YO/Prabhupada 0627 - Without Refreshness, One cannot Understand this Sublime Subject Matter



Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

kini awon iwa oluko mimo to daju? Gbogbo awon eyan lonfe d'Oluko mimo. Beena wanti salaaye nipa eto yi. Śābde pare ca niṣṇātam (SB 11.3.21). Eni toti we tan ninu omi okun imoye Veda, śābde pare ca niṣṇātam. gege b'ara yin se ma bale, leyin igba teyin ba we tan. teyin ba we dada, ara yin ma bale, śābde pare ca niṣṇātam. ti ara yin o ba bale, eyan o le ni oye ninu eto mimo yi. atii guru, tabi oluko mimo, oun na gbodo we ninu omi okun imoye Veda yi k'ara re na bale. Kini ibajade towa nibe? Śābde pare ca niṣṇātaṁ brahmaṇy upaśamāśrayam. lehin igbati ara re bati mo bayi, lehin na lole gba idaabo lati Eledumare, laisi ife okan aye kankan. Koni ife okan kankan mo; o kan fe sise fun Krsna tabi otito to gaju. Awon aami guru leleyi, tabi oluko mimo.

Beena lati ni oye na.. gege bi Krsna sen ko Arjuna. Śiṣyas te 'haṁ śādhi māṁ prapannam (BG 2.7). Botilejepe ore ni Krsna ati Arjuna je si ara won... Ni alakoko won soro bi ore, Arjuna sin ba Krsna jiyan. Ijiyan yi o daju nitoripe t'eni to ban jiyan o ba daju kini iwulo ijiyan wanyi? Ounkoun tinba fe jiyan, kole wa ni pipe. Beena kinidi lati lo asiko mi nilokulo ninu awon ijiyan wanyi. Ilana to wa ko niyen. Ilana to wa niwipe agbodo ba eni to wa ni pipe ka si gba itosona re boseje. Lehin na imoye wa ma daju. Lai jiyan. Awa ma gba imoye Veda yi bee. fun apeere, gege bi igbe eranko. Ninu awon iwe Veda won sowipe teyin ba fowokan, nkan idoti niyen je... Ninu ilana Veda teyin ba ya'gbe tan egbodo wee. Kama wa soro nipa igbe elomi. Ilana to wa niyen. Beena idoti ni igbe yi je. Lehin na teyan ba fowokan igbe ogbodo lo we. Ilana Veda niyen. Sugbon nibomi wan sowipe mimo ni igbe maalu, teyin ba si fi igbe maalu sibi tio mo ibe na mo. Nisin eyin lesowipe " Kosi bi igbe erank se fe je nkan mimo. Kilode tojepe nibi kan won sowipe idoti ni, nibo mi won sowipe o mo? Ko baramo." Sugbon kosi ijakadii kankan. Ele se idanwo fun ara yin. Emu igbe maalu ke fisibi kankan, ema ri wipe ibe ma moo. Lesekese loma mo. Beena ilana Veda niyen. Imoye to daju loje. Dipo teyin ma lo asiko yin nilokulo lati jiyan pelu igberaga, teyin ba gba imoye yi, bon se salaaye ninu iwe Veda, Lehin na awa ti ni imoye to daju, ile aye wa tini ilosiwaju niyen. Dipo teyin se awon idanwo lori ara eda lati mo boya emi wa ninu re.. Emi wa nibe, sugbon o kere to jepe kosi besele ri pel'oju lasan. kos'ero teyin le lo lati yeewo, nitoripe won sowipe o kere ju ikan ninu apa egberun mewa irun ori eyan. Beena ko s'ero tele lo. Kosi besele ri. Sugbon o wa n'be. Bibeko, bawo lasele mo iyato laarin oku ati eni to wa laaye?