YO/Prabhupada 0625 - Necessities of Life are being Supplied by The Supreme Eternal, God



Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

Awa taje awon eyan ton laju - kosejo boya olugbe America tabi India tabi Germany tabi olugbe ilu geesi, ko buru - awa si kere. Beena asi ni awon isoro ninu eto oro aje. Awa sin gbiyanju lati mo nipa eto oro aje tani. Kini ipo eto oro aje yi? Jijeun, sisun, imo ako ati abo, ati igbeja ara wa. Awasin sise nigbogbo'gba sugbon awon eranko na won sise lati jeun, sun, ni imo ako ati abo ati igbeja ara won, sugbon kosi isoro kankan l'aye won. Awa sini awon isoro to po. Beena egbiynaju lati ni imoye, ti awon eda to poju kosi isoro kankan laaye won.... Oluwa lon peese gbogbo nkan ton fe. Gege bi awon erin. Aimoye awon erin tonwa ninu awon aginju ni Africa. Ounje ton je o to kilo aadota. sugbon won ri ounje na je. Beena, awon kokoro, tonje erunrun iyo ireke. Oun na sin ri ounje re je. Beena eda towa tayeraye ti peese ounje, tabi iseda aye yi ti yanju awon isoro eto oro aje. Won o sise kankan, won o losi ile iwe eko kankan lati ko nipa imo ero, lati ko bonsele ri nkan je, sugbon won peese fun won. Won si wa dada. Kosi aisan kankan. Beena ilosiwaju awujo awon eyan ti da awon isoro wanyi. Otan. ilosiwaju awujo wa leleyi, awa osi mo nipa emi wa, bosen kuro lati ara eda kan sikeji, bi aye to kan re ma seri, boya awa ti gba ara eda tabi eyi toda ju ara eda lo, tabi eyi to kere ju ara eda lo. Toba jebe, bawo lawa sefe ri iru ara eda yi gba ninu aye wa to kan? Nitoripe awa ma wa tayeraye, awa sin paaro ara eda yi. Awa o de mope ara eda meji lowa: Ara teyin le foju ri ati ara eda tio se ri. Eyi tale foju ri lati ile,, omi, ina, ofurufu ati afefe, ara wa tawa o le foju ri lat'okan, ogbon ati igberaga lonti se. ninu ara eda yi tawa o le foju ri, ibe ni emi wa wa. Nisin, ti ara eda yi bati di iranu tio se lo mo, lehin na ara eda teyin o le foju ri ma gbe mi losinu ara eda imi. Nkan ton pe ni ipaaro ara eda fun emi niyen. Sugbon awa o le foju ri ara eda yi to wa ninu. Gbogbo wa mo wipe a si l'okan tawa o le foju ri. Kode si basele ri ogbon ori, kode si basele ri igberaga mi. Sugbon gbogbo won lon wa. Beena gbogbo nkan ko loye ke ri pelu oju lasan. Awon oju wa o wa ni pipe. Gege bi odi keji yara yi, mio le ri yi. Botilejepe mosi loju. Beena awa loju sugbon oju wa o fibe wa ni pipe. Konse gbogbo nkan ni mole foju ri. Nigbami a le foju ri awon nkan. Nitorina awa o gbodo fi igbagbo wa sinu awon nkan tale foju ri. Sugbon, botilejepe mio le ri yin, eyin le gbo ohun mi, tabi oye mi eyin feti si nkan timon so. Eti lagbara ju oju lo. Beena awon nkan to koja ogbon wa a le feti gbo nipa re. Botilejepe awa o le foju ri, iyen o wipe awon nkan wanyi o si laaye. Apeere kanna: mio leri okanmi, mio leri ogbon ori mi, tabi igberaga mi, sugbon mole gbo nipa re. Nitorina ogbon to wa ni pipe lati igboran lale mo. Beena lati igboran lale ni imoye. Apeere imi: kasowipe okurin wa ton sun. teyan ba wa lati fiku pa onitoun na, ton sun, kosi bosele mo. sugbon t'ore re ba kiloo fun, " Ore mi, arakurin bayi bayi, fe wa fiku pa yin. E dide soke" O le gbo, asi dide soke kobale soora. Nitorina, ti awon iye ara wa toku o ba sise mo, eti wa ma lagbara si. Nitorina agbodo lase funyin ni itosona pe egbodo gbo lati awon olori to daju. Awon ile eko gege bonse ri niyen. Kilode teyin se wa si ile eko giga? Lati gbo lowo awon alamodaju. Oun lo mo, eyin na le mo teba gbo nkan toba sofun yin.