YO/Prabhupada 0626 - If you want to Learn factually Things then You should Approach Acarya



Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

Beena eto igboran yi se pataki gan. Beena egbe imoye Krsna yi wa lati pin eto yi pe " E gboran lati awon olori, Krsna." Krsna ni Eledumare. Wonti gba ninu asiko tawayi ati asiko to koja. Lasiko to koja, awon eyan pataki bi Nārada, Vyāsa, Asita, Devala, awon alakowe giga, gbogbo won lon gba. Lasiko odun 1,500 seyin, awon acarya bi Śaṅkarācārya, Rāmānujācārya, Madhvācārya, Nimbārka... Awujo olugbe India, gbogbo wan lon sise lori oro awon acarya wanyi. wonde ti funwa ni itosona ninu Bhagavad-gita: ācāryopāsanam (BG 13.8). teyin bafe keeko nipa awon nkan, eyin gbodo summon awon acarya. Ācāryavān puruṣo veda, "Eyan gbodo gba awon acarya, o mo awon nkan bonseje." Ācāryavān puruṣo veda. Beena awa ti gba imoye lati awon acarya. Krsna si sofun Arjuna, Arjuna soro si Vyasadeva. Arjuna kolo ba Vyasadeva soro, sugbon Vyasadeva lo gbo, Krsna lon soro, osi kosile ninu iwe re Mahābhārata. Bhagavad-gita yi wa ninu Mahābhārata. Beena awa ti gba awon olori bi Vyasa. lati Vyāsa, Madhvācārya; lati Madhvācārya, awon akeeko ton pejo, titi de Madhavendra Puri. Lehin Mādhavendra Purī si Īśvara Purī; lati Īśvara Purī si Oluwa Caitanyadeva; lati Lord Caitanyadeva si awon Gosvāmī mefa; lati awon Gosvāmī mefa si Kṛṣṇadāsa Kavirāja; lati Krsnadada Kaviraja si Śrīnivāsa Ācārya; lati Viśvanātha Cakravartī; si Jagannātha dāsa Bābājī; lehin naGaura Kiśora dāsa Bābājī; Bhaktivinoda Ṭhākura; ati oluko mimo mi. Nkankana, lawa na sin sewaasu fun. Imoye Krsna niyen. Kosin nkankan tuntun. Lati enito koko soro na, Krsna loti wa, lati ipejo awon akeeko. Beena awa sin ka ninu Bhagavad-gita. Konsepe moti da iwe mi sile ati pe mon sewaasu na. Rara. Mon sewaasu Bhagavad-gita. Bhagavad-gita kanna ton so ni alakoko bi odun aadota-oke lona ogoji seyin si orisa- orun wonde ti tunso bi odun egberun maarun seyin si Arjuna. Nkankana lon wa lati awon akeeko wanyi, nkankana lawa sin funyin nisin. Kosi ipaaro kankan.

Beena awon olori ti sowipe,

dehino 'smin yathā dehe
kaumāraṁ yauvanaṁ jarā
tathā dehāntara-prāptir
dhīras tatra na muhyati
(BG 2.13)

Beena awa sin bere lowo awon eyan kon gba imoye yi lati awon olori wanyi, kesi gbiynaju lati ni oye re pel'ogbon yin. Konsepe eyin o ni rori mo, ke kon gba lai yeewo Rara. Eda eyan niwa, asi logbon. Eranko ko niwa pe won ma ti wa lati ni oye nkan. Rara. Tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā (BG 4.34). Ninu Bhagavad-gita eyin ma ri nibe. E gbiyanju lati ni oye re, tad viddhi. Egbiyanu lati ni oye re nitumo Viddhi. Praṇipāta. iteriba nitumo Praṇipātena, pelu ija ko. Akeeko gbodo gboran si Oluko mimo re lenu. Bibeko, o ma daloju. Ogbodo gboran si lenu.

tasmād guruṁ prapadyeta
jijñāsuḥ śreya uttamam
śābde pare ca niṣṇātaṁ
brahmaṇy upaśamāśrayam
(SB 11.3.21)

Ilana to wa niyen, Veda. Teyin bafe mo awon nkan tokoja ogbon yin lo, to koja irori ogbon yin, lehin na egbodo summo oluko mimo.