe Krsna o kin l'agidi. Krsna sowipe " E teriba funmi." Kosowipe, " Egbodo teriba funmi Olorun nimi. Nkankanna leje pelu Mi." Rara. Kole so iru nkan bayi. Nitoripe oti fun yin ni ominiran lati se besefe. Koni fowo kan. Bibeko kini iyato laarin okuta ati eda towa laaye? Eda to wa laaye gbodo ni ominiran, botilejepe iwonba kekere loje. Krsna o le fowokan. Koni fowokan lailai. Eyin gbodo gba fun ara yin, " Beeni, Krsna, Mofe teriba fun yin. Beeni. Fun ijeere mi loje." Imoye Krsna niyen. Eyin ma gba fun ara yin, konse nkan ton le ti enikankan lati se. " Oluko mimo ti sowipe nkan bayi bayi da. O da bee e jekin se." Rara. Egbodo ni oye nipa eto yi dada. Teṣāṁ satata-yuktānāṁ bhajatāṁ prīti-pūrvakam (BG 10.10). Prīti, pelu ife. Teyin ba sise, teyin ba sise fun Krsna pelu ife ati igbiyanju, imoye Krsna niyen. Teyin ba rowipe " oti darugbo, isoro loje funmi, sugbon kini mofe se? Awon eyan wanyi sowipe kin se. Nitorina nimo sen se," imoye Krsna ko niyen. Egbodo se lat'okan yin pelu idunnu to po, Lehin na le ma mo. Utsāhān niścayād dhairyāt tat-tat-karma-pravartanāt, sato vṛtteḥ sādhu-saṅge ṣaḍbhir bhaktiḥ prasidhyati. Eyin ma ri ninu Upadeśāmṛta (NOI 3). Egbodo gbiyanju ni gbogbo'gba, utsāhāt Dhairyāt, pelu isuru. Tat-tat-karma-pravartanāt. Niścayāt, pelu idaniloju nitumo niścayāt. "Tinba sise fun ise Krsna, Krsna ma mu mi pada si odo metalokan..." Niścayāt. And Kṛṣṇa says, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). " Ma mu e pada." Bon se so niyen. Oniro ko ni Krsna beena agbodo sise pelu igbiyanju to po. viparītāni ko. Arjuna ma gba toba paari. Krsna ma bere lowo re," Arjuna mi, kilo ro nisin?" Arjuna ma sowipe, " Beeni." Tvat prasādāt keśava naṣṭa-mohaḥ (BG 18.73): "Gbogbo aimokan mi ti tan,"

Otan. Ese pupo. Hare Krsna.