YO/Prabhupada 0631 - I am Eternal, the Body is not Eternal, This is the Fact



Lecture on BG 2.28 -- London, August 30, 1973

Nkan tose pataki niwipe laale tinba laala moti gbagbe nipa ara timo ni yi. Ara eda yi, ninu alaa timon ni, moti losi ibomi, ti mon ba awon eyan orisirisi soro, ipo mi ti yato. Sugbon lasiko yi, mio le rtanti pe ara mi wa lori ibusun ninu yara timo ti wa. Sugbon awa o le ranti. Ijeerisi gbogbo wa niyen. Beena laaro teyan ba ti ji, lati ibusun re, Masi gbagbe gbogbo ara eda timo ni, timo ti dasi le ninu awon alaa yi. Beena ewo lo daju? Ewo lo daju? Se ara eda yi lo daju tabi eyi to wa ninu ala na? Nitoripe laale masi gbagbe nipa ara eda yi, looju oji masi gbagbe nipa ara timoni ninu ala. Beena awon meejeji nio daju. Itanra-eni ni awon meejeji. Sugbon nkantimo ri laale daju, mosin riran looju ojo na. Beena mo wa tayeraye, fun igba die lara eda yi ma wa fuin. Otooro niyen. Antavanta ime dehā nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ (BG 2.18). Śarīriṇaḥ, eni ton ara eda yi, tayeraye lo wa fun, sugbon ara eda yi ko. L'ona orisirisi ni Krsna tin salaaye nipa ipo ara eda yi. Sugbon awon eyan tio logbon ton ni imoye die, o lee gan funwon lati mo. Bibeko, awon nkan wanyi o daju. Oro yi daju gan. Pe laale ma gbagbe ara eda yi, looju ojo masi gbagbe ara timoni laale. Otooro niyen> Beena, nigbami mole gbogbagbae mi ara timoni gbeyin se ri, iwonba odun wo ni aye timoni gbe to, tabi mio le mo nipa ara timo fe ni lojoowaju. Sugbon masi wa laaye, ara eda yi le yika gan, sugbon mo gbodo gba ara eda imi toma wa fun igba die. Sugbon, itumo re niwipe moni ara eda yi. Ara eda mimo niyen. Beena ara eda mimo yi si wa, itumo ilosiwaju mimo yi niwipe nialakoko egbodo mo nipa idanimo mimo teyin ni. gege bi Sanātana Gosvāmī se lo ba Śrī Caitanya Mahāprabhu leyin igba ti fi ise alakoso ijoba re sile. beena o sowipe, ke āmi, kene āmāya jāre tāpa-traya: "Lootooro, mio mo eni timo je, ati kilode timo se wa ninu isoro aye yi." Nitorina ni awon isoro aye yi se wa. Ninu ala na tinba ti ni ara eda imi, nigbami mole wa lori igi toga gan tabi lori oke Nigbami masi subu , t'eru ba tin ba mi ma bere sini sukun pe, " Mon subu." Beena ara eda yi, timo wa ninu re, Looto emi ko nimo ni awon ara eda wanyi. Moni ara eda temi to yato. Beena ile aye eda yi wa fun imora-eni, pe " Ara mi koni mi, moni ara mimo." Lehin na ibeere to tele niwipe " Lehin na kini ise mi?" Ninu ara eda timo ni yi, mon ronu wipe, " Ara mi leleyi," ara eda yi de ti wa lati ilu kan tabi ebi kan; nitorina, " ebi mi leleyi,ilu mi leleyi, orile-ede mi leleyi, " Gbogbo nkan ninu ara eda yi. toba sije wipe emi ko nimoni ara eda mi yi, beena awon ilu, orile-ede tabi ebi tabi awujo tabi awon ibasepo timoni, eke nigbogbo won na nitoripe ara eda eke nimoni.