YO/Prabhupada 0618 - The Spiritual Master feels very Happy that 'This Boy has Advanced more than Me'



Lecture on CC Adi-lila 7.91-2 -- Vrndavana, March 13, 1974

Nigbati akeeko ba di pipe ninu ilosiwaju mimo, inu oluko re ma dunsi gan, pe " Oniranu nimi sugbon omo okurin yi, ti tele awon itosona timo fun ode ti ni aseyori. Aseyori timoni niyen." àfojúsùn oluko mimo niyen. Gege bi baba. Ibasepo ton ni niyen. Koseni tofe ri pe elomi ni ilosiwaju ju lo. Bi ile aye yi se ri niyen. Matsarata. T'enikan ba ni ilosiwaju ju mi lo ninu eto kankan, lehin na ma bere sini ni itara si. Sugbon oluko mimo wa tabi baba wa, kole ni itara siwa. Inu re ma dun gan, pe " Omo okurin yi tini ilosiwaju jumi lo." Ipo oluko mimo wa niyen. Beena Kṛṣṇa, Caitanya Mahāprabhu ti salaaye pe nigbati ban korin ati ti ban jo ati tinba sukun ninu ayo ayoju, beena oluko mimo temi man dupe lowo bayi: bhāla haila, osi da gidi gidi gan." Pāile tumi parama-puruṣārtha: "Nisin eyin tini ilosiwaju to gaju ninu ile aye yi." Tomāra premete: "Nitoripe eyin tini ilosiwaju to po, āmi hailāṅ kṛtārtha, mosi ni igbese ore to po siyin." Ipo to wa leleyi. Lehin na osi gba mi niyanju, nāca, gāo, bhakta-saṅge kara saṅkīrtana: "Nisin e tesiwaju. EYin ti ni ilosiwaju to po. Nisin E le tesiwaju." Nāca: "E jo" Gāo: "E korin," bhakta-saṅge, "pelu awon olufokansi pelu." Ema je ko d'ise tefe fi pa owo, sugbon bhakta-saṅge. Ipo gidi lati ni ilosiwaju ninu ile aye mimo. Narottama dāsa Ṭhākura na ti sowipe

tāñdera caraṇa-sevi-bhakta-sane vāsa
janame janame mora ei abhilāṣa

Narottama dāsa Ṭhākura sowipe " Lati ibimo kan sikeji." Nitoripe olufokansi loje, koni ife okan kankan lati pada si odo metalokan. Rara. Ibikibi, kosejo kankan. O kan fe yin Olorun logo. Ise toni niyen. Konse ise bhakta lati korin ati lati jo ati lati sise ninu ise ifarafun Oluwa nitoripe ofe pada si Vaikuntha tabi Goloka Vrndavana. Ife okan Krsna niyen. "Toba feran mi, Oma gbami s'okan." Gege bi Bhaktivinoda Thakura se so: icchā yadi tora. Janmāobi yadi more icchā yadi tora, bhakta-gṛhete janma ha-u pa mora. Adura olufokansi niwipe... Koni bere lowo Krsna pe " E dakun e mu lo si Vaikuntha tabi Goloka Vrndavana." Rara. " Teba rowipe mo gbodo ni ibimo imi, o da bee. Sugbon ibeere kan soso timoni niwipe e je kin ni ibimo ninu ile awon olufokansi. Otan. Beena mio ni gbagbe Re." Adura kan soso ti awon olufokansi leleyi.